-
Ìṣe 18:5, 6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Nígbà tí Sílà+ àti Tímótì+ wá láti Makedóníà, ọ̀rọ̀ Ọlọ́run mú kí ọwọ́ Pọ́ọ̀lù dí gan-an, ó ń jẹ́rìí fún àwọn Júù láti fi ẹ̀rí hàn pé Jésù ni Kristi náà.+ 6 Àmọ́ nígbà tí wọn ò yéé ṣàtakò sí i, tí wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ láìdáa, ó gbọn ẹ̀wù rẹ̀,+ ó sì sọ fún wọn pé: “Kí ẹ̀jẹ̀ yín wà lórí ẹ̀yin fúnra yín.+ Ọrùn mi mọ́.+ Láti ìsinsìnyí lọ, màá lọ máa bá àwọn èèyàn orílẹ̀-èdè.”+
-