ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 30:5
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  5 Nítorí ìbínú rẹ̀ lórí èèyàn kì í pẹ́ rárá,+

      Àmọ́ ojú rere* rẹ̀ sí èèyàn wà títí ọjọ́ ayé.+

      Ẹkún lè wà ní àṣálẹ́, àmọ́ tó bá di àárọ̀, igbe ayọ̀ á sọ.+

  • Sáàmù 103:9
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  9 Kì í fìgbà gbogbo wá àṣìṣe,+

      Kì í sì í bínú títí lọ.+

  • Sáàmù 103:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Nítorí bí ọ̀run ṣe ga ju ayé,

      Bẹ́ẹ̀ ni ìfẹ́ tí kì í yẹ̀ tó ní sí àwọn tó bẹ̀rù rẹ̀ ṣe ga.+

  • Àìsáyà 54:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 “Torí mo pa ọ́ tì fún ìgbà díẹ̀,

      Àmọ́ màá ṣàánú rẹ gidigidi, màá sì kó ọ jọ pa dà.+

  • Jeremáyà 31:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “Ǹjẹ́ Éfúrémù kì í ṣe ọmọ mi àtàtà, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́?+

      Torí bí mo ṣe ń sọ̀rọ̀ sí i tó, síbẹ̀ mo ṣì ń rántí rẹ̀.

      Ìdí nìyẹn tí ọkàn* mi fi gbé sókè nítorí rẹ̀.+

      Ó sì dájú pé màá ṣàánú rẹ̀,” ni Jèhófà wí.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́