ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jẹ́nẹ́sísì 10:4
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 4 Àwọn ọmọ Jáfánì ni Élíṣáhì,+ Táṣíṣì,+ Kítímù+ àti Dódánímù.

  • Nọ́ńbà 24:24
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 24 Àwọn ọkọ̀ òkun máa wá láti etíkun Kítímù,+

      Wọ́n á sì fìyà jẹ Ásíríà,+

      Wọ́n á tún fìyà jẹ Ébérì.

      Àmọ́ ṣe lòun náà máa ṣègbé pátápátá.”

  • Àìsáyà 23:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 23 Ìkéde nípa Tírè:+

      Ẹ pohùn réré ẹkún, ẹ̀yin ọkọ̀ òkun Táṣíṣì!+

      Torí a ti run èbúté; kò ṣeé wọ̀.

      A ti ṣi í payá fún wọn láti ilẹ̀ Kítímù.+

  • Jeremáyà 2:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 ‘Ṣùgbọ́n ẹ kọjá sí etíkun* àwọn ará Kítímù+ kí ẹ sì wò ó.

      Bẹ́ẹ̀ ni, ẹ ránṣẹ́ lọ sí Kídárì,+ kí ẹ sì fara balẹ̀ wò ó;

      Kí ẹ sì wò ó bóyá ohun tó dà bí èyí ti ṣẹlẹ̀ rí.

  • Ìsíkíẹ́lì 27:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Àwọn igi ràgàjì* ti Báṣánì ni wọ́n fi ṣe àwọn àjẹ̀ rẹ,

      Igi sípírẹ́sì tí wọ́n fi eyín erin tẹ́ inú rẹ̀ láti àwọn erékùṣù Kítímù+ ni wọ́n fi ṣe iwájú ọkọ̀ rẹ.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́