Nínú Ìtẹ̀jáde Yìí
January-February 2015
© 2015 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Bí O Ṣe Lè Láyọ̀
OJÚ ÌWÉ 4-7
10 Ìrànlọ́wọ́ Fún Ìdílé Tí Ọmọ Rẹ Bá Ń Purọ́
14 Ìrànlọ́wọ́ Fún Ìdílé Bí Ẹ Ṣe Lè Gbà fún Ara Yín
16 “Àmì Ìrántí Kan Tó Ṣe Kedere”
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọye ìbéèrè. Irú bíi:
• “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Borí Ìbànújẹ́?”
• “Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Kí N Máa Ran Àwọn Míì Lọ́wọ́?”
Tún lọ wo fídíò tí wọ́n pe àkọlé rẹ̀ ní “Ohun Tí Àwọn Ojúgbà Rẹ Sọ”—Owó.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)