ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • mwb21 January ojú ìwé 8
  • Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

  • Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú
  • Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Àpilẹ̀kọ Míì Tó Jọ ọ́
  • Jèhófà Ló Ń Fúnni Ní Òmìnira
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́)—2019
  • Ìbéèrè Láti Ọwọ́ Àwọn Òǹkàwé
    Ilé Ìṣọ́ Tí Ń Kéde Ìjọba Jehofa—2004
  • Jèhófà Fẹ́ Káwọn Èèyàn Rẹ̀ Yàtọ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
  • Jèhófà Fọgbọ́n Pín Ilẹ̀ Fáwọn Èèyàn Rẹ̀
    Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
Àwọn Míì
Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Kristẹni—Ìwé Ìpàdé—2021
mwb21 January ojú ìwé 8

Àwọn tó wà lóko ẹrú ní Ísírẹ́lì ń pa dà sọ́dọ̀ ìdílé wọn, wọ́n sì gba ohun ìní wọn pa dà lọ́dún Júbílì

ÀWỌN ÌṢÚRA INÚ Ọ̀RỌ̀ ỌLỌ́RUN

Ọdún Júbílì Ṣàpẹẹrẹ Òmìnira Ọjọ́ Iwájú

Ọdún Júbílì máa ń jẹ́ káwọn ọmọ Ísírẹ́lì bọ́ lọ́wọ́ ìṣẹ́ àti òṣì (Le 25:10; it-1 871; wo àwòrán iwájú ìwé)

Wọn kì í ta ilẹ̀ wọn, ṣe ni wọ́n máa ń yá ara wọn nílẹ̀, bí ilẹ̀ náà bá ṣe dáa sí ni wọ́n fi máa ń ṣírò iye tí wọ́n máa dá lé e (Le 25:15; it-1 1200 ¶2)

Jèhófà máa ń bù kún wọn tí wọ́n bá pa òfin Júbílì mọ́ (Le 25:18-22; it-2 122-123)

Láìpẹ́, àwọn tó bá jẹ́ olóòótọ́ máa gbádùn Júbílì ìṣàpẹẹrẹ ní kíkún nígbà tí Ọlọ́run bá fún wọn ní òmìnira kúrò lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀ àti ikú.​—Ro 8:21.

Àwòrán: Àwọn èèyàn ń tún ayé ṣe kó lè di Párádísè. 1. Wọ́n ń kó ìdọ̀tí kúrò. 2. Wọ́n ń kọ́ ilé, wọ́n sì ń ṣe ojú ọ̀nà. 3. Wọ́n ń gbin òdòdó lóríṣiríṣi.

Kí lẹnì kọ̀ọ̀kan wa gbọ́dọ̀ máa ṣe ká lè gbádùn òmìnira tí Ọlọ́run ṣèlérí?

    Yorùbá Publications (1987-2025)
    Jáde
    Wọlé
    • Yorùbá
    • Fi Ráńṣẹ́
    • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
    • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
    • Àdéhùn Nípa Lílò
    • Òfin
    • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
    • JW.ORG
    • Wọlé
    Fi Ráńṣẹ́