ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 2:7
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  7 Ẹ jẹ́ kí n kéde àṣẹ Jèhófà;

      Ó sọ fún mi pé: “Ìwọ ni ọmọ mi;+

      Òní ni mo di bàbá rẹ.+

  • Mátíù 14:33
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 33 Àwọn tó wà nínú ọkọ̀ ojú omi náà wá tẹrí ba* fún un, wọ́n sọ pé: “Ọmọ Ọlọ́run ni ọ́ lóòótọ́.”

  • Ìṣe 9:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, ó bẹ̀rẹ̀ sí í wàásù nípa Jésù nínú àwọn sínágọ́gù, pé ẹni yìí ni Ọmọ Ọlọ́run.

  • Ìṣe 9:22
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 22 Àmọ́ Sọ́ọ̀lù ń gba agbára kún agbára, ó sì ń pa àwọn Júù tó ń gbé ní Damásíkù lẹ́nu mọ́, bí ó ṣe ń fi ẹ̀rí tó bọ́gbọ́n mu hàn pé Jésù ni Kristi náà.+

  • Hébérù 1:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Ní báyìí, ní òpin àwọn ọjọ́ yìí, ó ti bá wa sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ Ọmọ+ tó yàn ṣe ajogún ohun gbogbo,+ nípasẹ̀ ẹni tó dá àwọn ètò àwọn nǹkan.*+

  • 1 Jòhánù 4:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Ẹnikẹ́ni tó bá gbà pé Ọmọ Ọlọ́run ni Jésù,+ Ọlọ́run wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú ẹni yẹn, òun náà sì wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Ọlọ́run.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́