ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Tẹsalóníkà 1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Tẹsalóníkà

      • Ìkíni (1)

      • Pọ́ọ̀lù dúpẹ́ nítorí ìgbàgbọ́ àwọn ará Tẹsalóníkà (2-10)

1 Tẹsalóníkà 1:1

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wọ́n tún ń pè é ní Sílà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 15:22; 1Pe 5:12
  • +Iṣe 16:1, 2

1 Tẹsalóníkà 1:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 1:11, 12

1 Tẹsalóníkà 1:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2007, ojú ìwé 6

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2000, ojú ìwé 4

1 Tẹsalóníkà 1:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 194

    Ilé Ìṣọ́,

    3/1/2000, ojú ìwé 16-17

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2000, ojú ìwé 3-4

1 Tẹsalóníkà 1:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 11:1; Flp 3:17; 2Tẹ 3:9
  • +1Pe 2:21
  • +1Tẹ 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    2/2000, ojú ìwé 3-4

1 Tẹsalóníkà 1:8

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Tẹ 1:4

1 Tẹsalóníkà 1:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:14; 12:2; Ga 4:8; 1Jo 5:21

1 Tẹsalóníkà 1:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 1:10, 11; Tit 2:13
  • +1Tẹ 5:2; 2Pe 3:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2010, ojú ìwé 13

Àwọn míì

1 Tẹs. 1:1Iṣe 15:22; 1Pe 5:12
1 Tẹs. 1:1Iṣe 16:1, 2
1 Tẹs. 1:22Tẹ 1:11, 12
1 Tẹs. 1:31Pe 1:3, 4
1 Tẹs. 1:61Kọ 11:1; Flp 3:17; 2Tẹ 3:9
1 Tẹs. 1:61Pe 2:21
1 Tẹs. 1:61Tẹ 2:14
1 Tẹs. 1:82Tẹ 1:4
1 Tẹs. 1:91Kọ 10:14; 12:2; Ga 4:8; 1Jo 5:21
1 Tẹs. 1:101Tẹ 5:2; 2Pe 3:12
1 Tẹs. 1:10Iṣe 1:10, 11; Tit 2:13
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Tẹsalóníkà 1:1-10

Ìwé Kìíní sí Àwọn Ará Tẹsalóníkà

1 Pọ́ọ̀lù, Sílífánù*+ àti Tímótì,+ sí ìjọ àwọn ará Tẹsalóníkà tó wà ní ìṣọ̀kan pẹ̀lú Ọlọ́run tó jẹ́ Baba àti Jésù Kristi Olúwa:

Kí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí àti àlàáfíà wà pẹ̀lú yín.

2 Ìgbà gbogbo là ń dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run tí a bá ń rántí gbogbo yín nínú àdúrà wa,+ 3 torí a ò lè ṣe ká má rántí iṣẹ́ tí ìgbàgbọ́ mú kí ẹ ṣe àti ìsapá onífẹ̀ẹ́ yín pẹ̀lú ìfaradà yín nítorí ìrètí tí ẹ ní+ nínú Olúwa wa Jésù Kristi níwájú Ọlọ́run àti Baba wa. 4 Ẹ̀yin ará tí Ọlọ́run nífẹ̀ẹ́, a mọ̀ pé òun ló yàn yín, 5 nítorí kì í ṣe nípasẹ̀ ọ̀rọ̀ nìkan ni ìhìn rere tí à ń wàásù fi dé ọ̀dọ̀ yín, ó tún wá nípasẹ̀ agbára, nípasẹ̀ ẹ̀mí mímọ́ àti nípasẹ̀ ìdánilójú tó lágbára, bí ẹ ṣe mọ irú ẹni tí a dà láàárín yín àti nítorí yín. 6 Ẹ sì ń fara wé àwa+ àti Olúwa,+ bí ẹ ṣe tẹ́wọ́ gba ọ̀rọ̀ náà lójú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpọ́njú+ pẹ̀lú ayọ̀ ẹ̀mí mímọ́, 7 débi pé ẹ di àpẹẹrẹ fún gbogbo àwọn onígbàgbọ́ ní Makedóníà àti ní Ákáyà.

8 Òótọ́ ibẹ̀ ni pé, kì í ṣe pé ọ̀rọ̀ Jèhófà* ti dún jáde látọ̀dọ̀ yín ní Makedóníà àti Ákáyà nìkan ni, àmọ́ ìgbàgbọ́ yín nínú Ọlọ́run ti tàn káàkiri níbi gbogbo,+ débi pé a kò nílò láti sọ ohunkóhun. 9 Nítorí àwọn fúnra wọn ń ròyìn nípa bí a ṣe kọ́kọ́ dé ọ̀dọ̀ yín àti bí ẹ ṣe fi àwọn òrìṣà yín sílẹ̀,+ tí ẹ sì yíjú sọ́dọ̀ Ọlọ́run kí ẹ lè jẹ́ ẹrú Ọlọ́run tòótọ́ àti alààyè, 10 kí ẹ sì lè dúró de Ọmọ rẹ̀ láti ọ̀run,+ ẹni tó gbé dìde kúrò nínú ikú, ìyẹn Jésù tó gbà wá sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ ìrunú tó ń bọ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́