ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Dáníẹ́lì 12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Dáníẹ́lì

      • “Àkókò òpin” àti ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn náà (1-13)

        • Máíkẹ́lì máa dìde (1)

        • Àwọn tó ní ìjìnlẹ̀ òye máa tàn yinrin (3)

        • Ìmọ̀ tòótọ́ máa pọ̀ yanturu (4)

        • Dáníẹ́lì máa dìde fún ìpín rẹ̀ (13)

Dáníẹ́lì 12:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ta Ló Dà Bí Ọlọ́run?”

  • *

    Ní Héb., “àwọn ọmọ àwọn èèyàn rẹ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:13; Jud 9; Ifi 12:7, 8
  • +Da 10:21
  • +Ais 26:20; Joẹ 2:31, 32; Mt 24:21, 22; Ifi 7:13, 14
  • +Mal 3:16; Lk 10:20; Ifi 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2020, ojú ìwé 16

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2015, ojú ìwé 29

    11/1/1993, ojú ìwé 23

    5/1/1992, ojú ìwé 14, 17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 288-290

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 34

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 134, 184-185

Dáníẹ́lì 12:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 290-291

Dáníẹ́lì 12:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2016, ojú ìwé 23

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 22-23

    3/15/2010, ojú ìwé 23

    9/1/2007, ojú ìwé 20

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 292-293

Dáníẹ́lì 12:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “yẹ̀ ẹ́ [ìyẹn, ìwé náà] wò fínnífínní.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 8:17, 26; 12:9
  • +Ais 11:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 19

    Bíbélì Kọ́ Wa, ojú ìwé 99

    Bíbélì Fi Kọ́ni, ojú ìwé 92

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 35-36

    Ìfẹ́ Jèhófà, ẹ̀kọ́ 3

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2012, ojú ìwé 3-7

    8/15/2009, ojú ìwé 14-16

    5/15/2000, ojú ìwé 11

    11/1/1993, ojú ìwé 13

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 289, 293-294, 309-310

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 173-174

Dáníẹ́lì 12:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 294

Dáníẹ́lì 12:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “aṣọ àtàtà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 10:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 294

Dáníẹ́lì 12:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, àkókò mẹ́ta àti ààbọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 4:34; Ifi 4:9; 10:6
  • +Da 8:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 294-296

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    8/1/1994, ojú ìwé 31

    11/1/1993, ojú ìwé 9-10

Dáníẹ́lì 12:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Lk 18:34; Iṣe 1:7; 1Pe 1:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 296-297

Dáníẹ́lì 12:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 8:17, 26; 10:14; 12:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 289

Dáníẹ́lì 12:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 11:35
  • +Sm 111:10; Da 11:33; 12:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 296-297, 300

Dáníẹ́lì 12:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹbọ ìgbà gbogbo.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 8:11
  • +Da 11:31; Mk 13:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 297-301

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1993, ojú ìwé 10-11

Dáníẹ́lì 12:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tó ń retí lójú méjèèjì.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 301, 303-304

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    11/1/1993, ojú ìwé 11-12

Dáníẹ́lì 12:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ní ibi tí a pín ọ sí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 11:24; Iṣe 17:31; 24:15; Ifi 20:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2017, ojú ìwé 7

    Jí!,

    7/2012, ojú ìwé 31

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2005, ojú ìwé 12

    5/15/2000, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Dáníẹ́lì, ojú ìwé 306-319

Àwọn míì

Dán. 12:1Da 10:13; Jud 9; Ifi 12:7, 8
Dán. 12:1Da 10:21
Dán. 12:1Ais 26:20; Joẹ 2:31, 32; Mt 24:21, 22; Ifi 7:13, 14
Dán. 12:1Mal 3:16; Lk 10:20; Ifi 3:5
Dán. 12:4Da 8:17, 26; 12:9
Dán. 12:4Ais 11:9
Dán. 12:5Da 10:4
Dán. 12:6Da 10:5, 6
Dán. 12:7Da 4:34; Ifi 4:9; 10:6
Dán. 12:7Da 8:24
Dán. 12:8Lk 18:34; Iṣe 1:7; 1Pe 1:10, 11
Dán. 12:9Da 8:17, 26; 10:14; 12:4
Dán. 12:10Da 11:35
Dán. 12:10Sm 111:10; Da 11:33; 12:3
Dán. 12:11Da 8:11
Dán. 12:11Da 11:31; Mk 13:14
Dán. 12:13Jo 11:24; Iṣe 17:31; 24:15; Ifi 20:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Dáníẹ́lì 12:1-13

Dáníẹ́lì

12 “Ní àkókò yẹn, Máíkẹ́lì*+ máa dìde, ọmọ aládé ńlá+ tó dúró nítorí àwọn èèyàn rẹ.* Àkókò wàhálà máa wáyé, èyí tí irú rẹ̀ kò wáyé rí látìgbà tí orílẹ̀-èdè ti wà títí di àkókò yẹn. Ní àkókò yẹn, àwọn èèyàn rẹ máa yè bọ́,+ gbogbo àwọn tí orúkọ wọn wà nínú ìwé.+ 2 Ọ̀pọ̀ àwọn tó ń sùn nínú erùpẹ̀ ilẹ̀ máa jí, àwọn kan sí ìyè àìnípẹ̀kun, àwọn míì sí ẹ̀gàn àti sí ìkórìíra ayérayé.

3 “Àwọn tó ní ìjìnlẹ̀ òye máa tàn yinrin bí òfúrufú, àwọn tí wọ́n sì ń mú ọ̀pọ̀lọpọ̀ wá sí òdodo máa tàn bí ìràwọ̀, títí láé àti láéláé.

4 “Ní tìrẹ, Dáníẹ́lì, ṣe àwọn ọ̀rọ̀ náà ní àṣírí, kí o sì gbé èdìdì lé ìwé náà títí di àkókò òpin.+ Ọ̀pọ̀ máa lọ káàkiri,* ìmọ̀ tòótọ́ sì máa pọ̀ yanturu.”+

5 Èmi Dáníẹ́lì wá wò, mo sì rí àwọn méjì míì tó dúró síbẹ̀, ọ̀kan ní etí omi níbí àti ìkejì ní etí omi lọ́hùn-ún.+ 6 Ọ̀kan wá sọ fún ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀,*+ tó wà lórí omi tó ń ṣàn pé: “Ìgbà wo ni àwọn ohun àgbàyanu yìí máa dópin?” 7 Nígbà náà, mo gbọ́ tí ọkùnrin tó wọ aṣọ ọ̀gbọ̀ náà, tó wà lórí omi tó ń ṣàn sọ̀rọ̀, bó ṣe gbé ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀ àti ọwọ́ òsì rẹ̀ sókè ọ̀run, tó sì fi Ẹni tó wà láàyè títí láé búra pé:+ “Ó máa jẹ́ fún àkókò tí a yàn, àwọn àkókò tí a yàn àti ààbọ̀ àkókò.* Gbàrà tí fífọ́ agbára àwọn èèyàn mímọ́ túútúú bá ti dópin,+ gbogbo nǹkan yìí máa dópin.”

8 Ní tèmi, mo gbọ́, ṣùgbọ́n kò yé mi;+ mo wá sọ pé: “Olúwa mi, kí làwọn nǹkan yìí máa yọrí sí?”

9 Ó sì sọ pé: “Máa lọ, Dáníẹ́lì, torí pé ọ̀rọ̀ náà máa jẹ́ àṣírí, a sì máa gbé èdìdì lé e títí di àkókò òpin.+ 10 Ọ̀pọ̀ máa wẹ ara wọn mọ́, wọ́n máa sọ ara wọn di funfun, a sì máa yọ́ wọn mọ́.+ Àwọn ẹni burúkú máa hùwà burúkú, kò sì ní yé ìkankan nínú àwọn ẹni burúkú; ṣùgbọ́n àwọn tó ní ìjìnlẹ̀ òye máa lóye.+

11 “Látìgbà tí a bá ti mú ohun tó ń ṣẹlẹ̀ nígbà gbogbo*+ kúrò, tí a sì ti gbé ohun ìríra tó ń fa ìsọdahoro kalẹ̀,+ ẹgbẹ̀rún kan ó lé igba àti àádọ́rùn-ún (1,290) ọjọ́ máa wà.

12 “Aláyọ̀ ni ẹni tó ń fojú sọ́nà,* tó sì dé ní ẹgbẹ̀rún kan ó lé ọgọ́rùn-ún mẹ́ta àti márùndínlógójì (1,335) ọjọ́!

13 “Àmọ́ ní tìrẹ, máa lọ sí òpin. O máa sinmi, àmọ́ wàá dìde fún ìpín rẹ* ní òpin àwọn ọjọ́.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́