ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì (1-22)

        • Ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé! (6)

        • Àwọn ará Mídíà máa ṣẹ́gun Bábílónì (17)

        • Wọn ò ní gbé inú Bábílónì mọ́ láé (20)

Àìsáyà 13:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 25:12; 50:1-3; Ifi 18:2
  • +Ais 1:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 172-173

Àìsáyà 13:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òpó kan láti fi ṣe àmì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:12, 27, 28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 172-173

Àìsáyà 13:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “tí mo sọ di mímọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 45:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 173-174

Àìsáyà 13:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 5:28
  • +Jer 50:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 173-174

Àìsáyà 13:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:9; 51:28
  • +Jer 51:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 173-174

Àìsáyà 13:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 13:18; Jer 50:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 174

Àìsáyà 13:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:43

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 174-175

Àìsáyà 13:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Da 5:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 174-175

Àìsáyà 13:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:23, 29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 175

Àìsáyà 13:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àti àwọn Késílì wọn,” ó ṣeé ṣe kó jẹ́ Óríónì àtàwọn àgbájọ ìràwọ̀ tó yí i ká ló ń tọ́ka sí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 9:9; 38:31; Emọ 5:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 109-110

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 175

Àìsáyà 13:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 137:8; Jer 51:37; Ifi 18:2
  • +Jer 50:29; Da 5:22, 23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 175-176

Àìsáyà 13:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:30; 51:3, 4
  • +1Ọb 10:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176

Àìsáyà 13:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:29

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176

Àìsáyà 13:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176

Àìsáyà 13:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:3, 4

Àìsáyà 13:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 137:8, 9

Àìsáyà 13:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 21:2; Jer 50:9; 51:11; Da 5:30, 31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 6/2017,

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2006, ojú ìwé 10-11

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176-180

Àìsáyà 13:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 6/2017,

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176-178, 179-180

Àìsáyà 13:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “lọ́ṣọ̀ọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 47:5; Da 4:30
  • +Ais 47:1
  • +Jẹ 19:24, 25; Jer 50:40

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 14-15

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 176-178

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 27-28

Àìsáyà 13:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:3, 13; 51:29, 37; Ifi 18:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 180-181

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/1998, ojú ìwé 19-20

    Ìwé fún Gbogbo Ènìyàn, ojú ìwé 29

Àìsáyà 13:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Àwọn ẹ̀mí èṣù tó rí bí ewúrẹ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 18:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 261

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 180-181

Àìsáyà 13:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “akátá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 51:33

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 180-181

Àwọn míì

Àìsá. 13:1Jer 25:12; 50:1-3; Ifi 18:2
Àìsá. 13:1Ais 1:1
Àìsá. 13:2Jer 51:12, 27, 28
Àìsá. 13:3Ais 45:1
Àìsá. 13:4Da 5:28
Àìsá. 13:4Jer 50:15
Àìsá. 13:5Jer 50:9; 51:28
Àìsá. 13:5Jer 51:11
Àìsá. 13:6Ais 13:18; Jer 50:13
Àìsá. 13:7Jer 50:43
Àìsá. 13:8Da 5:6
Àìsá. 13:9Jer 50:23, 29
Àìsá. 13:10Job 9:9; 38:31; Emọ 5:8
Àìsá. 13:11Sm 137:8; Jer 51:37; Ifi 18:2
Àìsá. 13:11Jer 50:29; Da 5:22, 23
Àìsá. 13:12Jer 50:30; 51:3, 4
Àìsá. 13:121Ọb 10:11
Àìsá. 13:13Jer 51:29
Àìsá. 13:14Jer 50:16
Àìsá. 13:15Jer 51:3, 4
Àìsá. 13:16Sm 137:8, 9
Àìsá. 13:17Ais 21:2; Jer 50:9; 51:11; Da 5:30, 31
Àìsá. 13:18Jer 50:14
Àìsá. 13:19Ais 47:5; Da 4:30
Àìsá. 13:19Ais 47:1
Àìsá. 13:19Jẹ 19:24, 25; Jer 50:40
Àìsá. 13:20Jer 50:3, 13; 51:29, 37; Ifi 18:21
Àìsá. 13:21Ifi 18:2
Àìsá. 13:22Jer 51:33
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 13:1-22

Àìsáyà

13 Ọ̀rọ̀ ìkéde sí Bábílónì,+ tí Àìsáyà+ ọmọ Émọ́ọ̀sì rí nínú ìran:

 2 “Ẹ gbé àmì kan*+ sókè lórí òkè tó jẹ́ kìkì àpáta.

Ẹ ké pè wọ́n, ẹ ju ọwọ́,

Kí wọ́n lè wá sí ẹnu ọ̀nà àwọn èèyàn pàtàkì.

 3 Mo ti pàṣẹ fún àwọn tí mo yàn.*+

Mo ti ké sí àwọn jagunjagun mi pé kí wọ́n fi ìbínú mi hàn,

Àwọn èèyàn mi tó ń yangàn, tí wọ́n sì ń yọ̀.

 4 Fetí sílẹ̀! Ọ̀pọ̀ èèyàn wà lórí òkè;

Ìró wọn dà bí ìró ọ̀pọ̀ rẹpẹtẹ èèyàn!

Fetí sílẹ̀! Ariwo àwọn ìjọba,

Ti àwọn orílẹ̀-èdè tó kóra jọ!+

Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ń pe àwọn ọmọ ogun jọ.+

 5 Wọ́n ń bọ̀ láti ilẹ̀ tó jìnnà,+

Láti ìkángun ọ̀run,

Jèhófà àti àwọn ohun ìjà ìbínú rẹ̀,

Láti pa gbogbo ayé run.+

 6 Ẹ pohùn réré ẹkún, torí ọjọ́ Jèhófà sún mọ́lé!

Ó máa jẹ́ ọjọ́ ìparun látọ̀dọ̀ Olódùmarè.+

 7 Ìdí nìyẹn tí gbogbo ọwọ́ fi máa rọ,

Tí ìbẹ̀rù sì máa mú kí ọkàn gbogbo èèyàn domi.+

 8 Jìnnìjìnnì bo àwọn èèyàn náà.+

Iṣan wọn sún kì, wọ́n sì ń jẹ̀rora,

Bí obìnrin tó ń rọbí.

Wọ́n ń wo ara wọn tìbẹ̀rù-tìbẹ̀rù,

Ìrora sì hàn lójú wọn.

 9 Wò ó! Ọjọ́ Jèhófà ń bọ̀,

Ọjọ́ tó lágbára pẹ̀lú ìbínú tó le àti ìbínú tó ń jó fòfò,

Láti sọ ilẹ̀ náà di ohun àríbẹ̀rù,+

Kó sì pa àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ ilẹ̀ náà run kúrò lórí rẹ̀.

10 Torí àwọn ìràwọ̀ ojú ọ̀run àti àwọn àgbájọ ìràwọ̀ wọn*+

Kò ní tan ìmọ́lẹ̀ wọn jáde;

Oòrùn máa ṣókùnkùn tó bá ràn,

Òṣùpá ò sì ní tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀.

11 Màá pe àwọn tó ń gbé ayé lẹ́jọ́ torí ìwà burúkú wọn,+

Màá sì pe àwọn ẹni burúkú lẹ́jọ́ torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn.

Màá fòpin sí ìyangàn àwọn agbéraga,

Màá sì rẹ ìgbéraga àwọn oníwà ìkà wálẹ̀.+

12 Màá mú kí ẹni kíkú ṣọ̀wọ́n ju wúrà tí wọ́n yọ́ mọ́,+

Màá sì mú kí àwọn èèyàn ṣọ̀wọ́n ju wúrà Ófírì.+

13 Ìdí nìyẹn tí màá fi mú kí ọ̀run gbọ̀n rìrì,

Ayé sì máa mì jìgìjìgì kúrò ní àyè rẹ̀+

Nígbà tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun bá bínú gidigidi ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀ tó ń jó bí iná.

14 Bí egbin tí wọ́n ń dọdẹ àti bí agbo ẹran tí kò sí ẹnikẹ́ni tó máa kó wọn jọ,

Kálukú máa pa dà sọ́dọ̀ àwọn èèyàn rẹ̀;

Kálukú sì máa sá lọ sí ilẹ̀ rẹ̀.+

15 Wọ́n máa gún ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá rí ní àgúnyọ,

Wọ́n sì máa fi idà pa ẹnikẹ́ni tí wọ́n bá mú.+

16 Wọ́n máa já àwọn ọmọ wọn sí wẹ́wẹ́ níṣojú wọn,+

Wọ́n máa kó ẹrù ilé wọn,

Wọ́n sì máa fipá bá àwọn ìyàwó wọn lò pọ̀.

17 Màá gbé àwọn ará Mídíà dìde sí wọn,+

Àwọn tí kò ka fàdákà sí nǹkan kan,

Tí wúrà ò sì já mọ́ nǹkan kan lójú wọn.

18 Ọfà wọn máa run àwọn ọ̀dọ́kùnrin túútúú;+

Wọn ò ní káàánú èso ikùn,

Wọn ò sì ní ṣàánú àwọn ọmọdé.

19 Bábílónì tó lógo* jù nínú àwọn ìjọba,+

Ẹwà àti ògo àwọn ará Kálídíà,+

Máa dà bíi Sódómù àti Gòmórà nígbà tí Ọlọ́run bì wọ́n ṣubú.+

20 Ẹnikẹ́ni ò ní gbé inú rẹ̀ mọ́ láé,

Kò sì sẹ́ni tó máa gbé ibẹ̀ láti ìran dé ìran.+

Ará Arébíà kankan ò ní pàgọ́ síbẹ̀,

Olùṣọ́ àgùntàn kankan ò sì ní jẹ́ kí agbo ẹran rẹ̀ sinmi níbẹ̀.

21 Àwọn ẹranko inú aṣálẹ̀ máa dùbúlẹ̀ síbẹ̀;

Àwọn ẹyẹ òwìwí máa kún ilé wọn.

Àwọn ògòǹgò á máa gbé ibẹ̀,+

Àwọn ewúrẹ́ igbó* á máa tọ kiri níbẹ̀.

22 Àwọn ẹranko tó ń hu á máa ké nínú àwọn ilé gogoro rẹ̀

Àti àwọn ajáko* nínú àwọn ààfin rẹ̀ tó lọ́lá.

Àkókò rẹ̀ ti sún mọ́lé, a ò sì ní fi kún àwọn ọjọ́ rẹ̀.”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́