ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Kọ́ríńtì 13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Kọ́ríńtì

      • Ìfẹ́ jẹ́ ọ̀nà tó ta yọ (1-13)

1 Kọ́ríńtì 13:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ahọ́n.”

  • *

    Tàbí “aro.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 4

    7/15/1992, ojú ìwé 28

    5/1/1991, ojú ìwé 10-11

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 301

1 Kọ́ríńtì 13:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kúrò lọ sí ibòmíì.”

  • *

    Tàbí “wúlò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 12:8
  • +1Jo 4:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 301

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1992, ojú ìwé 28

1 Kọ́ríńtì 13:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 6:2
  • +2Kọ 9:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1992, ojú ìwé 28

    10/1/1991, ojú ìwé 20-21

1 Kọ́ríńtì 13:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìpamọ́ra.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:8
  • +1Tẹ 5:14
  • +Ro 13:10; Ef 4:32
  • +Ga 5:26
  • +1Pe 5:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 20

    10/15/2002, ojú ìwé 28

    11/1/2001, ojú ìwé 15-16

    2/15/1999, ojú ìwé 19-21

    9/15/1995, ojú ìwé 14-19

    9/1/1994, ojú ìwé 20

    10/15/1993, ojú ìwé 19, 21

    7/15/1992, ojú ìwé 28-29

    7/15/1991, ojú ìwé 14

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 302-303, 305-306

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 162-163

1 Kọ́ríńtì 13:5

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe ọ̀yájú.”

  • *

    Tàbí “Kì í kọ àkọsílẹ̀ ìṣeniléṣe.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:13; 1Kọ 14:40
  • +1Kọ 10:24; Flp 2:4
  • +Mt 5:39; Jem 1:19
  • +Ef 4:32; Kol 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 21-26

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 20-21

    8/1/2008, ojú ìwé 15

    2/15/1999, ojú ìwé 20-21

    10/15/1993, ojú ìwé 19-20

    7/15/1992, ojú ìwé 29

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 306-307

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 163-169

1 Kọ́ríńtì 13:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 21

    2/15/1999, ojú ìwé 20-21

    10/15/1993, ojú ìwé 20, 21-22

    7/15/1992, ojú ìwé 29-30

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 303, 307-308

    Jí!,

    1/2009, ojú ìwé 8-9

1 Kọ́ríńtì 13:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 4:8
  • +Iṣe 17:11
  • +Ro 8:25; 12:12
  • +1Tẹ 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 21

    12/15/2009, ojú ìwé 27-28

    7/15/2000, ojú ìwé 23

    2/15/1999, ojú ìwé 21-22

    10/15/1993, ojú ìwé 22

    7/15/1992, ojú ìwé 30

    11/1/1991, ojú ìwé 12-13

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 303-305

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 169-171

1 Kọ́ríńtì 13:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, kéèyàn máa fi iṣẹ́ ìyanu sọ àwọn èdè míì.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/2014, ojú ìwé 21

    12/15/2009, ojú ìwé 27-28

    7/1/2003, ojú ìwé 7

    10/15/1993, ojú ìwé 20-21

    8/15/1992, ojú ìwé 5

    7/15/1992, ojú ìwé 30

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 308-309

1 Kọ́ríńtì 13:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 4:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1992, ojú ìwé 30-31

1 Kọ́ríńtì 13:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/15/1992, ojú ìwé 30-31

1 Kọ́ríńtì 13:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    10/2011, ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2007, ojú ìwé 22

    8/1/1992, ojú ìwé 9-11

    7/15/1992, ojú ìwé 31

1 Kọ́ríńtì 13:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bàìbàì.”

  • *

    Tàbí “tó kún rẹ́rẹ́.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2015, ojú ìwé 15

    3/15/2000, ojú ìwé 12

    7/15/1992, ojú ìwé 31

1 Kọ́ríńtì 13:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 22:37; Ro 13:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2016, ojú ìwé 30

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 27

    7/15/1992, ojú ìwé 31

    9/15/1991, ojú ìwé 19

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 28-29

Àwọn míì

1 Kọ́r. 13:21Kọ 12:8
1 Kọ́r. 13:21Jo 4:20
1 Kọ́r. 13:3Mt 6:2
1 Kọ́r. 13:32Kọ 9:7
1 Kọ́r. 13:41Jo 4:8
1 Kọ́r. 13:41Tẹ 5:14
1 Kọ́r. 13:4Ro 13:10; Ef 4:32
1 Kọ́r. 13:4Ga 5:26
1 Kọ́r. 13:41Pe 5:5
1 Kọ́r. 13:5Ro 13:13; 1Kọ 14:40
1 Kọ́r. 13:51Kọ 10:24; Flp 2:4
1 Kọ́r. 13:5Mt 5:39; Jem 1:19
1 Kọ́r. 13:5Ef 4:32; Kol 3:13
1 Kọ́r. 13:6Ro 12:9
1 Kọ́r. 13:71Pe 4:8
1 Kọ́r. 13:7Iṣe 17:11
1 Kọ́r. 13:7Ro 8:25; 12:12
1 Kọ́r. 13:71Tẹ 1:3
1 Kọ́r. 13:9Owe 4:18
1 Kọ́r. 13:13Mt 22:37; Ro 13:10
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Kọ́ríńtì 13:1-13

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

13 Tí mo bá ń fi èdè* èèyàn àti ti àwọn áńgẹ́lì sọ̀rọ̀ àmọ́ tí mi ò ní ìfẹ́, mo ti di abala idẹ tó ń dún tàbí síńbálì* olóhùn gooro. 2 Tí mo bá sì ní ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀, tí mo lóye gbogbo àṣírí mímọ́ àti gbogbo ìmọ̀,+ tí mo ní gbogbo ìgbàgbọ́ láti ṣí àwọn òkè nípò pa dà,* àmọ́ tí mi ò ní ìfẹ́, mi ò já mọ́ nǹkan kan.*+ 3 Tí mo bá yọ̀ǹda gbogbo nǹkan tí mo ní láti bọ́ àwọn ẹlòmíì,+ tí mo sì fi ara mi lélẹ̀ kí n lè máa yangàn, àmọ́ tí mi ò ní ìfẹ́,+ kò ṣe mí láǹfààní kankan.

4 Ìfẹ́+ máa ń ní sùúrù*+ àti inú rere.+ Ìfẹ́ kì í jowú,+ kì í fọ́nnu, kì í gbéra ga,+ 5 kì í hùwà tí kò bójú mu,*+ kì í wá ire tirẹ̀ nìkan,+ kì í tètè bínú.+ Kì í di èèyàn sínú.*+ 6 Kì í yọ̀ lórí àìṣòdodo,+ àmọ́ ó máa ń yọ̀ lórí òtítọ́. 7 Ó máa ń mú ohun gbogbo mọ́ra,+ ó máa ń gba ohun gbogbo gbọ́,+ ó máa ń retí ohun gbogbo,+ ó máa ń fara da ohun gbogbo.+

8 Ìfẹ́ kì í yẹ̀ láé. Àmọ́ tí ẹ̀bùn ìsọtẹ́lẹ̀ bá wà, yóò dópin; tí àwọn ahọ́n àjèjì bá wà,* wọ́n á ṣíwọ́; tí ìmọ̀ bá wà, yóò dópin. 9 Nítorí a ní ìmọ̀ dé àyè kan,+ a sì ń sọ tẹ́lẹ̀ dé àyè kan, 10 àmọ́ nígbà tí èyí tó pé bá dé, èyí tó dé àyè kan yóò dópin. 11 Nígbà tí mo wà lọ́mọdé, mo máa ń sọ̀rọ̀ bí ọmọdé, mò ń ronú bí ọmọdé, mo sì ń gbèrò bí ọmọdé; àmọ́ ní báyìí tí mo ti di ọkùnrin, mo ti fòpin sí àwọn ìwà ọmọdé. 12 Ní báyìí à ń ríran fírífírí* nínú dígí onírin, àmọ́ nígbà yẹn yóò jẹ́ kedere ní ojúkojú. Lọ́wọ́lọ́wọ́ báyìí, mo ní ìmọ̀ dé àyè kan, àmọ́ nígbà yẹn màá ní ìmọ̀ tó péye,* bí Ọlọ́run ṣe mọ̀ mí lọ́nà tó péye. 13 Tóò, àwọn mẹ́ta tó ṣì wà nìyí: ìgbàgbọ́, ìrètí àti ìfẹ́; àmọ́ èyí tó tóbi jù lọ nínú wọn ni ìfẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́