ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 28:30
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Kí o fi Úrímù àti Túmímù*+ sínú aṣọ ìgbàyà ìdájọ́ náà, kí wọ́n sì máa wà ní àyà Áárónì nígbà tó bá wá síwájú Jèhófà, kí Áárónì máa gbé ohun tí wọ́n fi ń ṣe ìdájọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì sí àyà rẹ̀ níwájú Jèhófà nígbà gbogbo.

  • 1 Sámúẹ́lì 23:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 9 Nígbà tí Dáfídì gbọ́ pé Sọ́ọ̀lù ń gbìmọ̀ ibi sí òun, ó sọ fún àlùfáà Ábíátárì pé: “Mú éfódì wá.”+

  • 1 Sámúẹ́lì 28:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 6 Bí Sọ́ọ̀lù tilẹ̀ ń wádìí lọ́dọ̀ Jèhófà,+ Jèhófà kò dá a lóhùn rárá, ì báà jẹ́ nípasẹ̀ àlá tàbí nípasẹ̀ Úrímù  + tàbí àwọn wòlíì.

  • Nehemáyà 7:65
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 65 Gómìnà*+ sọ fún wọn pé wọn ò gbọ́dọ̀ jẹ lára àwọn ohun mímọ́ jù lọ,+ títí wọ́n á fi rí àlùfáà tó máa bá wọn fi Úrímù àti Túmímù+ wádìí.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́