ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Oníwàásù 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Oníwàásù

      • Ohun gbogbo ni àkókò wà fún (1-8)

      • Ká gbádùn ayé, ẹ̀bùn Ọlọ́run ni (9-15)

        • Ayérayé wà ní ọkàn èèyàn (11)

      • Òdodo ni Ọlọ́run fi ń ṣe ìdájọ́ gbogbo èèyàn (16, 17)

      • Bí èèyàn ṣe ń kú náà ni ẹranko ń kú (18-22)

        • Gbogbo wọn á pa dà sí erùpẹ̀ (20)

Oníwàásù 3:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2009, ojú ìwé 26

    3/1/2009, ojú ìwé 4-6

    10/1/1999, ojú ìwé 5-6

Oníwàásù 3:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ohun Tí Bíbélì Sọ, àpilẹ̀kọ 80

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 1 2017 ojú ìwé 14

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2009, ojú ìwé 26

    3/1/2009, ojú ìwé 5-6

    10/15/1991, ojú ìwé 5-6

Oníwàásù 3:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “fífò sókè; títa pọ́n-ún pọ́n-ún kiri.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1999, ojú ìwé 6-8

    10/15/1992, ojú ìwé 18

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 97-98

    Jí!,

    7/22/1996, ojú ìwé 25

    6/8/1996, ojú ìwé 14

Oníwàásù 3:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1999, ojú ìwé 8-10

Oníwàásù 3:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 3:31
  • +Sm 39:1
  • +1Sa 19:4; 25:23, 24; Ẹst 4:13, 14; Sm 145:11; Owe 9:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2020, ojú ìwé 18-23

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2019, ojú ìwé 11-12

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2015, ojú ìwé 19-20

    5/15/2009, ojú ìwé 3-5

    10/1/1999, ojú ìwé 12-14

    12/1/1998, ojú ìwé 15-18

    5/15/1996, ojú ìwé 21-23

    Ayọ̀ Ìdílé, ojú ìwé 66

Oníwàásù 3:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 139:21; Ro 12:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2011, ojú ìwé 23-24

    10/1/1999, ojú ìwé 10-12

Oníwàásù 3:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:3; 5:15, 16

Oníwàásù 3:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2009, ojú ìwé 5-6

Oníwàásù 3:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “létòlétò; lọ́nà tó yẹ; lọ́nà tó bá a mu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jẹ 1:31; Ro 1:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 25

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 3 2019 ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tá À Ń Fi Sóde),

    No. 2 2016 ojú ìwé 5

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2015, ojú ìwé 13

    1/1/2014, ojú ìwé 4-5

    3/1/2009, ojú ìwé 5-7

    11/1/2006, ojú ìwé 14

    6/1/2002, ojú ìwé 3

    4/15/1999, ojú ìwé 5-6

    4/1/1996, ojú ìwé 11-12

    1/1/1993, ojú ìwé 3

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 318-319

    1/22/1996, ojú ìwé 13

Oníwàásù 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 37:3; 1Tẹ 5:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2009, ojú ìwé 19

    2/15/1997, ojú ìwé 16-17

Oníwàásù 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 5:18, 19; Ais 65:21, 22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2009, ojú ìwé 19

    3/1/2006, ojú ìwé 17

    2/15/1997, ojú ìwé 16-17

Oníwàásù 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 10:7; Ifi 15:4

Oníwàásù 3:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “ohun tó ti kọjá lọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 1:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2006, ojú ìwé 14

Oníwàásù 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “lábẹ́ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 82:2; 94:16, 21

Oníwàásù 3:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 12:14; Iṣe 17:31; Ro 2:5, 6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/1999, ojú ìwé 14

Oníwàásù 3:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àtúbọ̀tán.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Job 14:10; Sm 39:5; 89:48
  • +Jẹ 7:22; Sm 104:29; Onw 12:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1997, ojú ìwé 10-11

    Ìmọ̀, ojú ìwé 82

Oníwàásù 3:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Onw 9:10
  • +Jẹ 2:7, 19
  • +Jẹ 3:19; Job 10:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 29

    Jí!,

    10/2007, ojú ìwé 31

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/1997, ojú ìwé 10-11

    Ìmọ̀, ojú ìwé 82

Oníwàásù 3:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 146:3, 4; Onw 3:19; 9:10

Oníwàásù 3:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìpín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 12:7; Onw 5:18
  • +Job 14:21; Onw 6:12

Àwọn míì

Oníw. 3:72Sa 3:31
Oníw. 3:7Sm 39:1
Oníw. 3:71Sa 19:4; 25:23, 24; Ẹst 4:13, 14; Sm 145:11; Owe 9:8
Oníw. 3:8Sm 139:21; Ro 12:9
Oníw. 3:9Onw 1:3; 5:15, 16
Oníw. 3:11Jẹ 1:31; Ro 1:20
Oníw. 3:12Sm 37:3; 1Tẹ 5:15
Oníw. 3:13Onw 5:18, 19; Ais 65:21, 22
Oníw. 3:14Jer 10:7; Ifi 15:4
Oníw. 3:15Onw 1:9
Oníw. 3:16Sm 82:2; 94:16, 21
Oníw. 3:17Onw 12:14; Iṣe 17:31; Ro 2:5, 6
Oníw. 3:19Job 14:10; Sm 39:5; 89:48
Oníw. 3:19Jẹ 7:22; Sm 104:29; Onw 12:7
Oníw. 3:20Onw 9:10
Oníw. 3:20Jẹ 2:7, 19
Oníw. 3:20Jẹ 3:19; Job 10:9
Oníw. 3:21Sm 146:3, 4; Onw 3:19; 9:10
Oníw. 3:22Di 12:7; Onw 5:18
Oníw. 3:22Job 14:21; Onw 6:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Oníwàásù 3:1-22

Oníwàásù

3 Ohun gbogbo ni àkókò wà fún,

Àkókò wà fún gbogbo iṣẹ́ lábẹ́ ọ̀run:

 2 Ìgbà bíbímọ àti ìgbà kíkú;

Ìgbà gbígbìn àti ìgbà fífa ohun tí a gbìn tu;

 3 Ìgbà pípa àti ìgbà wíwòsàn;

Ìgbà wíwólulẹ̀ àti ìgbà kíkọ́;

 4 Ìgbà sísunkún àti ìgbà rírẹ́rìn-ín;

Ìgbà pípohùnréré ẹkún àti ìgbà jíjó;*

 5 Ìgbà jíju òkúta sọ nù àti ìgbà kíkó òkúta jọ;

Ìgbà gbígbánimọ́ra àti ìgbà téèyàn ò ní gbáni mọ́ra;

 6 Ìgbà wíwá àti ìgbà gbígbà pé ó ti sọ nù;

Ìgbà fífi pa mọ́ àti ìgbà jíjù sọ nù;

 7 Ìgbà fífàya+ àti ìgbà ríránpọ̀;

Ìgbà dídákẹ́+ àti ìgbà sísọ̀rọ̀;+

 8 Ìgbà nínífẹ̀ẹ́ àti ìgbà kíkórìíra;+

Ìgbà ogun àti ìgbà àlàáfíà.

9 Kí ni èrè tí òṣìṣẹ́ rí jẹ látinú gbogbo ìsapá rẹ̀?+ 10 Mo ti rí iṣẹ́ tí Ọlọ́run gbé fún ọmọ aráyé láti mú kí ọwọ́ wọn dí. 11 Ó ti ṣe ohun gbogbo rèǹtèrente* ní ìgbà tirẹ̀.+ Kódà ó ti fi ayérayé sí wọn lọ́kàn; síbẹ̀ aráyé ò lè rídìí iṣẹ́ tí Ọlọ́run tòótọ́ ti ṣe láé láti ìbẹ̀rẹ̀ dé òpin.

12 Mo ti wá rí i pé kò sí ohun tó dáa fún wọn ju pé kí wọ́n máa yọ̀ kí wọ́n sì máa ṣe rere nígbà ayé wọn,+ 13 àti pé kí kálukú máa jẹ, kó máa mu, kó sì jẹ ìgbádùn gbogbo iṣẹ́ àṣekára rẹ̀. Ẹ̀bùn Ọlọ́run ni.+

14 Mo ti wá mọ̀ pé gbogbo ohun tí Ọlọ́run tòótọ́ ṣe máa wà títí láé. Kò sí nǹkan kan tí a máa fi kún un, kò sì sí nǹkan kan tí a máa yọ kúrò nínú rẹ̀. Ọlọ́run tòótọ́ ti ṣe é bẹ́ẹ̀ kí àwọn èèyàn lè máa bẹ̀rù rẹ̀.+

15 Ohun tó bá ṣẹlẹ̀ ti ṣẹlẹ̀ rí, ohun tó sì ń bọ̀ ti wà tẹ́lẹ̀;+ àmọ́ Ọlọ́run tòótọ́ ń wá ohun tí a ti lépa.*

16 Mo tún ti rí i lábẹ́ ọ̀run* pé: Ìwà burúkú ti rọ́pò ìdájọ́ òdodo, ìwà burúkú sì ti rọ́pò òdodo.+ 17 Torí náà, mo sọ lọ́kàn mi pé: “Ọlọ́run tòótọ́ yóò ṣe ìdájọ́ olódodo àti ẹni burúkú,+ nítorí àkókò wà fún gbogbo iṣẹ́ àti gbogbo akitiyan.”

18 Mo tún sọ nípa àwọn ọmọ aráyé lọ́kàn mi pé Ọlọ́run tòótọ́ máa dán wọn wò, á sì jẹ́ kí wọ́n rí i pé bí ẹranko ni wọ́n rí, 19 nítorí pé ohun* kan wà tó ń ṣẹlẹ̀ sí èèyàn, ohun kan sì wà tó ń ṣẹlẹ̀ sí ẹranko; ohun kan náà ló ń ṣẹlẹ̀ sí gbogbo wọn.+ Bí ọ̀kan ṣe ń kú, bẹ́ẹ̀ ni èkejì ń kú; ẹ̀mí kan náà ni gbogbo wọn ní.+ Torí náà, èèyàn kò lọ́lá ju ẹranko lọ, nítorí pé asán ni ohun gbogbo. 20 Ibì kan náà ni gbogbo wọn ń lọ.+ Inú erùpẹ̀ ni gbogbo wọn ti wá,+ inú erùpẹ̀ sì ni gbogbo wọn ń pa dà sí.+ 21 Ta ló mọ̀ bóyá ẹ̀mí èèyàn ń lọ sí òkè tàbí ẹ̀mí ẹranko ń lọ sí ilẹ̀?+ 22 Mo sì rí i pé kò sí ohun tó dáa fún èèyàn ju pé kó gbádùn iṣẹ́ rẹ̀,+ nítorí ìyẹn ni èrè* rẹ̀; torí ta ló lè mú kó rí ohun tó máa ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn tó bá ti lọ?+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́