Léfítíkù 7:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Ọwọ́ ara rẹ̀ ni kó fi mú ọ̀rá+ pẹ̀lú igẹ̀ wá láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, kó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì+ níwájú Jèhófà. Nọ́ńbà 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Àwọn ọmọ Léfì wẹ ara wọn mọ́, wọ́n sì fọ aṣọ+ wọn. Lẹ́yìn náà, Áárónì mú wọn wá* síwájú Jèhófà+ bí ọrẹ fífì. Áárónì wá ṣe ètùtù fún wọn kó lè wẹ̀ wọ́n mọ́.+
30 Ọwọ́ ara rẹ̀ ni kó fi mú ọ̀rá+ pẹ̀lú igẹ̀ wá láti fi ṣe ọrẹ àfinásun sí Jèhófà, kó sì fì í síwá-sẹ́yìn bí ọrẹ fífì+ níwájú Jèhófà.
21 Àwọn ọmọ Léfì wẹ ara wọn mọ́, wọ́n sì fọ aṣọ+ wọn. Lẹ́yìn náà, Áárónì mú wọn wá* síwájú Jèhófà+ bí ọrẹ fífì. Áárónì wá ṣe ètùtù fún wọn kó lè wẹ̀ wọ́n mọ́.+