1 Àwọn Ọba 4:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Ọlọ́run fún Sólómọ́nì ní ọgbọ́n àti òye tó pọ̀ gan-an àti ìjìnlẹ̀ òye tó pọ̀* bí iyanrìn etí òkun.+ Òwe 2:3-5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Bákan náà, tí o bá ké pe òye+Tí o sì nahùn pe ìfòyemọ̀;+ 4 Tí o bá ń wá a bíi fàdákà,+Tí o sì ń wá a kiri bí àwọn ìṣúra tó fara sin;+ 5 Nígbà náà, wàá lóye ìbẹ̀rù Jèhófà,+Wàá sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.+ Jémíìsì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Torí náà, tí ẹnikẹ́ni nínú yín ò bá ní ọgbọ́n, kó máa béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run,+ ó sì máa fún un,+ torí ó lawọ́ sí gbogbo èèyàn, kì í sì í pẹ̀gàn*+ tó bá ń fúnni.
29 Ọlọ́run fún Sólómọ́nì ní ọgbọ́n àti òye tó pọ̀ gan-an àti ìjìnlẹ̀ òye tó pọ̀* bí iyanrìn etí òkun.+
3 Bákan náà, tí o bá ké pe òye+Tí o sì nahùn pe ìfòyemọ̀;+ 4 Tí o bá ń wá a bíi fàdákà,+Tí o sì ń wá a kiri bí àwọn ìṣúra tó fara sin;+ 5 Nígbà náà, wàá lóye ìbẹ̀rù Jèhófà,+Wàá sì rí ìmọ̀ Ọlọ́run.+
5 Torí náà, tí ẹnikẹ́ni nínú yín ò bá ní ọgbọ́n, kó máa béèrè lọ́wọ́ Ọlọ́run,+ ó sì máa fún un,+ torí ó lawọ́ sí gbogbo èèyàn, kì í sì í pẹ̀gàn*+ tó bá ń fúnni.