Sáàmù 63:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ìpín tó dára jù lọ, tó sì ṣeyebíye jù lọ la fi tẹ́ mi* lọ́rùn,*Torí náà, ẹnu mi yóò yìn ọ́, ètè mi yóò sì kọrin.+ Sáàmù 71:17 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 17 Ọlọ́run, o ti kọ́ mi láti ìgbà èwe mi wá,+Títí di báyìí, mò ń kéde àwọn iṣẹ́ àgbàyanu rẹ.+ Sáàmù 145:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Wọ́n á máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ bí wọ́n ṣe ń sọ nípa ọ̀pọ̀ oore rẹ,+Wọ́n á sì máa kígbe ayọ̀ nítorí òdodo rẹ.+
5 Ìpín tó dára jù lọ, tó sì ṣeyebíye jù lọ la fi tẹ́ mi* lọ́rùn,*Torí náà, ẹnu mi yóò yìn ọ́, ètè mi yóò sì kọrin.+
7 Wọ́n á máa yọ̀ ṣẹ̀ṣẹ̀ bí wọ́n ṣe ń sọ nípa ọ̀pọ̀ oore rẹ,+Wọ́n á sì máa kígbe ayọ̀ nítorí òdodo rẹ.+