ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 1:23
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 “Wò ó! Wúńdíá náà máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan, wọ́n máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì,”+ tó túmọ̀ sí, “Ọlọ́run Wà Pẹ̀lú Wa.”+

  • Lúùkù 1:30-35
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 30 Áńgẹ́lì náà wá sọ fún un pé: “Má bẹ̀rù, Màríà, torí o ti rí ojúure Ọlọ́run. 31 Wò ó! o máa lóyún,* o sì máa bí ọmọkùnrin kan,+ kí o pe orúkọ rẹ̀ ní Jésù.+ 32 Ẹni yìí máa jẹ́ ẹni ńlá,+ wọ́n á máa pè é ní Ọmọ Ẹni Gíga Jù Lọ,+ Jèhófà* Ọlọ́run sì máa fún un ní ìtẹ́ Dáfídì bàbá rẹ̀,+ 33 ó máa jẹ Ọba lórí ilé Jékọ́bù títí láé, Ìjọba rẹ̀ ò sì ní lópin.”+

      34 Àmọ́ Màríà sọ fún áńgẹ́lì náà pé: “Báwo ló ṣe máa ṣẹlẹ̀, nígbà tó jẹ́ pé mi ò bá ọkùnrin lò pọ̀?”+ 35 Áńgẹ́lì náà dá a lóhùn pé: “Ẹ̀mí mímọ́ máa bà lé ọ,+ agbára Ẹni Gíga Jù Lọ sì máa ṣíji bò ọ́. Ìdí nìyẹn tí a fi máa pe ẹni tí o bí ní mímọ́,+ Ọmọ Ọlọ́run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́