Sáàmù 37:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà, kí o sì máa ṣe rere;+Máa gbé ayé,* kí o sì máa hùwà òtítọ́.+ Sáàmù 62:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé e ní gbogbo ìgbà. Ẹ tú ọkàn yín jáde níwájú rẹ̀.+ Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò fún wa.+ (Sélà) Òwe 3:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Fi gbogbo ọkàn rẹ gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà,+Má sì gbára lé òye tìrẹ.+ 1 Pétérù 4:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Nítorí náà, kí àwọn tó ń jìyà lọ́nà tó bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu máa fi ara* wọn lé Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́ lọ́wọ́,* kí wọ́n sì máa ṣe rere.+
8 Ẹ gbẹ́kẹ̀ lé e ní gbogbo ìgbà. Ẹ tú ọkàn yín jáde níwájú rẹ̀.+ Ọlọ́run jẹ́ ibi ààbò fún wa.+ (Sélà)
19 Nítorí náà, kí àwọn tó ń jìyà lọ́nà tó bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu máa fi ara* wọn lé Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́ lọ́wọ́,* kí wọ́n sì máa ṣe rere.+