Ẹ́kísódù 29:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 “Kí o mú Áárónì àti àwọn ọmọ rẹ̀ wá sí ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé,+ kí o sì fi omi wẹ̀ wọ́n.+ Àìsáyà 52:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Ẹ yíjú pa dà, ẹ yíjú pa dà, ẹ jáde kúrò níbẹ̀,+ ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kankan!+ Ẹ jáde kúrò ní àárín rẹ̀,+ ẹ wà ní mímọ́,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà.+
11 Ẹ yíjú pa dà, ẹ yíjú pa dà, ẹ jáde kúrò níbẹ̀,+ ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ kankan!+ Ẹ jáde kúrò ní àárín rẹ̀,+ ẹ wà ní mímọ́,Ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbé àwọn ohun èlò Jèhófà.+