-
Nọ́ńbà 10:11-13Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 Ó ṣẹlẹ̀ pé ní ogúnjọ́ oṣù kejì, ọdún kejì,+ ìkùukùu* náà gbéra lórí àgọ́+ Ẹ̀rí. 12 Àwọn ọmọ Ísírẹ́lì bẹ̀rẹ̀ sí í kúrò ní aginjù Sínáì, wọ́n tẹ̀ lé ètò tó wà nílẹ̀ nípa bí wọ́n ṣe máa gbéra,+ ìkùukùu náà sì dúró ní aginjù Páránì.+ 13 Èyí ni ìgbà àkọ́kọ́ tí wọ́n gbéra bí Jèhófà ṣe pa á láṣẹ nípasẹ̀ Mósè.+
-