Diutarónómì 33:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Jẹ́ kí wọ́n fi àwọn ìdájọ́ rẹ kọ́ Jékọ́bù,+Kí wọ́n sì fi Òfin rẹ kọ́ Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ kí wọ́n sun tùràrí láti mú òórùn dídùn jáde sí ọ*+Àti odindi ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.+ Àìsáyà 48:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+
10 Jẹ́ kí wọ́n fi àwọn ìdájọ́ rẹ kọ́ Jékọ́bù,+Kí wọ́n sì fi Òfin rẹ kọ́ Ísírẹ́lì.+ Jẹ́ kí wọ́n sun tùràrí láti mú òórùn dídùn jáde sí ọ*+Àti odindi ẹbọ lórí pẹpẹ rẹ.+
17 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, Olùtúnrà rẹ, Ẹni Mímọ́ Ísírẹ́lì:+ “Èmi, Jèhófà, ni Ọlọ́run rẹ,Ẹni tó ń kọ́ ọ kí o lè ṣe ara rẹ láǹfààní,*+Ẹni tó ń jẹ́ kí o mọ ọ̀nà tó yẹ kí o máa rìn.+