Mósè àti Áárónì ṣiṣẹ́ ìyanu níwájú Fáráò
Ohun Tá A Lè Bá Àwọn Èèyàn Sọ
●○ NÍGBÀ ÀKỌ́KỌ́
Ìbéèrè: Báwo la ṣe mọ̀ pé Ọlọ́run kọ́ ló ń fìyà jẹ wá?
Bíbélì: Jem 1:13
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?
○● ÌPADÀBẸ̀WÒ
Ìbéèrè: Kí ló dé tá a fi ń jìyà?
Bíbélì: 1Jo 5:19
Ìbéèrè fún ìgbà míì: Báwo ló ṣe máa ń rí lára Ọlọ́run tá a bá ń jìyà?