ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Tímótì 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tímótì

      • Ìkíni (1, 2)

      • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run torí ìgbàgbọ́ Tímótì (3-5)

      • Jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run máa jó bí iná (6-11)

      • Máa tẹ̀ lé àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní (12-14)

      • Àwọn ọ̀tá Pọ́ọ̀lù àtàwọn ọ̀rẹ́ rẹ̀ (15-18)

2 Tímótì 1:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 3:16; 6:40, 44; 1Pe 1:3, 4

2 Tímótì 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 4:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2020, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2003, ojú ìwé 28

2 Tímótì 1:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2015, ojú ìwé 15

2 Tímótì 1:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 4:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2015, ojú ìwé 14

    7/1/1999, ojú ìwé 9

    5/15/1998, ojú ìwé 8-9

2 Tímótì 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 4:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2020, ojú ìwé 28-29

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, ojú ìwé 116

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1998, ojú ìwé 26

    Jí!,

    3/22/1998, ojú ìwé 21

2 Tímótì 1:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:15; 1Tẹ 2:2
  • +Lk 24:49; Iṣe 1:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àlàyé Àwọn Ẹsẹ Bíbélì, àpilẹ̀kọ 24

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 47

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2013, ojú ìwé 23-24

    5/15/2009, ojú ìwé 15

    10/1/2006, ojú ìwé 22

2 Tímótì 1:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 1:16
  • +Kol 1:24; 2Ti 2:3
  • +Flp 4:13; Kol 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2003, ojú ìwé 9

2 Tímótì 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 1:4; Heb 3:1
  • +Ef 2:5, 8; Tit 3:5

2 Tímótì 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 1:14; Heb 2:9
  • +1Kọ 15:54; Heb 2:14
  • +Ro 1:16
  • +Jo 5:24; 1Jo 1:2
  • +1Pe 1:3, 4

2 Tímótì 1:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 9:15; 1Ti 2:7

2 Tímótì 1:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 9:16; Ef 3:1
  • +2Kọ 4:2
  • +2Ti 4:8

2 Tímótì 1:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àpẹẹrẹ.”

  • *

    Tàbí “tó ṣeni lóore; tó wúlò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 6:3, 4; Tit 1:7, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 31

    8/15/2008, ojú ìwé 24

    3/15/2006, ojú ìwé 31

    1/1/2003, ojú ìwé 29

    9/15/2002, ojú ìwé 16-17

    1/15/1996, ojú ìwé 12

2 Tímótì 1:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 8:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2020, ojú ìwé 29

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 14

2 Tímótì 1:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 19:10

2 Tímótì 1:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 4:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2004, ojú ìwé 20

    11/15/1997, ojú ìwé 29-30

2 Tímótì 1:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 29-30

2 Tímótì 1:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/1997, ojú ìwé 30-31

Àwọn míì

2 Tím. 1:1Jo 3:16; 6:40, 44; 1Pe 1:3, 4
2 Tím. 1:21Kọ 4:17
2 Tím. 1:51Ti 4:6
2 Tím. 1:61Ti 4:14
2 Tím. 1:7Ro 8:15; 1Tẹ 2:2
2 Tím. 1:7Lk 24:49; Iṣe 1:8
2 Tím. 1:8Ro 1:16
2 Tím. 1:8Kol 1:24; 2Ti 2:3
2 Tím. 1:8Flp 4:13; Kol 1:11
2 Tím. 1:9Ef 2:5, 8; Tit 3:5
2 Tím. 1:9Ef 1:4; Heb 3:1
2 Tím. 1:10Jo 1:14; Heb 2:9
2 Tím. 1:101Kọ 15:54; Heb 2:14
2 Tím. 1:10Ro 1:16
2 Tím. 1:10Jo 5:24; 1Jo 1:2
2 Tím. 1:101Pe 1:3, 4
2 Tím. 1:11Iṣe 9:15; 1Ti 2:7
2 Tím. 1:12Iṣe 9:16; Ef 3:1
2 Tím. 1:122Kọ 4:2
2 Tím. 1:122Ti 4:8
2 Tím. 1:131Ti 6:3, 4; Tit 1:7, 9
2 Tím. 1:14Ro 8:11
2 Tím. 1:15Iṣe 19:10
2 Tím. 1:162Ti 4:19
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Tímótì 1:1-18

Ìwé Kejì sí Tímótì

1 Pọ́ọ̀lù, àpọ́sítélì Kristi Jésù nípasẹ̀ ìfẹ́ Ọlọ́run, èyí tó bá ìlérí ìyè tí a rí gbà nípasẹ̀ Kristi Jésù mu,+ 2 sí Tímótì, ọmọ tí mo nífẹ̀ẹ́:+

Kí o ní inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, àánú àti àlàáfíà látọ̀dọ̀ Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti látọ̀dọ̀ Kristi Jésù Olúwa wa.

3 Mo dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ẹni tí mò ń fi ẹ̀rí ọkàn tó mọ́ ṣe iṣẹ́ ìsìn mímọ́ fún bí àwọn baba ńlá mi ti ṣe, mi ò sì yéé rántí rẹ nínú àwọn ìrawọ́ ẹ̀bẹ̀ mi tọ̀sántòru. 4 Bí mo ṣe ń rántí omijé rẹ, àárò rẹ ń sọ mí, kí inú mi lè dùn gidigidi. 5 Torí mo rántí ìgbàgbọ́ rẹ tí kò ní ẹ̀tàn,+ èyí tí ìyá rẹ àgbà Lọ́ìsì àti ìyá rẹ Yùníìsì kọ́kọ́ ní, ó sì dá mi lójú pé irú ìgbàgbọ́ yìí ni ìwọ náà ní.

6 Torí èyí ni mo ṣe rán ọ létí pé kí o jẹ́ kí ẹ̀bùn Ọlọ́run tó wà nínú rẹ nígbà tí mo gbé ọwọ́ lé+ ọ máa jó bí iná. 7 Nítorí Ọlọ́run kò fún wa ní ẹ̀mí ojo,+ àmọ́ ó fún wa ní ẹ̀mí agbára+ àti ti ìfẹ́ àti ti àròjinlẹ̀. 8 Torí náà, má ṣe tijú láti jẹ́rìí nípa Olúwa wa+ tàbí èmi, ẹlẹ́wọ̀n nítorí rẹ̀, àmọ́ kí ìwọ náà jìyà torí ìhìn rere,+ kí o sì gbára lé agbára Ọlọ́run.+ 9 Ó gbà wá, ó sì fi ìpè mímọ́ pè wá,+ kì í ṣe torí àwọn iṣẹ́ wa, àmọ́ torí ohun tó fẹ́ ṣe àti inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí rẹ̀.+ Ọjọ́ pẹ́ tí a ti fún wa ní èyí nípasẹ̀ Kristi Jésù, 10 àmọ́ nísinsìnyí ìfarahàn Olùgbàlà wa, Kristi Jésù,+ ti mú kó ṣe kedere, ẹni tó mú ikú kúrò,+ tó sì tipasẹ̀ ìhìn rere+ tan ìmọ́lẹ̀ sí ìyè+ àti àìdíbàjẹ́.+ 11 Torí rẹ̀ ni a ṣe yàn mí láti di oníwàásù, àpọ́sítélì àti olùkọ́.+

12 Ìdí tí èmi náà ṣe ń jìyà àwọn nǹkan yìí nìyẹn,+ àmọ́ ojú ò tì mí.+ Torí mo mọ Ẹni tí mo gbà gbọ́, ó sì dá mi lójú pé ó lè dáàbò bo ohun tí mo fi sí ìkáwọ́ rẹ̀ títí di ọjọ́ náà.+ 13 Máa tẹ̀ lé ìlànà* àwọn ọ̀rọ̀ tó ṣàǹfààní*+ tí o gbọ́ lọ́dọ̀ mi pẹ̀lú ìgbàgbọ́ àti ìfẹ́ tó ń wá látinú àjọṣe tí a ní pẹ̀lú Kristi Jésù. 14 Máa fi ẹ̀mí mímọ́ tó ń gbé inú wa+ ṣọ́ ohun rere tí a fi síkàáwọ́ rẹ.

15 O mọ̀ pé gbogbo èèyàn ní ìpínlẹ̀ Éṣíà+ ti pa mí tì, títí kan Fíjẹ́lọ́sì àti Hẹmojẹ́nísì. 16 Kí Olúwa fi àánú hàn sí ìdílé Ónẹ́sífórù,+ torí pé ó máa ń mú kí ara tù mí lọ́pọ̀ ìgbà, kò sì tijú pé wọ́n fi ẹ̀wọ̀n dè mí. 17 Kàkà bẹ́ẹ̀, nígbà tó wà ní Róòmù, ó fara balẹ̀ wá mi, ó sì rí mi. 18 Kí Olúwa jẹ́ kó rí àánú gbà látọ̀dọ̀ Jèhófà* ní ọjọ́ yẹn. Gbogbo iṣẹ́ ìsìn tó ṣe ní Éfésù lo mọ̀ dáadáa.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́