Àwọn Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Yìí
September–October 2013
© 2013 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania.
TÚN LỌ WO ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ÀWỌN Ọ̀DỌ́
ÀWỌN Ọ̀DỌ́ BÉÈRÈ PÉ . . .
Bí Ara Mi Kò Bá Yá Ńkọ́? (Apá Kejì)
Kà nípa bí àwọn ọ̀dọ́ mẹ́rin kan ṣe mọ bí wọ́n ṣe lè fara da ìṣòro àìsàn tí kò lọ bọ̀rọ̀.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN Ọ̀DỌ́)
ÀWỌN ỌMỌDÉ
Ka àwọn ìtàn tá a mú látinú Bíbélì. Lo àwọn eré ọwọ́ tó wà níbẹ̀ láti fi kọ́ àwọn ọmọ rẹ lẹ́kọ̀ọ́ nípa àwọn èèyàn tí Bíbélì sọ̀rọ̀ nípa wọn àti nípa ìwà rere.
(Wo abẹ́ Ẹ̀KỌ́ BÍBÉLÌ > ÀWỌN ỌMỌDÉ)