ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 24
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Jeremáyà

      • Àwọn ọ̀pọ̀tọ́ tó dára àtèyí tó ti bà jẹ́ (1-10)

Jeremáyà 24:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “Nebukadirésárì,” ọ̀nà míì tí wọ́n ń gbà kọ orúkọ yìí.

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Jèhóákínì àti Konáyà.

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “àwọn tó ń kọ́ odi ààbò.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 22:24
  • +2Ọb 24:6; 1Kr 3:16
  • +2Ọb 24:15, 16; Jer 29:1, 2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 13-14

Jeremáyà 24:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 13-14

Jeremáyà 24:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 24:8

Jeremáyà 24:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 14-15, 17

Jeremáyà 24:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:3; Jer 12:15; 25:11; 29:10; Isk 36:24
  • +Jer 1:10; 30:18; 32:41

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 14-15, 17

Jeremáyà 24:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 30:6; Jer 31:33; Isk 11:19
  • +Jer 30:22; 32:38; Sek 8:8
  • +Jer 29:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2013, ojú ìwé 8-9

    3/1/1994, ojú ìwé 14-15, 17

Jeremáyà 24:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 29:17
  • +2Ọb 25:6, 7; Isk 12:12, 13
  • +Jer 44:1; 46:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 15-16

Jeremáyà 24:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 15:4; 34:17
  • +Jer 26:4, 6; 29:22
  • +Di 28:64; Jer 29:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 15

Jeremáyà 24:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àìsàn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:33; Jer 9:16
  • +Di 28:59; Jer 15:2; Isk 7:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    3/1/1994, ojú ìwé 15

Àwọn míì

Jer. 24:1Jer 22:24
Jer. 24:12Ọb 24:6; 1Kr 3:16
Jer. 24:12Ọb 24:15, 16; Jer 29:1, 2
Jer. 24:3Jer 24:8
Jer. 24:6Ẹsr 1:3; Jer 12:15; 25:11; 29:10; Isk 36:24
Jer. 24:6Jer 1:10; 30:18; 32:41
Jer. 24:7Di 30:6; Jer 31:33; Isk 11:19
Jer. 24:7Jer 30:22; 32:38; Sek 8:8
Jer. 24:7Jer 29:13
Jer. 24:8Jer 29:17
Jer. 24:82Ọb 25:6, 7; Isk 12:12, 13
Jer. 24:8Jer 44:1; 46:13
Jer. 24:9Jer 15:4; 34:17
Jer. 24:9Jer 26:4, 6; 29:22
Jer. 24:9Di 28:64; Jer 29:18
Jer. 24:10Le 26:33; Jer 9:16
Jer. 24:10Di 28:59; Jer 15:2; Isk 7:15
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Jeremáyà 24:1-10

Jeremáyà

24 Lẹ́yìn náà, Jèhófà fi apẹ̀rẹ̀ méjì tí ọ̀pọ̀tọ́ wà nínú wọn níwájú tẹ́ńpìlì Jèhófà hàn mí. Èyí wáyé lẹ́yìn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì mú Jekonáyà*+ ọmọ Jèhóákímù,+ ọba Júdà lọ sí ìgbèkùn pẹ̀lú àwọn ìjòyè Júdà àti àwọn oníṣẹ́ ọnà pẹ̀lú àwọn oníṣẹ́ irin.* Ó kó wọn láti Jerúsálẹ́mù lọ sí Bábílónì.+ 2 Ọ̀pọ̀tọ́ inú apẹ̀rẹ̀ àkọ́kọ́ dára gan-an, ó dà bí àkọ́pọ́n èso ọ̀pọ̀tọ́, àmọ́ ọ̀pọ̀tọ́ inú apẹ̀rẹ̀ kejì ti bà jẹ́ gan-an débi pé kò ṣeé jẹ.

3 Jèhófà wá bi mí pé: “Jeremáyà, kí lo rí?” Torí náà, mo sọ pé: “Èso ọ̀pọ̀tọ́ ni. Àwọn tó dára, dára gan-an, àwọn tó sì bà jẹ́ ti bà jẹ́ gan-an débi pé wọn ò ṣeé jẹ.”+

4 Ìgbà náà ni Jèhófà bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 5 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Bí àwọn ọ̀pọ̀tọ́ yìí ṣe dára, bẹ́ẹ̀ ni màá ṣe fi ojú tó dára wo àwọn ará Júdà tó wà ní ìgbèkùn, àwọn tí mo rán lọ kúrò ní ibí yìí sí ilẹ̀ àwọn ará Kálídíà. 6 Ojú mi yóò wà lára wọn láti ṣe wọ́n lóore, màá sì mú kí wọ́n pa dà sí ilẹ̀ yìí.+ Màá gbé wọn ró, mi ò sì ní ya wọ́n lulẹ̀, màá gbìn wọ́n, mi ò sì ní fà wọ́n tu.+ 7 Màá fún wọn ní ọkàn tí á jẹ́ kí wọ́n fẹ́ láti mọ̀ mí, pé èmi ni Jèhófà.+ Wọ́n á di èèyàn mi, màá sì di Ọlọ́run wọn,+ nítorí wọ́n á fi gbogbo ọkàn wọn pa dà sọ́dọ̀ mi.+

8 “‘Àmọ́ ní ti ọ̀pọ̀tọ́ tó ti bà jẹ́ débi pé kò ṣeé jẹ,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Bákan náà ni màá ṣe sí Sedekáyà+ ọba Júdà àti àwọn ìjòyè rẹ̀ pẹ̀lú àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn Jerúsálẹ́mù tó wà ní ilẹ̀ yìí àti àwọn tó ń gbé ní ilẹ̀ Íjíbítì.+ 9 Màá sọ wọ́n di ohun àríbẹ̀rù àti àjálù lójú gbogbo ìjọba ayé,+ màá jẹ́ kí wọ́n di ẹni ẹ̀gàn àti ẹni àfipòwe, ẹni ẹ̀sín àti ẹni ègún + ní gbogbo ibi tí màá fọ́n wọn ká sí.+ 10 Màá rán idà+ àti ìyàn pẹ̀lú àjàkálẹ̀ àrùn* sí wọn,+ títí wọ́n á fi ṣègbé kúrò lórí ilẹ̀ tí mo fún àwọn àti àwọn baba ńlá wọn.”’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́