ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Tẹsalóníkà 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Tẹsalóníkà

      • Ọkùnrin arúfin (1-12)

      • Ó gbà wọ́n níyànjú pé kí wọ́n dúró gbọn-in (13-17)

2 Tẹsalóníkà 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:3
  • +1Tẹ 4:17

2 Tẹsalóníkà 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “torí ẹ̀mí.” Wo Àlàyé Ọ̀rọ̀, “Ẹ̀mí.”

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:1
  • +Sef 1:14; 2Pe 3:10

2 Tẹsalóníkà 2:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “sún yín dẹ́ṣẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Ti 4:1; 2Ti 2:16-18; 4:3; 2Pe 2:1; 1Jo 2:18, 19
  • +Mt 7:15; Iṣe 20:29, 30
  • +2Pe 2:1, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2015, ojú ìwé 15

    9/15/2008, ojú ìwé 30

    9/1/2003, ojú ìwé 6

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1703

    “Kí Ijọba Rẹ Dé,” ojú ìwé 89

    “Ete aiyeraiye,” ojú ìwé 170

2 Tẹsalóníkà 2:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọ̀wọ̀.”

2 Tẹsalóníkà 2:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    7/2019, ojú ìwé 4

2 Tẹsalóníkà 2:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 20:29, 30; 1Kọ 11:18, 19; 1Jo 2:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    7/2019, ojú ìwé 4

2 Tẹsalóníkà 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:4; Ifi 19:15
  • +1Ti 6:13-15; 2Ti 4:1, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    7/2019, ojú ìwé 4

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2010, ojú ìwé 28

    9/15/2008, ojú ìwé 30

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 282

2 Tẹsalóníkà 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àwọn àmì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 11:3
  • +Mt 24:24

2 Tẹsalóníkà 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1991, ojú ìwé 24

2 Tẹsalóníkà 2:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 24:5; 1Ti 4:1; 2Ti 4:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 7/2019, ojú ìwé 4

2 Tẹsalóníkà 2:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 6:44; Ro 8:30
  • +Jo 17:17; 1Kọ 6:11; 1Tẹ 4:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 30

2 Tẹsalóníkà 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 5:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2008, ojú ìwé 30

2 Tẹsalóníkà 2:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 15:58; 16:13
  • +1Kọ 11:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2013, ojú ìwé 8-9

2 Tẹsalóníkà 2:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Jo 4:10
  • +1Pe 1:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1995, ojú ìwé 19

2 Tẹsalóníkà 2:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “fún yín lókun.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    4/1/1995, ojú ìwé 19

Àwọn míì

2 Tẹs. 2:1Mt 24:3
2 Tẹs. 2:11Tẹ 4:17
2 Tẹs. 2:21Jo 4:1
2 Tẹs. 2:2Sef 1:14; 2Pe 3:10
2 Tẹs. 2:31Ti 4:1; 2Ti 2:16-18; 4:3; 2Pe 2:1; 1Jo 2:18, 19
2 Tẹs. 2:3Mt 7:15; Iṣe 20:29, 30
2 Tẹs. 2:32Pe 2:1, 3
2 Tẹs. 2:7Iṣe 20:29, 30; 1Kọ 11:18, 19; 1Jo 2:18
2 Tẹs. 2:8Ais 11:4; Ifi 19:15
2 Tẹs. 2:81Ti 6:13-15; 2Ti 4:1, 8
2 Tẹs. 2:92Kọ 11:3
2 Tẹs. 2:9Mt 24:24
2 Tẹs. 2:10Mt 24:11
2 Tẹs. 2:11Mt 24:5; 1Ti 4:1; 2Ti 4:3, 4
2 Tẹs. 2:13Jo 6:44; Ro 8:30
2 Tẹs. 2:13Jo 17:17; 1Kọ 6:11; 1Tẹ 4:7
2 Tẹs. 2:141Pe 5:10
2 Tẹs. 2:151Kọ 15:58; 16:13
2 Tẹs. 2:151Kọ 11:2
2 Tẹs. 2:161Jo 4:10
2 Tẹs. 2:161Pe 1:3, 4
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Tẹsalóníkà 2:1-17

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Tẹsalóníkà

2 Àmọ́, ẹ̀yin ará, ní ti wíwàníhìn-ín Olúwa wa Jésù Kristi+ àti kíkó wa jọ sọ́dọ̀ rẹ̀,+ a rọ̀ yín 2 kí ọkàn yín má tètè mì tàbí kí ó dà rú nítorí ọ̀rọ̀ onímìísí*+ tàbí nítorí iṣẹ́ tí a fẹnu jẹ́ tàbí nítorí lẹ́tà kan tó dà bíi pé ó wá látọ̀dọ̀ wa, tó ń sọ pé ọjọ́ Jèhófà*+ ti dé.

3 Ẹ má ṣe jẹ́ kí ẹnì kankan kó yín ṣìnà* lọ́nàkọnà, nítorí kò ní dé láìjẹ́ pé ìpẹ̀yìndà+ kọ́kọ́ dé, tí a sì fi ọkùnrin arúfin+ hàn, ìyẹn ọmọ ìparun.+ 4 Alátakò ni, ó sì gbé ara rẹ̀ lékè gbogbo àwọn tí wọ́n ń pè ní ọlọ́run tàbí ohun ìjọsìn,* tó fi jẹ́ pé ó jókòó nínú tẹ́ńpìlì Ọlọ́run, ó sì ń fi ara rẹ̀ hàn ní gbangba pé òun jẹ́ ọlọ́run. 5 Ṣé ẹ rántí pé nígbà tí mo ṣì wà pẹ̀lú yín, mo máa ń sọ àwọn nǹkan yìí fún yín?

6 Ní báyìí, ẹ mọ ohun tó ń ṣèdíwọ́ kó má bàa fara hàn ṣáájú àkókò rẹ̀. 7 Lóòótọ́, àṣírí ìwà ìkà yìí ti wà lẹ́nu iṣẹ́,+ àmọ́ ó dìgbà tí ẹni tó ń ṣèdíwọ́ ní báyìí bá kúrò lọ́nà. 8 Lẹ́yìn náà, a ó fi arúfin náà hàn, ẹni tí Jésù Olúwa máa fi ẹ̀mí ẹnu rẹ̀ pa,+ tí á sì sọ di asán nígbà tó bá ṣe kedere+ pé ó ti wà níhìn-ín. 9 Àmọ́ ohun tó mú kí arúfin náà wà níhìn-ín jẹ́ iṣẹ́ ọwọ́ Sátánì+ pẹ̀lú gbogbo iṣẹ́ agbára àti àwọn iṣẹ́ àmì àti iṣẹ́ ìyanu* tó jẹ́ irọ́ + 10 pẹ̀lú gbogbo ẹ̀tàn àìṣòdodo  + fún àwọn tó ń ṣègbé, gẹ́gẹ́ bí ẹ̀san iṣẹ́ wọn nítorí pé wọn ò gba ìfẹ́ òtítọ́ kí wọ́n lè rí ìgbàlà. 11 Ìdí nìyẹn tí Ọlọ́run fi jẹ́ kí ohun tó ń ṣiṣẹ́ ẹ̀tàn kó wọn ṣìnà, kí wọ́n lè gba irọ́ gbọ́,+ 12 kí a lè dá gbogbo wọn lẹ́jọ́ torí pé wọn ò gba òtítọ́ gbọ́, kàkà bẹ́ẹ̀ ṣe ni wọ́n ń fi àìṣòdodo ṣayọ̀.

13 Síbẹ̀, ó di dandan fún wa láti máa dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run nígbà gbogbo nítorí yín, ẹ̀yin ará tí Jèhófà* nífẹ̀ẹ́, torí pé àtìbẹ̀rẹ̀ ni Ọlọ́run ti yàn yín+ fún ìgbàlà nípa fífi ẹ̀mí rẹ̀ sọ yín di mímọ́+ àti nípa ìgbàgbọ́ yín nínú òtítọ́. 14 Ó tipasẹ̀ ìhìn rere tí à ń kéde pè yín sí èyí, kí ẹ lè ní ògo Olúwa wa Jésù Kristi.+ 15 Nítorí náà, ẹ̀yin ará, ẹ dúró gbọn-in,+ kí ẹ sì di àwọn àṣà tí a fi kọ́ yín mú ṣinṣin,+ ì báà jẹ́ nípasẹ̀ iṣẹ́ tí a fẹnu jẹ́ tàbí nípasẹ̀ lẹ́tà látọ̀dọ̀ wa. 16 Jù bẹ́ẹ̀ lọ, kí Olúwa wa Jésù Kristi fúnra rẹ̀ àti Ọlọ́run, Baba wa, ẹni tó nífẹ̀ẹ́ wa,+ tó sì fún wa ní ìtùnú ayérayé àti ìrètí rere+ nípasẹ̀ inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí, 17 tu ọkàn yín lára, kó sì fìdí yín múlẹ̀ gbọn-in* nínú gbogbo iṣẹ́ rere àti ọ̀rọ̀ rere.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́