Àìsáyà 52:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ yíjú pa dà, ẹ yíjú pa dà, ẹ jáde kúrò níbẹ̀,+ ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kankan!+ Ẹ jáde kúrò ní àárín rẹ̀,+ ẹ wà ní mímọ́,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà.+ 1 Pétérù 1:15, 16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+ 16 nítorí a ti kọ ọ́ pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́, torí èmi jẹ́ mímọ́.”+
11 Ẹ yíjú pa dà, ẹ yíjú pa dà, ẹ jáde kúrò níbẹ̀,+ ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kankan!+ Ẹ jáde kúrò ní àárín rẹ̀,+ ẹ wà ní mímọ́,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà.+
15 àmọ́ bíi ti Ẹni Mímọ́ tó pè yín, kí ẹ̀yin náà di mímọ́ nínú gbogbo ìwà yín,+ 16 nítorí a ti kọ ọ́ pé: “Ẹ gbọ́dọ̀ jẹ́ mímọ́, torí èmi jẹ́ mímọ́.”+