Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
May–June 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Má Ṣe Jẹ́ Káyé Sú Ẹ
1 Torí Pé Nǹkan Máa Ń Yí Pa Dà
3 Nítorí Pé Ọ̀rọ̀ Rẹ Ò Kọjá Àtúnṣe
OJÚ ÌWÉ 6 SÍ 9
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọye ìbéèrè. Lára àwọn àpilẹ̀kọ tó wà níbẹ̀ ni:
• “Tí Mi Ò Bá Rí Ọ̀rẹ́ Tí Ọ̀rọ̀ Wa Bára Mu Ńkọ́?”
• “Báwo Ni Mi Ò Ṣe Ní Máa Fi Nǹkan Falẹ̀ Mọ́?”
• “Ṣé Ẹni Tó Yẹ Kí N Fẹ́ Nìyí?”
O tún lè wo fídíò èdè Gẹ̀ẹ́sì kan tá a pè ní “What Your Peers Say—Sexual Harassment.”
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)