Ẹ́kísódù 28:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+ Ẹ́kísódù 29:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Kí o mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé,+ kí o sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ Ẹ́kísódù 29:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 kí o mú òróró àfiyanni,+ kí o sì dà á sí i lórí láti fòróró yàn án.+ Ẹ́kísódù 40:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Kí o wọ àwọn aṣọ mímọ́ náà fún Áárónì,+ kí o fòróró yàn án,+ kí o sì sọ ọ́ di mímọ́, yóò sì di àlùfáà mi.
28 “Kí o mú Áárónì ẹ̀gbọ́n rẹ, pẹ̀lú àwọn ọmọ rẹ̀ látinú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì, kí wọ́n lè di àlùfáà mi,+ Áárónì,+ pẹ̀lú Nádábù àti Ábíhù,+ Élíásárì àti Ítámárì,+ àwọn ọmọ Áárónì.+
13 Kí o wọ àwọn aṣọ mímọ́ náà fún Áárónì,+ kí o fòróró yàn án,+ kí o sì sọ ọ́ di mímọ́, yóò sì di àlùfáà mi.