Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
January-Febuary 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọye ìbéèrè táwọn ọ̀dọ́ máa ń béèrè. Lára àwọn àpilẹ̀kọ tó wà níbẹ̀ ni:
• “Kí Ni Mo Lè Ṣe Tí Wọ́n Bá Ń Sọ̀rọ̀ Mi Lẹ́yìn?”
• “Kí Ló Yẹ Kí N Mọ̀ Nípa Fífi Ọ̀rọ̀ Ìṣekúṣe Ránṣẹ́ Lórí Fóònù?”
Kà nípa bí Bíbélì ṣe lè ran àwọn ọ̀dọ́ lọ́wọ́ kí wọ́n lè rí ojútùú sáwọn ìṣòro tí wọ́n bá dojú kọ.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)