ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Ẹ́kísódù 15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Ẹ́kísódù

      • Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọrin ìṣẹ́gun (1-19)

      • Míríámù fi orin dáhùn pa dà (20, 21)

      • Omi tó korò wá dùn (22-27)

Ẹ́kísódù 15:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ond 5:1; 2Sa 22:1; Ifi 15:3
  • +Ẹk 9:16; 18:10, 11; Sm 106:11, 12
  • +Ẹk 15:21; Sm 136:15

Ẹ́kísódù 15:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    “Jáà” ni ìkékúrú Jèhófà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 12:2
  • +2Sa 22:47; Ais 25:1
  • +Ẹk 3:15
  • +Sm 83:18; 148:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1995, ojú ìwé 10-11

Ẹ́kísódù 15:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 24:8
  • +Ẹk 6:3; Ais 42:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1995, ojú ìwé 11

    8/15/1991, ojú ìwé 24-25

Ẹ́kísódù 15:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:27
  • +Ẹk 14:6, 7

Ẹ́kísódù 15:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ne 9:10, 11

Ẹ́kísódù 15:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 60:5; 89:13

Ẹ́kísódù 15:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 37:23

Ẹ́kísódù 15:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2004, ojú ìwé 26

Ẹ́kísódù 15:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọkàn mi.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:5, 9

Ẹ́kísódù 15:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:21, 28

Ẹ́kísódù 15:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 3:24; 2Sa 7:22
  • +Ais 6:3
  • +Ẹk 11:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2021, ojú ìwé 3

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/15/1995, ojú ìwé 11-12

Ẹ́kísódù 15:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 78:53; Heb 11:29

Ẹ́kísódù 15:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 106:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Sún Mọ́ Jèhófà, ojú ìwé 285-286

Ẹ́kísódù 15:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “jẹ̀rora ìbímọ.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 14:13, 14

Ẹ́kísódù 15:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Séríkí jẹ́ olóyè láàárín ẹ̀yà kan.

  • *

    Tàbí “Àwọn olórí tó ń ṣi agbára lò ní Móábù.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 22:1, 3
  • +Joṣ 2:9-11; 5:1

Ẹ́kísódù 15:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 11:25
  • +2Sa 7:23; Ais 43:1
  • +Nọ 20:14, 17; 21:21, 22

Ẹ́kísódù 15:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 80:8

Ẹ́kísódù 15:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 10:16

Ẹ́kísódù 15:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:23
  • +Ẹk 14:28
  • +Ẹk 14:22

Ẹ́kísódù 15:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 9:16; 18:11
  • +Ẹk 14:27, 28; Sm 106:11, 12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 8/2020, ojú ìwé 3

Ẹ́kísódù 15:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó túmọ̀ sí “Ìkorò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Nọ 33:8

Ẹ́kísódù 15:24

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 16:2, 3; 17:3; 1Kọ 10:6, 10

Ẹ́kísódù 15:25

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 17:4
  • +Ẹk 16:4; Di 8:2

Ẹ́kísódù 15:26

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:1
  • +Di 7:12, 15
  • +Ẹk 23:25; Sm 103:3

Àwọn míì

Ẹ́kís. 15:1Ond 5:1; 2Sa 22:1; Ifi 15:3
Ẹ́kís. 15:1Ẹk 9:16; 18:10, 11; Sm 106:11, 12
Ẹ́kís. 15:1Ẹk 15:21; Sm 136:15
Ẹ́kís. 15:2Ais 12:2
Ẹ́kís. 15:22Sa 22:47; Ais 25:1
Ẹ́kís. 15:2Ẹk 3:15
Ẹ́kís. 15:2Sm 83:18; 148:13
Ẹ́kís. 15:3Sm 24:8
Ẹ́kís. 15:3Ẹk 6:3; Ais 42:8
Ẹ́kís. 15:4Ẹk 14:27
Ẹ́kís. 15:4Ẹk 14:6, 7
Ẹ́kís. 15:5Ne 9:10, 11
Ẹ́kís. 15:6Sm 60:5; 89:13
Ẹ́kís. 15:7Ais 37:23
Ẹ́kís. 15:9Ẹk 14:5, 9
Ẹ́kís. 15:10Ẹk 14:21, 28
Ẹ́kís. 15:11Di 3:24; 2Sa 7:22
Ẹ́kís. 15:11Ais 6:3
Ẹ́kís. 15:11Ẹk 11:9
Ẹ́kís. 15:12Sm 78:53; Heb 11:29
Ẹ́kís. 15:13Sm 106:10
Ẹ́kís. 15:14Nọ 14:13, 14
Ẹ́kís. 15:15Nọ 22:1, 3
Ẹ́kís. 15:15Joṣ 2:9-11; 5:1
Ẹ́kís. 15:16Di 11:25
Ẹ́kís. 15:162Sa 7:23; Ais 43:1
Ẹ́kís. 15:16Nọ 20:14, 17; 21:21, 22
Ẹ́kís. 15:17Sm 80:8
Ẹ́kís. 15:18Sm 10:16
Ẹ́kís. 15:19Ẹk 14:23
Ẹ́kís. 15:19Ẹk 14:28
Ẹ́kís. 15:19Ẹk 14:22
Ẹ́kís. 15:21Ẹk 9:16; 18:11
Ẹ́kís. 15:21Ẹk 14:27, 28; Sm 106:11, 12
Ẹ́kís. 15:23Nọ 33:8
Ẹ́kís. 15:24Ẹk 16:2, 3; 17:3; 1Kọ 10:6, 10
Ẹ́kís. 15:25Ẹk 17:4
Ẹ́kís. 15:25Ẹk 16:4; Di 8:2
Ẹ́kís. 15:26Di 28:1
Ẹ́kís. 15:26Di 7:12, 15
Ẹ́kís. 15:26Ẹk 23:25; Sm 103:3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
  • 26
  • 27
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Ẹ́kísódù 15:1-27

Ẹ́kísódù

15 Nígbà yẹn, Mósè àti àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kọ orin yìí sí Jèhófà:+

“Jẹ́ kí n kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+

Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.+

 2 Jáà* ni okun àti agbára mi, torí ó ti wá gbà mí là.+

Ọlọ́run mi nìyí, màá yìn ín;+ Ọlọ́run bàbá mi,+ màá gbé e ga.+

 3 Jagunjagun tó lágbára ni Jèhófà.+ Jèhófà ni orúkọ rẹ̀.+

 4 Ó ti ju àwọn kẹ̀kẹ́ ẹṣin Fáráò àti àwọn ọmọ ogun rẹ̀ sínú òkun,+

Àwọn tó dára jù nínú àwọn jagunjagun rẹ̀ sì ti rì sínú Òkun Pupa.+

 5 Alagbalúgbú omi bò wọ́n; wọ́n rì sí ìsàlẹ̀ ibú omi bí òkúta.+

 6 Ọwọ́ ọ̀tún rẹ mà lágbára o, Jèhófà;+

Jèhófà, ọwọ́ ọ̀tún rẹ lè fọ́ ọ̀tá túútúú.

 7 Nínú ọlá ńlá rẹ, o lè bi àwọn tó bá dìde sí ọ ṣubú;+

O mú kí ìbínú rẹ tó ń jó fòfò jẹ wọ́n run bí àgékù pòròpórò.

 8 Èémí tó ti ihò imú rẹ jáde mú kí omi wọ́ jọ;

Omi náà dúró, kò pa dà;

Alagbalúgbú omi dì láàárín òkun.

 9 Ọ̀tá sọ pé: ‘Màá lépa wọn! Màá lé wọn bá!

Màá pín ẹrù ogun wọn títí yóò fi tẹ́ mi* lọ́rùn!

Màá fa idà mi yọ! Ọwọ́ mi yóò ṣẹ́gun wọn!’+

 10 O fẹ́ èémí rẹ jáde, òkun sì bò wọ́n;+

Wọ́n rì sínú alagbalúgbú omi bí òjé.

 11 Jèhófà, ta ló dà bí rẹ nínú àwọn ọlọ́run?+

Ta ló dà bí rẹ, ìwọ tí o fi hàn pé ẹni mímọ́ jù lọ ni ọ́?+

Ẹni tó yẹ ká máa bẹ̀rù, ká máa fi orin yìn, Ẹni tó ń ṣe ohun ìyanu.+

 12 O na ọwọ́ ọ̀tún rẹ, ilẹ̀ sì gbé wọn mì.+

 13 O fi ìfẹ́ rẹ tí kì í yẹ̀ ṣamọ̀nà àwọn èèyàn tí o rà pa dà;+

Ìwọ yóò fi agbára rẹ darí wọn lọ sí ibùgbé rẹ mímọ́.

 14 Àwọn èèyàn gbọ́dọ̀ gbọ́,+ jìnnìjìnnì á bò wọ́n;

Àwọn tó ń gbé Filísíà máa jẹ̀rora.*

 15 Ní àkókò yẹn, ẹ̀rù yóò ba àwọn séríkí* Édómù,

Àwọn alágbára tó ń ṣàkóso Móábù* yóò gbọ̀n rìrì.+

Ọkàn gbogbo àwọn tó ń gbé ní Kénáánì yóò domi.+

 16 Ìbẹ̀rù àti jìnnìjìnnì yóò bò wọ́n.+

Ọwọ́ ńlá rẹ yóò mú kí wọ́n dúró sójú kan bí òkúta

Títí àwọn èèyàn rẹ yóò fi kọjá, Jèhófà,

Títí àwọn èèyàn tí o mú jáde+ yóò fi kọjá.+

 17 Ìwọ yóò mú wọn wá, ìwọ yóò sì gbìn wọ́n sí òkè ogún rẹ,+

Ibi tó fìdí múlẹ̀ tí o ti pèsè kí ìwọ fúnra rẹ lè máa gbé, Jèhófà,

Ibi mímọ́ tí o fi ọwọ́ rẹ ṣe, Jèhófà.

 18 Jèhófà yóò máa jọba títí láé àti láéláé.+

 19 Nígbà tí àwọn ẹṣin Fáráò àti àwọn kẹ̀kẹ́ ogun rẹ̀ àti àwọn agẹṣin rẹ̀ wọnú òkun,+

Jèhófà mú kí omi òkun pa dà, ó sì bò wọ́n mọ́lẹ̀,+

Àmọ́ àwọn ọmọ Ísírẹ́lì gba orí ilẹ̀ kọjá láàárín òkun.”+

20 Míríámù wòlíì obìnrin, ẹ̀gbọ́n Áárónì wá mú ìlù tanboríìnì, gbogbo obìnrin sì ń jó tẹ̀ lé e pẹ̀lú ìlù tanboríìnì. 21 Míríámù fi orin dá àwọn ọkùnrin lóhùn pé:

“Ẹ kọrin sí Jèhófà, torí ó ti di ẹni àgbéga.+

Ó taari ẹṣin àti ẹni tó gùn ún sínú òkun.”+

22 Lẹ́yìn náà, Mósè darí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kúrò ní Òkun Pupa, wọ́n sì lọ sí aginjù Ṣúrì. Wọ́n rin ìrìn ọjọ́ mẹ́ta ní aginjù, àmọ́ wọn ò rí omi. 23 Wọ́n dé Márà,*+ àmọ́ wọn ò lè mu omi tó wà ní Márà torí ó korò. Ìdí nìyẹn tó fi pè é ní Márà. 24 Àwọn èèyàn náà wá ń kùn sí Mósè+ pé: “Kí la máa mu báyìí?” 25 Ó bá ké pe Jèhófà,+ Jèhófà sì darí rẹ̀ síbi igi kan. Nígbà tó jù ú sínú omi, omi náà wá dùn.

Ibẹ̀ ni Ọlọ́run ti gbé òfin àti ìlànà ìdájọ́ kalẹ̀ fún wọn, Ó sì dán wọn wò níbẹ̀.+ 26 Ó sọ pé: “Tí ẹ bá ṣègbọràn sí ohùn Jèhófà Ọlọ́run yín délẹ̀délẹ̀, tí ẹ ṣe ohun tó tọ́ ní ojú rẹ̀, tí ẹ pa àwọn àṣẹ rẹ̀ mọ́, tí ẹ sì ń tẹ̀ lé gbogbo ìlànà rẹ̀,+ mi ò ní mú kí ìkankan ṣe yín nínú àwọn àrùn tí mo mú kó ṣe àwọn ará Íjíbítì,+ torí èmi Jèhófà ló ń mú yín lára dá.”+

27 Lẹ́yìn náà, wọ́n dé Élímù, níbi tí ìsun omi méjìlá (12) àti àádọ́rin (70) igi ọ̀pẹ wà. Wọ́n sì pàgọ́ síbẹ̀ lẹ́gbẹ̀ẹ́ omi náà.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́