Sáàmù 90:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+ Hábákúkù 1:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+ Ìfihàn 1:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+
2 Kí a tó bí àwọn òkèTàbí kí o tó dá ayé àti ilẹ̀ tó ń méso jáde,*+Láti ayérayé dé ayérayé,* ìwọ ni Ọlọ́run.+
12 Jèhófà, ṣebí láti ayérayé ni ìwọ ti wà?+ Ọlọ́run mi, Ẹni Mímọ́ mi, ìwọ kì í kú.*+ Jèhófà, ìwọ lo yàn wọ́n láti ṣèdájọ́;Àpáta mi,+ o lò wọ́n láti fìyà jẹni.*+
8 Jèhófà* Ọlọ́run sọ pé, “Èmi ni Ááfà àti Ómégà,*+ Ẹni tó ti wà tipẹ́, tó wà báyìí, tó sì ń bọ̀, Olódùmarè.”+