ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Iṣẹ́ ìwàásù Pọ́ọ̀lù ní Kọ́ríńtì (1-5)

      • Ọgbọ́n Ọlọ́run ju ti èèyàn lọ (6-10)

      • Ẹni tara àti ẹni tẹ̀mí (11-16)

1 Kọ́ríńtì 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 1:17
  • +Ef 3:5, 6; Kol 2:2

1 Kọ́ríńtì 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “mọ́ òpó igi.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 6:14

1 Kọ́ríńtì 2:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

1 Kọ́ríńtì 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:18, 19; 1Kọ 4:20; 1Tẹ 1:5

1 Kọ́ríńtì 2:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsìkò yìí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 14:20; Ef 4:13; Heb 5:14
  • +1Kọ 15:24

1 Kọ́ríńtì 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 16:25, 26; Ef 3:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 189-198

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2003, ojú ìwé 24-25

    6/1/1997, ojú ìwé 13

    8/15/1994, ojú ìwé 13

1 Kọ́ríńtì 2:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àsìkò yìí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí “kan Olúwa ológo mọ́ òpó igi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 7:48; Iṣe 13:27, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2019, ojú ìwé 4

1 Kọ́ríńtì 2:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 64:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 366

1 Kọ́ríńtì 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 16:17; Mk 4:11; Ef 3:5; 2Ti 1:9, 10; 1Pe 1:12
  • +Jo 14:26; 1Jo 2:27
  • +Ro 11:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2010, ojú ìwé 20-24

    11/1/2007, ojú ìwé 27-29

1 Kọ́ríńtì 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “àfi ẹ̀mí.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    2/8/1998, ojú ìwé 14-15

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1994, ojú ìwé 19

1 Kọ́ríńtì 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 15:26

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 54-56

    Ilé Ìṣọ́,

    10/15/2012, ojú ìwé 13

    7/15/2010, ojú ìwé 3-4

    10/1/2006, ojú ìwé 23-24

    4/1/2004, ojú ìwé 9-14

    9/1/1999, ojú ìwé 8-9

    10/1/1997, ojú ìwé 25-26

    4/1/1994, ojú ìwé 14-19

    Jí!,

    1/2010, ojú ìwé 26-27

1 Kọ́ríńtì 2:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pa àwọn ọ̀rọ̀ tẹ̀mí pọ̀ mọ́ àwọn nǹkan tẹ̀mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 2:8
  • +Jo 16:13

1 Kọ́ríńtì 2:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kì í gba.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2018, ojú ìwé 19

    Jí!,

    1/2010, ojú ìwé 26-27

1 Kọ́ríńtì 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2018, ojú ìwé 19-20

1 Kọ́ríńtì 2:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 40:13
  • +Ro 15:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2022, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    2/2018, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2015, ojú ìwé 13

    10/15/2010, ojú ìwé 3-7

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    8/1/2007, ojú ìwé 4-7

    3/15/2002, ojú ìwé 18

    2/15/2000, ojú ìwé 10-25

    9/1/1998, ojú ìwé 6

    6/15/1995, ojú ìwé 22-23

Àwọn míì

1 Kọ́r. 2:11Kọ 1:17
1 Kọ́r. 2:1Ef 3:5, 6; Kol 2:2
1 Kọ́r. 2:2Ga 6:14
1 Kọ́r. 2:4Ro 15:18, 19; 1Kọ 4:20; 1Tẹ 1:5
1 Kọ́r. 2:61Kọ 14:20; Ef 4:13; Heb 5:14
1 Kọ́r. 2:61Kọ 15:24
1 Kọ́r. 2:7Ro 16:25, 26; Ef 3:8, 9
1 Kọ́r. 2:8Jo 7:48; Iṣe 13:27, 28
1 Kọ́r. 2:9Ais 64:4
1 Kọ́r. 2:10Mt 16:17; Mk 4:11; Ef 3:5; 2Ti 1:9, 10; 1Pe 1:12
1 Kọ́r. 2:10Jo 14:26; 1Jo 2:27
1 Kọ́r. 2:10Ro 11:33
1 Kọ́r. 2:12Jo 15:26
1 Kọ́r. 2:13Kol 2:8
1 Kọ́r. 2:13Jo 16:13
1 Kọ́r. 2:15Ro 8:5
1 Kọ́r. 2:16Ais 40:13
1 Kọ́r. 2:16Ro 15:5
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 2:1-16

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

2 Torí náà, nígbà tí mo wá sọ́dọ̀ yín, ẹ̀yin ará, mi ò wá pẹ̀lú ọ̀rọ̀ kàbìtì-kàbìtì+ tàbí ọgbọ́n láti kéde àṣírí mímọ́+ Ọlọ́run fún yín. 2 Nítorí mo ti pinnu pé mi ò ní sọ̀rọ̀ nípa ohun míì láàárín yín àfi nípa Jésù Kristi, ẹni tí wọ́n kàn mọ́gi.*+ 3 Nígbà tí mo wá sọ́dọ̀ yín, ara mi ò le, ẹ̀rù ń bà mí, jìnnìjìnnì sì bá mi; 4 nígbà tí mo bá ń sọ̀rọ̀ tí mo sì ń wàásù, kì í ṣe àwọn ọ̀rọ̀ kàbìtì-kàbìtì tí àwọn ọlọ́gbọ́n ń lò ni mò ń sọ, àmọ́ ọ̀rọ̀ mi ń fi agbára ẹ̀mí mímọ́ hàn,+ 5 kí ẹ má bàa gbé ìgbàgbọ́ yín ka ọgbọ́n èèyàn, bí kò ṣe agbára Ọlọ́run.

6 Ní báyìí, àwa ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n láàárín àwọn tó dàgbà nípa tẹ̀mí,+ àmọ́ kì í ṣe ọgbọ́n ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí ti àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí, àwọn tó máa di asán.+ 7 Àmọ́ à ń sọ̀rọ̀ ọgbọ́n Ọlọ́run nínú àṣírí mímọ́,+ tó jẹ́ ọgbọ́n tí a fi pa mọ́, èyí tí Ọlọ́run ti yàn ṣáájú àwọn ètò àwọn nǹkan fún ògo wa. 8 Kò sí ìkankan nínú àwọn alákòóso ètò àwọn nǹkan yìí* tó mọ ọgbọ́n yìí,+ torí ká ní wọ́n mọ̀ ọ́n ni, wọn ì bá má pa Olúwa ológo.* 9 Àmọ́, bó ṣe wà lákọsílẹ̀ pé: “Ojú kò tíì rí, etí kò sì tíì gbọ́, bẹ́ẹ̀ ni ọkàn èèyàn kò tíì ro àwọn ohun tí Ọlọ́run ti pèsè sílẹ̀ fún àwọn tó nífẹ̀ẹ́ rẹ̀.”+ 10 Nítorí àwa ni Ọlọ́run ti ṣí wọn payá fún+ nípasẹ̀ ẹ̀mí rẹ̀,+ nítorí ẹ̀mí ń wá inú ohun gbogbo, títí kan àwọn ohun ìjìnlẹ̀ Ọlọ́run.+

11 Nítorí ta ló lè mọ ohun tí ẹnì kan ń rò àfi* onítọ̀hún? Bẹ́ẹ̀ náà ni kò sí ẹni tó mọ àwọn nǹkan ti Ọlọ́run, àfi ẹ̀mí Ọlọ́run. 12 Ní báyìí, kì í ṣe ẹ̀mí ayé ni àwa gbà, bí kò ṣe ẹ̀mí tó wá látọ̀dọ̀ Ọlọ́run,+ kí a lè mọ àwọn nǹkan tí Ọlọ́run fi ṣe wá lóore. 13 Àwọn nǹkan yìí ni àwa náà ń sọ, kì í ṣe pẹ̀lú àwọn ọ̀rọ̀ tí a fi kọ́ni nípa ọgbọ́n èèyàn,+ bí kò ṣe pẹ̀lú àwọn tí a fi kọ́ni nípasẹ̀ ẹ̀mí,+ bí a ṣe ń fi àwọn ọ̀rọ̀ tẹ̀mí ṣàlàyé àwọn nǹkan tẹ̀mí.*

14 Ẹni ti ara kì í tẹ́wọ́ gba* àwọn nǹkan ti ẹ̀mí Ọlọ́run, torí wọ́n jẹ́ nǹkan òmùgọ̀ lójú rẹ̀; kò sì lè mọ̀ wọ́n, nítorí ẹ̀mí la fi ń wádìí wọn. 15 Àmọ́ ẹni tẹ̀mí máa ń wádìí ohun gbogbo,+ ṣùgbọ́n èèyàn èyíkéyìí kì í wádìí òun fúnra rẹ̀. 16 Nítorí “ta ló ti wá mọ èrò inú Jèhófà,* kí ó lè kọ́ ọ lẹ́kọ̀ọ́?”+ Àmọ́ àwa ní èrò inú Kristi.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́