ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 28
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Ó mà ṣe fún àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù o! (1-6)

      • Àwọn àlùfáà àti wòlíì Júdà ń ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́ (7-13)

      • Wọ́n “bá Ikú dá májẹ̀mú” (14-22)

        • Òkúta igun tó ṣeyebíye ní Síónì (16)

        • Iṣẹ́ Jèhófà tó ṣàjèjì (21)

      • Bí Jèhófà ṣe ń fi ọgbọ́n báni wí (23-29)

Àìsáyà 28:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó jọ pé Samáríà tó jẹ́ olú ìlú ló ń sọ.

  • *

    Tàbí “ìyangàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 7:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 287-288

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 11

Àìsáyà 28:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2011, ojú ìwé 3

    6/1/1991, ojú ìwé 11-12

Àìsáyà 28:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìyangàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 17:6; Ais 17:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 287-288

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 12

Àìsáyà 28:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 288

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/15/1993, ojú ìwé 4-5

    6/1/1991, ojú ìwé 12

Àìsáyà 28:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 288

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 24-25

Àìsáyà 28:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 18:34; 68:35

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 24-25

Àìsáyà 28:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 16:10, 11; Jer 5:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 289-291, 300-301

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 12-13

Àìsáyà 28:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 289-291

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 12-13

Àìsáyà 28:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 291-292

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 13-14

Àìsáyà 28:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Okùn ìdíwọ̀n lé okùn ìdíwọ̀n, okùn ìdíwọ̀n lé okùn ìdíwọ̀n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:13; Ais 28:17; Ida 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 291-292

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 13-14

Àìsáyà 28:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “àwọn tí ètè wọn ń kólòlò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:49, 50; Jer 5:15; 1Kọ 14:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 291-292

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 14

Àìsáyà 28:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 81:10, 11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 14-15

Àìsáyà 28:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Okùn ìdíwọ̀n lé okùn ìdíwọ̀n, okùn ìdíwọ̀n lé okùn ìdíwọ̀n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:17
  • +2Kr 36:15, 16; Ais 8:14, 15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 291-292

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 14-15

Àìsáyà 28:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “A sì ti fìdí ìran kan múlẹ̀ pẹ̀lú Isà Òkú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:18
  • +Ais 30:9, 10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2003, ojú ìwé 13-14

    6/1/1991, ojú ìwé 16-17

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 293

Àìsáyà 28:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 118:22
  • +Mt 21:42; Mk 12:10; Lk 20:17; Iṣe 4:11
  • +Ef 2:19, 20
  • +Ro 9:33; 10:11; 1Pe 2:4, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 293-294

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 17

    Yiyan, ojú ìwé 50, 55

Àìsáyà 28:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “okùn tí a fi ń mọ̀ bóyá nǹkan gún régé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ọb 21:13
  • +Jer 11:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 11/2022,

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2011, ojú ìwé 3, 6-7

    6/1/1991, ojú ìwé 19, 25

Àìsáyà 28:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ṣìọ́ọ̀lù,” ìyẹn ibojì aráyé. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 294

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 19

Àìsáyà 28:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Tó bá ti yé wọn, ìbẹ̀rù máa bò wọ́n.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 24:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 294

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 19

Àìsáyà 28:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 294-295

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 21

Àìsáyà 28:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “pẹ̀tẹ́lẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joṣ 10:8-14; 2Sa 5:20; 1Kr 14:10-16
  • +Ida 2:15; Hab 1:5-7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 295

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 20-25

Àìsáyà 28:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbogbo ayé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 36:15, 16; Jer 20:7
  • +Ais 10:23; 24:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 295-296, 300-301

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1991, ojú ìwé 23

Àìsáyà 28:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 30:5; 103:9; Mik 7:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2001, ojú ìwé 11

Àìsáyà 28:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “wíìtì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 9:31, 32; Isk 4:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2001, ojú ìwé 11

Àìsáyà 28:26

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “bá a wí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 119:71

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 296, 301

Àìsáyà 28:27

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 41:15; Emọ 1:3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 296, 301

Àìsáyà 28:28

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 103:9; Ais 21:10; Mik 7:18
  • +Le 26:44; Jer 10:24

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 296, 301

Àìsáyà 28:29

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ète.”

  • *

    Tàbí “Tí ọgbọ́n rẹ̀ tó gbéṣẹ́ sì ga lọ́lá.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 40:5; Jer 32:19; Ro 11:33

Àwọn míì

Àìsá. 28:1Ais 7:2
Àìsá. 28:32Ọb 17:6; Ais 17:3
Àìsá. 28:5Ais 11:16
Àìsá. 28:6Sm 18:34; 68:35
Àìsá. 28:72Ọb 16:10, 11; Jer 5:31
Àìsá. 28:102Ọb 21:13; Ais 28:17; Ida 2:8
Àìsá. 28:11Di 28:49, 50; Jer 5:15; 1Kọ 14:21
Àìsá. 28:12Sm 81:10, 11
Àìsá. 28:13Ais 28:17
Àìsá. 28:132Kr 36:15, 16; Ais 8:14, 15
Àìsá. 28:15Ais 28:18
Àìsá. 28:15Ais 30:9, 10
Àìsá. 28:16Sm 118:22
Àìsá. 28:16Mt 21:42; Mk 12:10; Lk 20:17; Iṣe 4:11
Àìsá. 28:16Ef 2:19, 20
Àìsá. 28:16Ro 9:33; 10:11; 1Pe 2:4, 6
Àìsá. 28:172Ọb 21:13
Àìsá. 28:17Jer 11:20
Àìsá. 28:18Ais 28:15
Àìsá. 28:19Ais 24:1
Àìsá. 28:21Joṣ 10:8-14; 2Sa 5:20; 1Kr 14:10-16
Àìsá. 28:21Ida 2:15; Hab 1:5-7
Àìsá. 28:222Kr 36:15, 16; Jer 20:7
Àìsá. 28:22Ais 10:23; 24:1
Àìsá. 28:24Sm 30:5; 103:9; Mik 7:18
Àìsá. 28:25Ẹk 9:31, 32; Isk 4:9
Àìsá. 28:26Sm 119:71
Àìsá. 28:27Ais 41:15; Emọ 1:3
Àìsá. 28:28Sm 103:9; Ais 21:10; Mik 7:18
Àìsá. 28:28Le 26:44; Jer 10:24
Àìsá. 28:29Sm 40:5; Jer 32:19; Ro 11:33
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
  • 28
  • 29
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 28:1-29

Àìsáyà

28 Adé* ìgbéraga* àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù+ gbé

Àti ìtànná ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,

Tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá tó jẹ́ ti àwọn tí wáìnì ti kápá wọn!

 2 Wò ó! Jèhófà ní ẹnì kan tó lókun tó sì lágbára.

Bí ìjì yìnyín tó ń sán ààrá, ìjì apanirun,

Bí ìjì tó ń sán ààrá tó ń fa àkúnya omi tó bùáyà,

Ó máa fipá jù ú sílẹ̀.

 3 Wọ́n máa fi ẹsẹ̀ tẹ

Àwọn adé ìgbéraga* ti àwọn ọ̀mùtípara Éfúrémù mọ́lẹ̀.+

 4 Òdòdó ẹwà ológo rẹ̀ tó ti ń rọ,

Èyí tó wà ní orí àfonífojì ọlọ́ràá,

Máa dà bí àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́ ṣáájú ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn.

Tí ẹnì kan bá rí i, ṣe ló máa gbé e mì ní gbàrà tó bá ti wà lọ́wọ́ rẹ̀.

5 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun máa di adé ológo àti òdòdó ẹ̀yẹ fún àwọn èèyàn rẹ̀ tó ṣẹ́ kù.+ 6 Ó máa di ẹ̀mí ìdájọ́ òdodo fún ẹni tó jókòó láti ṣe ìdájọ́, ó sì máa jẹ́ orísun agbára fún àwọn tó ń lé ogun sẹ́yìn ní ẹnubodè.+

 7 Àwọn yìí náà ṣìnà torí wáìnì;

Ohun mímu wọn tó ní ọtí ń mú kí wọ́n ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́,

Àlùfáà àti wòlíì ti ṣìnà torí ọtí;

Wáìnì ò jẹ́ kí wọ́n mọ nǹkan tí wọ́n ń ṣe,

Ọtí wọn sì ń jẹ́ kí wọ́n ta gọ̀ọ́gọ̀ọ́;

Ìran wọn ń mú kí wọ́n ṣìnà,

Wọ́n sì ń kọsẹ̀ nínú ìdájọ́.+

 8 Torí pé èébì ẹlẹ́gbin kún àwọn tábìlì wọn,

Kò sí ibi tí kò sí.

 9 Ta ni èèyàn máa fún ní ìmọ̀,

Ta sì ni èèyàn máa ṣàlàyé ọ̀rọ̀ fún?

Ṣé àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ gba wàrà lẹ́nu wọn ni,

Àwọn tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ já lẹ́nu ọmú?

10 Torí ó jẹ́ “àṣẹ kan tẹ̀ lé òmíràn, àṣẹ kan tẹ̀ lé òmíràn,

Okùn tẹ̀ lé okùn, okùn tẹ̀ lé okùn,*+

Díẹ̀ níbí, díẹ̀ lọ́hùn-ún.”

11 Torí náà, ó máa bá àwọn èèyàn yìí sọ̀rọ̀ nípasẹ̀ àwọn tó ń kólòlò* tí wọ́n sì ń sọ èdè àjèjì.+ 12 Ó ti sọ fún wọn rí pé: “Ibi ìsinmi nìyí. Ẹ jẹ́ kí ẹni tó ti rẹ̀ sinmi; ibi ìtura nìyí,” àmọ́ wọn ò fetí sílẹ̀.+ 13 Torí náà, ohun tí ọ̀rọ̀ Jèhófà máa jẹ́ fún wọn ni pé:

“Àṣẹ kan tẹ̀ lé òmíràn, àṣẹ kan tẹ̀ lé òmíràn,

Okùn tẹ̀ lé okùn, okùn tẹ̀ lé okùn,*+

Díẹ̀ níbí, díẹ̀ lọ́hùn-ún,”

Kí wọ́n lè kọsẹ̀, kí wọ́n sì ṣubú sẹ́yìn

Tí wọ́n bá ń rìn,

Kí wọ́n lè ṣèṣe, kí wọ́n lè dẹkùn mú wọn, kí ọwọ́ sì tẹ̀ wọ́n.+

14 Torí náà, ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà, ẹ̀yin afọ́nnu,

Ẹ̀yin alákòóso àwọn èèyàn yìí ní Jerúsálẹ́mù,

15 Nítorí ẹ sọ pé:

“A ti bá Ikú dá májẹ̀mú,+

A sì ti bá Isà Òkú* ṣe àdéhùn.*

Tí omi tó ń ru gùdù bá ya kọjá lójijì,

Kò ní dé ọ̀dọ̀ wa,

Torí a ti fi irọ́ ṣe ibi ààbò wa,

A sì ti fi ara wa pa mọ́ sínú èké.”+

16 Torí náà, ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí:

“Wò ó, màá fi òkúta+ tí a ti dán wò ṣe ìpìlẹ̀ ní Síónì,

Òkúta igun ilé+ tó ṣeyebíye, ti ìpìlẹ̀ tó dájú.+

Ẹnikẹ́ni tó bá ní ìgbàgbọ́ kò ní bẹ̀rù.+

17 Màá fi ìdájọ́ òdodo ṣe okùn ìdíwọ̀n,+

Màá sì fi òdodo ṣe irinṣẹ́ tí a fi ń mú nǹkan tẹ́jú.*+

Yìnyín máa gbá ibi ààbò irọ́ lọ,

Omi sì máa kún bo ibi ìfarapamọ́.

18 Májẹ̀mú tí ẹ bá Ikú dá ò ní fìdí múlẹ̀ mọ́,

Àdéhùn tí ẹ sì bá Isà Òkú* ṣe ò ní lẹ́sẹ̀ nílẹ̀.+

Tí omi tó ń ru gùdù bá ya kọjá lójijì,

Ó máa pa yín rẹ́.

19 Ní gbogbo ìgbà tó bá ti ń kọjá,

Ó máa gbá yín lọ;+

Torí á máa kọjá ní àràárọ̀,

Ní ọ̀sán àti ní òru.

Ìbẹ̀rù nìkan ló máa jẹ́ kí ohun tí wọ́n gbọ́ yé wọn.”*

20 Torí pé ibùsùn ti kéré jù láti na ara,

Aṣọ tí wọ́n hun sì ti tẹ́ẹ́rẹ́ jù láti fi bora.

21 Torí Jèhófà máa dìde bó ṣe ṣe ní Òkè Pérásímù;

Ó máa gbéra sọ bó ṣe ṣe ní àfonífojì* tó wà nítòsí Gíbíónì,+

Kó lè ṣe ìṣe rẹ̀, ìṣe rẹ̀ tó ṣàjèjì,

Kó sì lè ṣe iṣẹ́ rẹ̀, iṣẹ́ rẹ̀ tó ṣàrà ọ̀tọ̀.+

22 Ní báyìí, ẹ má fini ṣe yẹ̀yẹ́,+

Ká má bàa tún mú kí àwọn ìdè yín le sí i,

Torí mo ti gbọ́ látọ̀dọ̀ Olúwa Ọba Aláṣẹ, Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun

Pé a ti pinnu láti pa gbogbo ilẹ̀ náà* run.+

23 Ẹ gbọ́, kí ẹ sì fetí sí ohùn mi;

Ẹ fiyè sílẹ̀, kí ẹ sì fetí sí ọ̀rọ̀ mi.

24 Ṣé ẹni tó ń túlẹ̀ máa ń fi gbogbo ọjọ́ túlẹ̀ kó tó fúnrúgbìn ni?

Ṣé á máa túlẹ̀, tí á sì máa fọ́ ilẹ̀ rẹ̀ sí wẹ́wẹ́ láìdáwọ́ dúró ni?+

25 Tó bá ti mú kí ilẹ̀ náà tẹ́jú,

Ṣebí ó máa fọ́n kúmínì dúdú, kó sì gbin kúmínì,

Ṣebí ó sì máa gbin àlìkámà,* jéró àti ọkà bálì sí àyè wọn

Àti ọkà sípẹ́ẹ̀tì+ sí eteetí ilẹ̀?

26 Torí Ó ń kọ́ ọ* ní ọ̀nà tó tọ́;

Ọlọ́run rẹ̀ ń fún un ní ìtọ́ni.+

27 Torí a kì í fi ohun tí wọ́n fi ń pakà fọ́ kúmínì dúdú,+

A kì í sì í yí àgbá kẹ̀kẹ́ lórí kúmínì.

Kàkà bẹ́ẹ̀, ọ̀pá la fi ń lu kúmínì dúdú,

Igi la sì fi ń lu kúmínì.

28 Ṣé èèyàn máa ń fọ́ ọkà kó lè fi ṣe búrẹ́dì ni?

Rárá, kì í pa ọkà náà láìdáwọ́ dúró;+

Nígbà tó bá sì fi àwọn ẹṣin rẹ̀ fa àgbá kẹ̀kẹ́ rẹ̀ lórí rẹ̀,

Kò ní fọ́ ọ.+

29 Ọ̀dọ̀ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni èyí náà ti wá,

Ẹni tí ìmọ̀ràn* rẹ̀ jẹ́ àgbàyanu,

Tó sì gbé àwọn ohun ńlá ṣe.*+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́