ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 21
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Àwọn Ọba

      • Mánásè di ọba Júdà; ó ta ẹ̀jẹ̀ sílẹ̀ (1-18)

        • Wọ́n máa pa Jerúsálẹ́mù run (12-15)

      • Ámọ́nì di ọba Júdà (19-26)

2 Àwọn Ọba 21:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 3:13; Mt 1:10
  • +2Kr 33:1

2 Àwọn Ọba 21:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:30, 31; 2Kr 36:14; Isk 16:51
  • +2Kr 33:2-6

2 Àwọn Ọba 21:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 18:1, 4
  • +2Ọb 23:4
  • +1Ọb 16:30, 32
  • +Di 4:19

2 Àwọn Ọba 21:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 32:34
  • +Di 12:5; 2Sa 7:12, 13; 1Ọb 8:29; 9:3

2 Àwọn Ọba 21:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Isk 8:16
  • +1Ọb 6:36; 7:12

2 Àwọn Ọba 21:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:26
  • +Le 20:27; Di 18:10, 11

2 Àwọn Ọba 21:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 23:6
  • +2Kr 33:7-9

2 Àwọn Ọba 21:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kr 17:9
  • +Di 28:1

2 Àwọn Ọba 21:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 7:1

2 Àwọn Ọba 21:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:10; 36:15, 16; Jer 7:25; Mt 23:37

2 Àwọn Ọba 21:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kí ọ̀rọ̀ Hébérù yìí ní í ṣe pẹ̀lú ọ̀rọ̀ tí wọ́n ń lò fún “ìgbẹ́,” wọ́n sì máa ń lò ó fún ohun tí wọ́n bá kórìíra.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 15:16
  • +Le 18:24, 25; 2Ọb 23:26; 24:3; Jer 15:4

2 Àwọn Ọba 21:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:16, 17; Mik 3:12
  • +Jer 19:3

2 Àwọn Ọba 21:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “okùn tí a fi ń mọ̀ bóyá nǹkan gún régé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:17; Ida 2:8
  • +2Ọb 17:6; Isk 23:33
  • +1Ọb 21:21; 2Ọb 10:11
  • +Jer 25:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2022,

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 162

2 Àwọn Ọba 21:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 32:9; 2Ọb 17:18
  • +Le 26:25; Di 28:63

2 Àwọn Ọba 21:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 9:21; 31:29; Ond 2:11, 13

2 Àwọn Ọba 21:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 24:3, 4; Jer 2:34; Mt 23:30; Heb 11:37

2 Àwọn Ọba 21:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:23, 26

2 Àwọn Ọba 21:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 1:10
  • +2Kr 33:21

2 Àwọn Ọba 21:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:22, 23

2 Àwọn Ọba 21:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:1, 3

2 Àwọn Ọba 21:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 22:16, 17; Jer 2:13

2 Àwọn Ọba 21:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 33:25

2 Àwọn Ọba 21:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:18
  • +Mt 1:10

Àwọn míì

2 Ọba 21:11Kr 3:13; Mt 1:10
2 Ọba 21:12Kr 33:1
2 Ọba 21:2Di 12:30, 31; 2Kr 36:14; Isk 16:51
2 Ọba 21:22Kr 33:2-6
2 Ọba 21:32Ọb 18:1, 4
2 Ọba 21:32Ọb 23:4
2 Ọba 21:31Ọb 16:30, 32
2 Ọba 21:3Di 4:19
2 Ọba 21:4Jer 32:34
2 Ọba 21:4Di 12:5; 2Sa 7:12, 13; 1Ọb 8:29; 9:3
2 Ọba 21:5Isk 8:16
2 Ọba 21:51Ọb 6:36; 7:12
2 Ọba 21:6Le 19:26
2 Ọba 21:6Le 20:27; Di 18:10, 11
2 Ọba 21:72Ọb 23:6
2 Ọba 21:72Kr 33:7-9
2 Ọba 21:81Kr 17:9
2 Ọba 21:8Di 28:1
2 Ọba 21:9Di 7:1
2 Ọba 21:102Kr 33:10; 36:15, 16; Jer 7:25; Mt 23:37
2 Ọba 21:11Jẹ 15:16
2 Ọba 21:11Le 18:24, 25; 2Ọb 23:26; 24:3; Jer 15:4
2 Ọba 21:122Ọb 22:16, 17; Mik 3:12
2 Ọba 21:12Jer 19:3
2 Ọba 21:13Ais 28:17; Ida 2:8
2 Ọba 21:132Ọb 17:6; Isk 23:33
2 Ọba 21:131Ọb 21:21; 2Ọb 10:11
2 Ọba 21:13Jer 25:9
2 Ọba 21:14Di 32:9; 2Ọb 17:18
2 Ọba 21:14Le 26:25; Di 28:63
2 Ọba 21:15Di 9:21; 31:29; Ond 2:11, 13
2 Ọba 21:162Ọb 24:3, 4; Jer 2:34; Mt 23:30; Heb 11:37
2 Ọba 21:182Ọb 21:23, 26
2 Ọba 21:19Mt 1:10
2 Ọba 21:192Kr 33:21
2 Ọba 21:202Kr 33:22, 23
2 Ọba 21:212Ọb 21:1, 3
2 Ọba 21:222Ọb 22:16, 17; Jer 2:13
2 Ọba 21:242Kr 33:25
2 Ọba 21:262Ọb 21:18
2 Ọba 21:26Mt 1:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Àwọn Ọba 21:1-26

Àwọn Ọba Kejì

21 Ọmọ ọdún méjìlá (12) ni Mánásè+ nígbà tó jọba, ọdún márùndínlọ́gọ́ta (55) ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Héfísíbà. 2 Ó ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà, torí pé ó ń ṣe àwọn ohun ìríra bíi ti àwọn orílẹ̀-èdè+ tí Jèhófà lé kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+ 3 Ó tún àwọn ibi gíga kọ́, èyí tí Hẹsikáyà bàbá rẹ̀ pa run,+ ó mọ àwọn pẹpẹ fún Báálì, ó sì ṣe òpó òrìṣà,*+ bí Áhábù ọba Ísírẹ́lì ti ṣe.+ Ó forí balẹ̀ fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run, ó sì ń sìn wọ́n.+ 4 Ó tún mọ àwọn pẹpẹ sí ilé Jèhófà,+ níbi tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ pé: “Inú Jerúsálẹ́mù ni màá fi orúkọ mi sí.”+ 5 Ó mọ àwọn pẹpẹ fún gbogbo ọmọ ogun ọ̀run+ sí àgbàlá méjì nínú ilé Jèhófà.+ 6 Ó sun ọmọ rẹ̀ nínú iná; ó ń pidán, ó ń woṣẹ́,+ ó sì yan àwọn abẹ́mìílò àti àwọn woṣẹ́woṣẹ́.+ Ohun búburú tó pọ̀ gan-an ló ṣe lójú Jèhófà, ó sì tipa bẹ́ẹ̀ mú un bínú.

7 Ó gbé ère òpó òrìṣà*+ tó gbẹ́ wá sínú ilé tí Jèhófà sọ nípa rẹ̀ fún Dáfídì àti Sólómọ́nì ọmọ rẹ̀ pé: “Inú ilé yìí àti ní Jerúsálẹ́mù, tí mo ti yàn nínú gbogbo ẹ̀yà Ísírẹ́lì, ni màá fi orúkọ mi sí títí láé.+ 8 Mi ò tún ní mú kí Ísírẹ́lì rìn gbéregbère kúrò ní ilẹ̀ tí mo fún àwọn baba ńlá wọn,+ tí wọ́n bá ṣáà ti rí i pé wọ́n tẹ̀ lé gbogbo ohun tí mo pa láṣẹ fún wọn,+ ìyẹn gbogbo Òfin tí Mósè ìránṣẹ́ mi pa láṣẹ fún wọn pé kí wọ́n máa tẹ̀ lé.” 9 Àmọ́, wọn kò ṣègbọràn, Mánásè sì ń ṣì wọ́n lọ́nà, ó ń mú kí wọ́n ṣe ohun tó burú ju ti àwọn orílẹ̀-èdè tí Jèhófà pa run kúrò níwájú àwọn ọmọ Ísírẹ́lì.+

10 Jèhófà ń gbẹnu àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀ wòlíì sọ̀rọ̀ léraléra+ pé: 11 “Mánásè ọba Júdà ṣe gbogbo àwọn ohun ìríra yìí; ó ṣe ohun tó burú ju ti gbogbo àwọn Ámórì+ tó wà ṣáájú rẹ̀,+ ó sì fi àwọn òrìṣà ẹ̀gbin* rẹ̀ mú Júdà dẹ́ṣẹ̀. 12 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí: ‘Wò ó, màá fa àjálù bá Jerúsálẹ́mù+ àti Júdà, tó jẹ́ pé bí ẹnikẹ́ni bá gbọ́ nípa rẹ̀, etí rẹ̀ méjèèjì á hó yee.+ 13 Màá na okùn ìdíwọ̀n+ tí a lò fún Samáríà+ sórí Jerúsálẹ́mù àti irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú* tí a lò fún ilé Áhábù,+ màá sì fọ Jerúsálẹ́mù mọ́ bí ẹni fọ abọ́ mọ́, màá nù ún, màá sì dojú rẹ̀ dé.+ 14 Màá pa àwọn tó ṣẹ́ kù nínú ogún mi tì,+ màá sì fi wọ́n lé àwọn ọ̀tá wọn lọ́wọ́, àwọn ọ̀tá wọn á kó wọn lẹ́rú, wọ́n á sì kó wọn lẹ́rù,+ 15 nítorí pé wọ́n ṣe ohun tó burú ní ojú mi, tí wọ́n sì ń mú mi bínú láti ọjọ́ tí àwọn baba ńlá wọn ti jáde kúrò ní Íjíbítì títí di òní yìí.’”+

16 Mánásè ta ẹ̀jẹ̀ àwọn aláìṣẹ̀ sílẹ̀ lọ́pọ̀lọpọ̀ débi pé ó kún Jerúsálẹ́mù láti ìkángun kan dé ìkángun kejì,+ yàtọ̀ sí ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ èyí tí ó mú Júdà ṣẹ̀, tí wọ́n fi ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà. 17 Ní ti ìyókù ìtàn Mánásè àti gbogbo ohun tí ó ṣe àti ẹ̀ṣẹ̀ tí ó dá, ǹjẹ́ wọn ò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? 18 Níkẹyìn, Mánásè sinmi pẹ̀lú àwọn baba ńlá rẹ̀, wọ́n sì sin ín sínú ọgbà ilé rẹ̀, nínú ọgbà Úúsà;+ Ámọ́nì ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

19 Ẹni ọdún méjìlélógún (22) ni Ámọ́nì+ nígbà tó jọba, ọdún méjì ló sì fi ṣàkóso ní Jerúsálẹ́mù.+ Orúkọ ìyá rẹ̀ ni Méṣúlémétì ọmọ Hárúsì láti Jótíbà. 20 Ó ń ṣe ohun tó burú ní ojú Jèhófà bí Mánásè bàbá rẹ̀ ti ṣe.+ 21 Ó ń rìn ní gbogbo ọ̀nà tí bàbá rẹ̀ rìn, ó ń sin àwọn òrìṣà ẹ̀gbin tí bàbá rẹ̀ sìn, ó sì ń forí balẹ̀ fún wọn.+ 22 Torí náà, ó fi Jèhófà Ọlọ́run àwọn baba ńlá rẹ̀ sílẹ̀, kò sì rìn ní ọ̀nà Jèhófà.+ 23 Níkẹyìn, àwọn ìránṣẹ́ Ámọ́nì dìtẹ̀ mọ́ ọn, wọ́n sì pa á nínú ilé rẹ̀. 24 Àmọ́ àwọn èèyàn ilẹ̀ náà pa gbogbo àwọn tó dìtẹ̀ mọ́ Ọba Ámọ́nì, wọ́n sì fi Jòsáyà ọmọ rẹ̀ jọba ní ipò rẹ̀.+ 25 Ní ti ìyókù ìtàn Ámọ́nì àti ohun tí ó ṣe, ǹjẹ́ kò wà lákọsílẹ̀ nínú ìwé ìtàn ìgbà àwọn ọba Júdà? 26 Nítorí náà, wọ́n sin ín sí sàréè rẹ̀ nínú ọgbà Úúsà,+ Jòsáyà+ ọmọ rẹ̀ sì jọba ní ipò rẹ̀.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́