Nọ́ńbà 1:53 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 53 Kí àwọn ọmọ Léfì sì pàgọ́ yí àgọ́ Ẹ̀rí ká, kí n má bàa bínú sí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì;+ àwọn ọmọ Léfì ni kó máa bójú tó* àgọ́ ìjọsìn Ẹ̀rí+ náà.” Nọ́ńbà 18:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Kí ẹ máa ṣe ojúṣe yín tó jẹ mọ́ ibi mímọ́ + àti pẹpẹ,+ kí n má bàa tún bínú+ sí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì. 1 Sámúẹ́lì 6:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Àmọ́ Ọlọ́run pa àwọn ọkùnrin Bẹti-ṣémẹ́ṣì, torí pé wọ́n wo Àpótí Jèhófà. Ó pa ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta ó lé àádọ́rin (50,070)* lára àwọn èèyàn náà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀ nítorí pé Jèhófà ti pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ.+
53 Kí àwọn ọmọ Léfì sì pàgọ́ yí àgọ́ Ẹ̀rí ká, kí n má bàa bínú sí àpéjọ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì;+ àwọn ọmọ Léfì ni kó máa bójú tó* àgọ́ ìjọsìn Ẹ̀rí+ náà.”
19 Àmọ́ Ọlọ́run pa àwọn ọkùnrin Bẹti-ṣémẹ́ṣì, torí pé wọ́n wo Àpótí Jèhófà. Ó pa ẹgbẹ̀rún lọ́nà àádọ́ta ó lé àádọ́rin (50,070)* lára àwọn èèyàn náà, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í ṣọ̀fọ̀ nítorí pé Jèhófà ti pa wọ́n lọ rẹpẹtẹ.+