Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
July–August 2014
© 2014 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
KÓKÓ IWÁJÚ ÌWÉ
Báwo Lèèyàn Ṣe Lè Jẹ́ Ọ̀rẹ́ Gidi?
OJÚ ÌWÉ 4 SÍ 7
16 ‘Ọgbọ́n Ń Ké Jáde’—Ṣé Ò Ń Gbọ́ Ohun Tó Ń Sọ?
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
Wàá rí ìdáhùn Bíbélì sí àìmọye ìbéèrè. Lára àwọn àpilẹ̀kọ tó wà níbẹ̀ ni:
• “Ṣé Ó Ti Yẹ Kí N Kúrò Lọ́dọ̀ Àwọn Òbí Mi?”
• “Báwo Ni Mo Ṣe Lè Gbọ́kàn Mi Kúrò Lórí Ìbálòpọ̀?”
O tún lè wo fídíò èdè Gẹ̀ẹ́sì kan tá a pè ní What Your Peers Say—Cell Phones
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)