1 KÍRÓNÍKÀ
OHUN TÓ WÀ NÍNÚ ÌWÉ YÌÍ
1
Látọ̀dọ̀ Ádámù dé ọ̀dọ̀ Ábúráhámù (1-27)
Àwọn àtọmọdọ́mọ Ábúráhámù (28-37)
Àwọn ọmọ Édómù àti àwọn ọba wọn pẹ̀lú àwọn Séríkí wọn (38-54)
2
3
4
5
Àwọn àtọmọdọ́mọ Rúbẹ́nì (1-10)
Àwọn àtọmọdọ́mọ Gádì (11-17)
Wọ́n ṣẹ́gun àwọn ọmọ Hágárì (18-22)
Ààbọ̀ ẹ̀yà Mánásè (23-26)
6
Àwọn àtọmọdọ́mọ Léfì (1-30)
Àwọn akọrin inú tẹ́ńpìlì (31-47)
Àwọn àtọmọdọ́mọ Áárónì (48-53)
Àwọn ibi tí àwọn ọmọ Léfì gbé (54-81)
7
Àwọn àtọmọdọ́mọ Ísákà (1-5), ti Bẹ́ńjámínì (6-12), ti Náfútálì (13), ti Mánásè (14-19), ti Éfúrémù (20-29) àti ti Áṣérì (30-40)
8
9
10
11
12
13
14
15
16
Wọ́n gbé Àpótí náà sínú àgọ́ (1-6)
Orin ìdúpẹ́ tí Dáfídì kọ (7-36)
Iṣẹ́ ìsìn níwájú Àpótí náà (37-43)
17
Dáfídì kò ní kọ́ tẹ́ńpìlì (1-6)
Ọlọ́run bá Dáfídì dá májẹ̀mú ìjọba (7-15)
Àdúrà ìdúpẹ́ tí Dáfídì gbà (16-27)
18
19
20
21
22
Ètò tí Dáfídì ṣe sílẹ̀ fún kíkọ́ tẹ́ńpìlì (1-5)
Dáfídì sọ ohun tí Sólómọ́nì máa ṣe fún un (6-16)
Ó ní kí àwọn ìjòyè ran Sólómọ́nì lọ́wọ́ (17-19)
23
24
25
26
27
28
29