ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 25:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Yóò darí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ láti ṣe ohun tí ó tọ́,*+

      Yóò sì kọ́ àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ ní ọ̀nà rẹ̀.+

  • Sáàmù 32:8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  8 “Màá fún ọ ní ìjìnlẹ̀ òye, màá sì kọ́ ọ ní ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+

      Màá fún ọ ní ìmọ̀ràn pẹ̀lú ojú mi lára rẹ.+

  • Sáàmù 37:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  23 Jèhófà máa ń darí ẹsẹ̀ ẹni*+

      Nígbà tí inú Rẹ̀ bá dùn sí ọ̀nà ẹni náà.+

  • Sáàmù 143:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Kọ́ mi láti máa ṣe ìfẹ́ rẹ,+

      Nítorí ìwọ ni Ọlọ́run mi.

      Ẹ̀mí rẹ dára;

      Kí ó máa darí mi ní ilẹ̀ tó tẹ́jú.*

  • Òwe 3:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Máa kíyè sí i ní gbogbo ọ̀nà rẹ,+

      Á sì mú kí àwọn ọ̀nà rẹ tọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́