Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
November–December 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọ̀ye ìbéèrè táwọn ọ̀dọ́ máa ń béèrè. Lára àwọn àpilẹ̀kọ náà ni:
• “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Yẹra fún Àwọn Tó Máa Ń Fi Ọ̀ranyàn Báni Tage?”
• “Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ọ̀rọ̀ Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?”
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ/ÀWỌN ỌMỌDÉ)