-
Ẹ́kísódù 17:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Jèhófà wá sọ fún Mósè pé: “Kọ ọ̀rọ̀ yìí sínú ìwé fún ìrántí, kí o sì tún un sọ fún Jóṣúà pé, ‘Màá mú kí wọ́n gbàgbé Ámálékì pátápátá lábẹ́ ọ̀run.’”+
-
-
1 Sámúẹ́lì 15:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí: ‘Màá pe àwọn ọmọ Ámálékì wá jíhìn nítorí ohun tí wọ́n ṣe sí Ísírẹ́lì bí wọ́n ṣe gbéjà kò ó nígbà tó ń jáde bọ̀ láti Íjíbítì.+
-