ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 10
  • Bá A Ṣe Lè Rí Ìbùkún Jèhófà

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Bá A Ṣe Lè Rí Ìbùkún Jèhófà
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Kí Nìdí Tó Fi Yẹ Ká Ní Ìtẹ́lọ́rùn, Ká sì Mọ̀wọ̀n Ara Wa?
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2022
  • Ohun Tí Àjọyọ̀ Àwọn Ọmọ Ísírẹ́lì Kọ́ Wa
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 10

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Bá A Ṣe Lè Rí Ìbùkún Jèhófà

Yẹra fún àwọn ọlọ́run tí kò ní láárí (Le 26:1; w08 4/15 4 ¶8)

Máa sin Jèhófà bó ṣe yẹ (Le 26:2; it-1 223 ¶3)

Máa pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́ (Le 26:3, 12; w91 3/1 17 ¶10)

Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì máa ń gbádùn àjọṣe tó dáa pẹ̀lú Jèhófà, ó sì máa ń bù kún wọn tí wọ́n bá jẹ́ olóòótọ́, tí wọ́n sì ń sapá láti pa òfin rẹ̀ mọ́.

Bí àwọn èèyàn ṣe ń ra àwọn nǹkan ńláńlá, táwọn míì sì ń wa ọkọ̀ olówó ńlá, ṣe làwọn tọkọtaya yìí ń láyọ̀ lẹ́nu iṣẹ́ ìwàásù.

Èwo nínú àwọn ìbùkún Jèhófà yìí lò ń gbádùn báyìí?

  • Ẹ̀kọ́ òtítọ́ Bíbélì

  • Ìbàlẹ̀ ọkàn

  • Ìdílé aláyọ̀

  • Ìrètí ọjọ́ iwájú

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́