ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 30:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 “Tí gbogbo ọ̀rọ̀ yìí bá ṣẹ sí ọ lára, ìbùkún àti ègún tí mo fi síwájú rẹ,+ tí o sì rántí wọn*+ ní gbogbo orílẹ̀-èdè tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tú ọ+ ká sí,

  • Diutarónómì 30:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 nígbà náà, Jèhófà Ọlọ́run rẹ máa mú àwọn èèyàn rẹ tí wọ́n kó lẹ́rú+ pa dà wá, ó máa ṣàánú+ rẹ, ó sì máa kó ọ jọ látọ̀dọ̀ gbogbo èèyàn tí Jèhófà Ọlọ́run rẹ tú ọ+ ká sí.

  • Sáàmù 30:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Nítorí ìbínú rẹ̀ lórí èèyàn kì í pẹ́ rárá,+

      Àmọ́ ojú rere* rẹ̀ sí èèyàn wà títí ọjọ́ ayé.+

      Ẹkún lè wà ní àṣálẹ́, àmọ́ tó bá di àárọ̀, igbe ayọ̀ á sọ.+

  • Sáàmù 106:47
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 47 Gbà wá, Jèhófà Ọlọ́run wa,+

      Kí o sì kó wa jọ látinú àwọn orílẹ̀-èdè+

      Ká lè máa fi ọpẹ́ fún orúkọ mímọ́ rẹ,

      Ká sì máa yọ̀ bí a ṣe ń yìn ọ́.*+

  • Àìsáyà 27:12
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà máa lu èso jáde láti Odò* tó ń ṣàn títí dé Àfonífojì Íjíbítì,+ a sì máa kó yín jọ ní ọ̀kọ̀ọ̀kan, ẹ̀yin èèyàn Ísírẹ́lì.+

  • Jeremáyà 29:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Tó bá ti pé àádọ́rin (70) ọdún tí ẹ ti wà ní Bábílónì, màá yí ojú mi sí yín,+ màá sì mú ìlérí mi ṣẹ láti mú yín pa dà wá sí ibí yìí.’+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́