10 Ilẹ̀ lanu,* ó sì gbé wọn mì. Ní ti Kórà, òun àtàwọn tó ń tì í lẹ́yìn kú nígbà tí iná jó igba ó lé àádọ́ta (250) ọkùnrin+ run. Wọ́n wá di àpẹẹrẹ tó jẹ́ ìkìlọ̀.+11 Àmọ́, àwọn ọmọ Kórà kò kú.+
11 Ó mà ṣe o, wọ́n tẹ̀ lé àpẹẹrẹ Kéènì.+ Láìronú, wọ́n ṣe ohun tí kò tọ́ bíi ti Báláámù+ torí ohun tí wọ́n máa rí gbà, ọ̀rọ̀ ọ̀tẹ̀+ wọn sì mú kí wọ́n ṣègbé bíi ti Kórà!+