ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Pétérù

      • Ẹ ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run bíi ti Kristi (1-6)

      • Òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé (7-11)

      • Tí a bá ń jìyà torí pé a jẹ́ Kristẹni (12-19)

1 Pétérù 4:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣèpinnu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 2:8
  • +Ro 6:11; Kol 3:5; 1Jo 3:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 129

1 Pétérù 4:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 2:20; Ef 5:17
  • +2Kọ 5:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 129

1 Pétérù 4:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìwà ọ̀dájú.” Ó ń tọ́ka sí ọ̀rọ̀ Gíríìkì náà, a·selʹgei·a tí wọ́n bá lò ó fún ohun tó ju ẹyọ kan lọ. Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Tit 3:3
  • +Ro 13:13; 1Kọ 5:11; Ga 5:19, 21; Ef 4:17-19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 44

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2001, ojú ìwé 28

    12/15/1996, ojú ìwé 28

    8/1/1996, ojú ìwé 15

    8/15/1992, ojú ìwé 17-18

    Jí!,

    6/8/1996, ojú ìwé 14-15

    Yiyan, ojú ìwé 110

1 Pétérù 4:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    7/8/1999, ojú ìwé 12

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    12/15/1996, ojú ìwé 28

    Yiyan, ojú ìwé 110

1 Pétérù 4:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 10:42; 17:31; 2Ti 4:1; Ifi 20:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 110

1 Pétérù 4:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 2:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    Yiyan, ojú ìwé 110

1 Pétérù 4:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kí ẹ má sùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:3; 1Ti 3:2; Tit 2:6
  • +Kol 4:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2013, ojú ìwé 3, 4-5

    3/15/2009, ojú ìwé 15-16, 19

    8/15/1997, ojú ìwé 17-22

    6/1/1993, ojú ìwé 15-16

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    8/2003, ojú ìwé 1

    Yiyan, ojú ìwé 180-182

1 Pétérù 4:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 3:14
  • +Owe 10:12; 17:9; 1Kọ 13:4, 7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 303-304

    Ṣọ́nà!, ojú ìwé 28-30

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/1999, ojú ìwé 22

    12/1/1997, ojú ìwé 18

    Yiyan, ojú ìwé 180-182

1 Pétérù 4:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 9:7; Heb 13:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    3/2018, ojú ìwé 14-15

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    10/2017, ojú ìwé 9-10

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1996, ojú ìwé 19

    Yiyan, ojú ìwé 180-181, 182-183

1 Pétérù 4:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:6-8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    7/2016, ojú ìwé 22-25

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 10

    1/15/2009, ojú ìwé 12-14

    6/15/2005, ojú ìwé 30-31

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 75-76

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    6/1998, ojú ìwé 3

    Yiyan, ojú ìwé 183-184

1 Pétérù 4:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 12:2; Ef 3:20
  • +1Kọ 10:31

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 184-185

1 Pétérù 4:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 5:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 129-130

1 Pétérù 4:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 5:41; Jem 1:2
  • +Ro 8:17; 2Kọ 4:10; 2Ti 3:12
  • +1Pe 1:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    5/1/1993, ojú ìwé 21-22

    Yiyan, ojú ìwé 130-131

1 Pétérù 4:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sọ̀rọ̀ àbùkù sí yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jem 1:12; 5:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2014, ojú ìwé 32

    Yiyan, ojú ìwé 130-131

1 Pétérù 4:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 5:13; 1Pe 2:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Jí!,

    2/8/2003, ojú ìwé 24

    Ilé Ìṣọ́,

    6/15/1997, ojú ìwé 30-31

    Yiyan, ojú ìwé 131-133

1 Pétérù 4:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 1:24; Heb 12:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 133

1 Pétérù 4:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 3:6
  • +1Kọ 11:32
  • +2Tẹ 1:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 102-103

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 31-32, 259-260, 284

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2004, ojú ìwé 16

    4/1/1996, ojú ìwé 18

    10/15/1995, ojú ìwé 22

    Yiyan, ojú ìwé 133-134

1 Pétérù 4:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Owe 11:31; Mt 7:13, 14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 133-134

1 Pétérù 4:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn.”

  • *

    Tàbí “máa wá ìtẹ́wọ́gbà Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Ti 1:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 133-134, 136

Àwọn míì

1 Pét. 4:1Flp 2:8
1 Pét. 4:1Ro 6:11; Kol 3:5; 1Jo 3:6
1 Pét. 4:2Ga 2:20; Ef 5:17
1 Pét. 4:22Kọ 5:15
1 Pét. 4:3Tit 3:3
1 Pét. 4:3Ro 13:13; 1Kọ 5:11; Ga 5:19, 21; Ef 4:17-19
1 Pét. 4:41Pe 3:16
1 Pét. 4:5Iṣe 10:42; 17:31; 2Ti 4:1; Ifi 20:12
1 Pét. 4:6Ef 2:1
1 Pét. 4:7Ro 12:3; 1Ti 3:2; Tit 2:6
1 Pét. 4:7Kol 4:2
1 Pét. 4:8Kol 3:14
1 Pét. 4:8Owe 10:12; 17:9; 1Kọ 13:4, 7
1 Pét. 4:92Kọ 9:7; Heb 13:2
1 Pét. 4:10Ro 12:6-8
1 Pét. 4:11Ais 12:2; Ef 3:20
1 Pét. 4:111Kọ 10:31
1 Pét. 4:121Pe 5:9
1 Pét. 4:13Iṣe 5:41; Jem 1:2
1 Pét. 4:13Ro 8:17; 2Kọ 4:10; 2Ti 3:12
1 Pét. 4:131Pe 1:7
1 Pét. 4:14Jem 1:12; 5:11
1 Pét. 4:151Ti 5:13; 1Pe 2:20
1 Pét. 4:16Kol 1:24; Heb 12:2
1 Pét. 4:17Heb 3:6
1 Pét. 4:171Kọ 11:32
1 Pét. 4:172Tẹ 1:7, 8
1 Pét. 4:18Owe 11:31; Mt 7:13, 14
1 Pét. 4:192Ti 1:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Pétérù 4:1-19

Ìwé Kìíní Pétérù

4 Níwọ̀n bí Kristi ti jìyà nínú ẹran ara,+ kí ẹ̀yin náà fi irú èrò kan náà gbára dì;* torí ẹni tó ti jìyà nínú ẹran ara ti jáwọ́ nínú ẹ̀ṣẹ̀,+ 2 kó lè fi àkókò tó ṣẹ́ kù fún un láti gbé nínú ẹran ara ṣe ìfẹ́ Ọlọ́run,+ kó má fi ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ èèyàn mọ́.+ 3 Torí àkókò tó ti kọjá tí ẹ fi ṣe ìfẹ́ àwọn orílẹ̀-èdè ti tó yín,+ nígbà tí ẹ̀ ń hu ìwà àìnítìjú,* tí ẹ̀ ń ṣe ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́, tí ẹ̀ ń mu ọtí àmujù, ṣe àríyá aláriwo, ṣe ìdíje ọtí mímu àti àwọn ìbọ̀rìṣà tó jẹ́ ohun ìríra.+ 4 Ó ń yà wọ́n lẹ́nu pé ẹ ò tún bá wọn lọ́wọ́ sí irú ìwà pálapàla tó ń buni kù bẹ́ẹ̀ mọ́, torí náà, wọ́n ń sọ̀rọ̀ yín láìdáa.+ 5 Ṣùgbọ́n àwọn èèyàn yìí máa jíhìn fún ẹni tó ti ṣe tán láti ṣèdájọ́ àwọn tó wà láàyè àtàwọn tó ti kú.+ 6 Kódà, ìdí nìyẹn tí a fi kéde ìhìn rere fún àwọn òkú pẹ̀lú,+ kó lè jẹ́ pé bí a tiẹ̀ ṣèdájọ́ wọn nínú ẹran ara lójú àwọn èèyàn, wọ́n á lè wà láàyè nípa tẹ̀mí lójú Ọlọ́run.

7 Àmọ́ òpin ohun gbogbo ti sún mọ́lé. Torí náà, kí ẹ máa ronú jinlẹ̀,+ kí ẹ sì wà lójúfò,* kí ẹ lè máa gbàdúrà.+ 8 Ju gbogbo rẹ̀ lọ, ẹ ní ìfẹ́ tó jinlẹ̀ fún ara yín,+ torí ìfẹ́ máa ń bo ọ̀pọ̀lọpọ̀ ẹ̀ṣẹ̀ mọ́lẹ̀.+ 9 Ẹ máa ṣe ara yín lálejò láìráhùn.+ 10 Bí kálukú bá ṣe ń rí ẹ̀bùn gbà, ẹ máa fi ṣe ìránṣẹ́ fún ara yín bí ìríjú àtàtà tó ń rí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run gbà lóríṣiríṣi ọ̀nà.+ 11 Tí ẹnikẹ́ni bá ń sọ̀rọ̀, kó sọ ọ́ bíi pé ó ń kéde ọ̀rọ̀ Ọlọ́run; tí ẹnikẹ́ni bá ń ṣe ìránṣẹ́, kó ṣe é bí ẹni tó gbára lé okun tí Ọlọ́run ń fúnni;+ ká lè yin Ọlọ́run lógo nínú ohun gbogbo+ nípasẹ̀ Jésù Kristi. Ògo àti agbára jẹ́ tirẹ̀ títí láé àti láéláé. Àmín.

12 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, ẹ má ṣe jẹ́ kí àwọn àdánwò gbígbóná tó ń bá yín yà yín lẹ́nu,+ bíi pé nǹkan àjèjì ló ń ṣẹlẹ̀ sí yín. 13 Kàkà bẹ́ẹ̀, ẹ máa yọ̀+ torí ibi tí ẹ lè bá Kristi jìyà dé,+ kí ẹ̀yin pẹ̀lú lè yọ̀, kí ayọ̀ yín sì kún nígbà ìfihàn ògo rẹ̀.+ 14 Inú yín máa dùn tí wọ́n bá ń gàn yín* nítorí orúkọ Kristi,+ torí pé ẹ̀mí ògo, àní ẹ̀mí Ọlọ́run, ti bà lé yín.

15 Àmọ́ ká má ṣe rí ẹnikẹ́ni nínú yín tó ń jìyà torí pé ó jẹ́ apààyàn tàbí olè tàbí aṣebi tàbí torí ó ń tojú bọ ọ̀rọ̀ ọlọ́rọ̀.+ 16 Àmọ́ tí ẹnikẹ́ni bá jìyà torí pé ó jẹ́ Kristẹni, kó má ṣe tijú,+ àmọ́ kó túbọ̀ máa yin Ọlọ́run lógo bó ṣe ń jẹ́ orúkọ yìí. 17 Torí àkókò tí ìdájọ́ máa bẹ̀rẹ̀ ní ilé Ọlọ́run ti tó.+ Tó bá wá bẹ̀rẹ̀ lọ́dọ̀ wa,+ kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ sí àwọn tí kò ṣègbọràn sí ìhìn rere Ọlọ́run?+ 18 “Tí kò bá ní rọrùn láti gba olódodo là, kí ló máa wá ṣẹlẹ̀ sí aláìṣèfẹ́ Ọlọ́run àti ẹlẹ́ṣẹ̀?”+ 19 Nítorí náà, kí àwọn tó ń jìyà lọ́nà tó bá ìfẹ́ Ọlọ́run mu máa fi ara* wọn lé Ẹlẹ́dàá tó jẹ́ olóòótọ́ lọ́wọ́,* kí wọ́n sì máa ṣe rere.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́