Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September-October 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Báwo La Ṣe Lè Yanjú Aáwọ̀?
OJÚ ÌWÉ 3-6
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọye ìbéèrè. Lára wọn ni:
• “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Máa Bá Àwọn Òbí Mi Sọ̀rọ̀ Nípa Àwọn Òfin Wọn?”
• “Ṣé Kémi Àtẹni Tá a Jọ Ń Fẹ́ra Fira Wa Sílẹ̀?”
O tún lè wo fídíò èdè Gẹ̀ẹ́sì kan tá a pè ní What Your Peers Say—Healthy Lifestyles.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)