ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sekaráyà 8
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Sekaráyà

      • Jèhófà fún Síónì ní àlàáfíà àti òtítọ́ (1-23)

        • Jerúsálẹ́mù, “ìlú òtítọ́” (3)

        • “Ẹ máa bá ara yín sọ òtítọ́” (16)

        • Àsìkò ààwẹ̀ yóò di àsìkò àjọ̀dún (18, 19)

        • ‘Ẹ jẹ́ ká tètè wá Jèhófà’ (21)

        • Ọkùnrin mẹ́wàá di aṣọ Júù kan mú (23)

Sekaráyà 8:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Joẹ 2:18; Sek 1:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Bíbélì Ìtumọ̀ Ayé Tuntun, ojú ìwé 1719-1720

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 10-11

Sekaráyà 8:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òdodo.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 1:16
  • +Ais 12:6; Joẹ 3:17; Sek 2:11; 8:8
  • +Ais 1:26; 60:14; Jer 33:16
  • +Ais 2:2; 11:9; 66:20; Jer 31:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/1/2007, ojú ìwé 10

    1/1/1996, ojú ìwé 10-11

Sekaráyà 8:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “wọ́n ti lọ́jọ́ lórí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:20; Jer 30:10

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 11-16

Sekaráyà 8:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 30:19; 31:4, 27; Sek 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 11, 16

Sekaráyà 8:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 16-17

Sekaráyà 8:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “láti ilẹ̀ yíyọ oòrùn àti láti ilẹ̀ wíwọ̀ oòrùn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 107:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 17

Sekaráyà 8:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 3:17; Joẹ 3:20; Emọ 9:14
  • +Le 26:12; Jer 30:22; Isk 11:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 17

Sekaráyà 8:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ fún ọwọ́ yín lókun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 35:4; Hag 2:4
  • +Ẹsr 5:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 18-19

Sekaráyà 8:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hag 1:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 18-19

Sekaráyà 8:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Hag 2:19

Sekaráyà 8:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 26:4; Di 28:4; Ais 30:23
  • +Ais 35:10; 61:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/15/2006, ojú ìwé 26-27

    1/1/1996, ojú ìwé 19-20

Sekaráyà 8:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ẹ fún ọwọ́ yín lókun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 28:37; Jer 42:18
  • +Jẹ 22:18; Ais 19:24, 25
  • +Ais 41:10
  • +Ais 35:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 19

Sekaráyà 8:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 4:28; Isk 24:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 20

Sekaráyà 8:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 31:28; 32:42
  • +Ais 43:1; Sef 3:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 20

Sekaráyà 8:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:11; Owe 12:19; Ef 4:25
  • +Sek 7:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 36

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 78-80, 82, 116

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 20

Sekaráyà 8:17

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 7:10
  • +Sek 5:4
  • +Owe 6:16-19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 20

Sekaráyà 8:19

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 52:6, 7
  • +Jer 52:12-14
  • +2Ọb 25:25; Sek 7:5
  • +Jer 52:4
  • +Ais 35:10; Jer 31:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 20-21

Sekaráyà 8:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 21-22

Sekaráyà 8:21

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tu Jèhófà lójú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jer 50:4, 5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 21-22

Sekaráyà 8:22

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “tu Jèhófà lójú.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 22:27; Ais 2:2, 3; 11:10; 55:5; 60:3; Ho 1:10; Mik 4:2; Hag 2:7

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    1/1/1996, ojú ìwé 21-22

Sekaráyà 8:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “etí aṣọ.”

  • *

    Ní Héb., “ọkùnrin Júù kan.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sek 2:11; Ifi 7:9; 14:6
  • +Ẹk 12:37, 38
  • +Ais 45:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2022, ojú ìwé 22

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2020, ojú ìwé 26-27

    Ìjọsìn Mímọ́, ojú ìwé 119, 134

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 20-21

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2014, ojú ìwé 27

    2/15/2009, ojú ìwé 27

    12/1/2005, ojú ìwé 23

    7/1/2005, ojú ìwé 23

    7/1/2004, ojú ìwé 11-12

    1/1/1996, ojú ìwé 22

    Ọjọ́ Jèhófà, ojú ìwé 175-176

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 60-61

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 407-408

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 88-89

Àwọn míì

Sek. 8:2Joẹ 2:18; Sek 1:14
Sek. 8:3Sek 1:16
Sek. 8:3Ais 12:6; Joẹ 3:17; Sek 2:11; 8:8
Sek. 8:3Ais 1:26; 60:14; Jer 33:16
Sek. 8:3Ais 2:2; 11:9; 66:20; Jer 31:23
Sek. 8:4Ais 65:20; Jer 30:10
Sek. 8:5Jer 30:19; 31:4, 27; Sek 2:4
Sek. 8:7Sm 107:2, 3
Sek. 8:8Jer 3:17; Joẹ 3:20; Emọ 9:14
Sek. 8:8Le 26:12; Jer 30:22; Isk 11:20
Sek. 8:9Ais 35:4; Hag 2:4
Sek. 8:9Ẹsr 5:1
Sek. 8:10Hag 1:6
Sek. 8:11Hag 2:19
Sek. 8:12Le 26:4; Di 28:4; Ais 30:23
Sek. 8:12Ais 35:10; 61:7
Sek. 8:13Di 28:37; Jer 42:18
Sek. 8:13Jẹ 22:18; Ais 19:24, 25
Sek. 8:13Ais 41:10
Sek. 8:13Ais 35:4
Sek. 8:14Jer 4:28; Isk 24:14
Sek. 8:15Jer 31:28; 32:42
Sek. 8:15Ais 43:1; Sef 3:16
Sek. 8:16Le 19:11; Owe 12:19; Ef 4:25
Sek. 8:16Sek 7:9
Sek. 8:17Sek 7:10
Sek. 8:17Sek 5:4
Sek. 8:17Owe 6:16-19
Sek. 8:19Jer 52:6, 7
Sek. 8:19Jer 52:12-14
Sek. 8:192Ọb 25:25; Sek 7:5
Sek. 8:19Jer 52:4
Sek. 8:19Ais 35:10; Jer 31:12
Sek. 8:21Jer 50:4, 5
Sek. 8:22Sm 22:27; Ais 2:2, 3; 11:10; 55:5; 60:3; Ho 1:10; Mik 4:2; Hag 2:7
Sek. 8:23Sek 2:11; Ifi 7:9; 14:6
Sek. 8:23Ẹk 12:37, 38
Sek. 8:23Ais 45:14
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Sekaráyà 8:1-23

Sekaráyà

8 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 2 “‘Màá ní ìtara tó pọ̀ fún Síónì,+ tìbínútìbínú sì ni màá fi ní ìtara fún un,’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”

3 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Èmi yóò pa dà sí Síónì,+ èmi yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọ́n á máa pe Jerúsálẹ́mù ní ìlú òtítọ́,*+ wọ́n á sì máa pe òkè Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ní òkè mímọ́.’”+

4 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Àwọn ọkùnrin àti obìnrin tó ti darúgbó yóò pa dà jókòó ní àwọn ojúde ìlú Jerúsálẹ́mù, kálukú pẹ̀lú ọ̀pá ní ọwọ́ rẹ̀ torí ọjọ́ ogbó wọn.*+ 5 Àwọn ojúde ìlú náà yóò sì kún fún àwọn ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin tó ń ṣeré.’”+

6 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Bó tilẹ̀ jẹ́ pé àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn èèyàn yìí láwọn ọjọ́ yẹn lè máa wò ó bíi pé ó ṣòro gan-an, ṣé ó yẹ kó dà bíi pé ó ṣòro gan-an fún èmi náà?’ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí.”

7 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Èmi yóò gba àwọn èèyàn mi là láti àwọn ilẹ̀ tó wà ní ìlà oòrùn àti ìwọ̀ oòrùn.*+ 8 Èmi yóò mú wọn wá, wọn yóò sì máa gbé ní Jerúsálẹ́mù;+ wọn yóò di èèyàn mi, èmi yóò sì di Ọlọ́run wọn+ ní òtítọ́ àti ní òdodo.’”

9 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ẹ jẹ́ onígboyà,*+ ẹ̀yin tí ẹ̀ ń gbọ́ ọ̀rọ̀ yìí láti ẹnu àwọn wòlíì,+ ọ̀rọ̀ yìí náà ni wọ́n sọ ní ọjọ́ tí wọ́n fi ìpìlẹ̀ ilé Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun lélẹ̀ kí wọ́n lè kọ́ tẹ́ńpìlì náà. 10 Torí ṣáájú ìgbà yẹn, wọn kì í san owó iṣẹ́ fún èèyàn tàbí ẹranko;+ àwọn èèyàn ò lè lọ kí wọ́n sì bọ̀ láìséwu torí ọ̀tá, torí mo ti kẹ̀yìn gbogbo èèyàn sí ara wọn.’

11 “‘Àmọ́ lọ́tẹ̀ yìí, mi ò ní ṣe bíi ti àtijọ́ sí àwọn tó ṣẹ́ kù nínú àwọn èèyàn yìí,’+ ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí. 12 Torí èso tí wọ́n máa gbìn yóò mú àlàáfíà wá; àjàrà yóò so èso, ilẹ̀ yóò mú èso rẹ̀ jáde,+ ọ̀run yóò sẹ ìrì; èmi yóò sì mú kí àwọn tó ṣẹ́ kù lára àwọn èèyàn yìí jogún gbogbo nǹkan yìí.+ 13 Ẹ̀yin ilé Júdà àti ilé Ísírẹ́lì, bí ẹ ṣe di ẹni ègún láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ bẹ́ẹ̀ náà ni èmi yóò gbà yín là, ẹ ó sì di ẹni ìbùkún.+ Ẹ má bẹ̀rù!+ Ẹ jẹ́ onígboyà.’*+

14 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘“Bí mo ṣe pinnu láti mú àjálù wá sórí yín torí àwọn baba ńlá yín múnú bí mi, tí mi ò sì pèrò dà,” ni Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun wí,+ 15 “bẹ́ẹ̀ náà ni mo ṣe pinnu báyìí láti ṣe dáadáa sí Jerúsálẹ́mù àti sí ilé Júdà.+ Ẹ má bẹ̀rù!”’+

16 “‘Àwọn ohun tó yẹ kí ẹ ṣe nìyí: Ẹ máa bá ara yín sọ òtítọ́,+ kí ẹ sì máa dá ẹjọ́ òtítọ́ àti ti àlàáfíà ní ẹnubodè yín.+ 17 Ẹ má gbèrò ibi sí ara yín nínú ọkàn yín,+ ẹ má sì fẹ́ràn ìbúra èké,+ torí mo kórìíra gbogbo àwọn nǹkan yìí,’+ ni Jèhófà wí.”

18 Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun tún bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: 19 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ààwẹ̀ oṣù kẹrin,+ ààwẹ̀ oṣù karùn-ún,+ ààwẹ̀ oṣù keje+ àti ààwẹ̀ oṣù kẹwàá+ yóò di àsìkò ìdùnnú àti ayọ̀ fún ilé Júdà, yóò jẹ́ àjọ̀dún aláyọ̀.+ Torí náà, ẹ nífẹ̀ẹ́ òtítọ́ àti àlàáfíà.’

20 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Yóò ṣẹlẹ̀ pé àwọn èèyàn àti àwọn tó ń gbé ọ̀pọ̀ ìlú yóò wá; 21 àwọn tó ń gbé ìlú kan yóò lọ sọ́dọ̀ àwọn tó ń gbé ìlú míì, wọ́n á sì sọ pé: “Ẹ jẹ́ ká tètè lọ bẹ Jèhófà pé kó ṣojúure sí wa,* ká sì wá Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun. Èmi náà yóò lọ.”+ 22 Ọ̀pọ̀ èèyàn àti orílẹ̀-èdè alágbára yóò wá sí Jerúsálẹ́mù láti wá Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun,+ kí wọ́n sì lè bẹ Jèhófà pé kó ṣojúure sí àwọn.’*

23 “Ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun sọ nìyí, ‘Ní àwọn ọjọ́ yẹn, ọkùnrin mẹ́wàá láti inú gbogbo èdè àwọn orílẹ̀-èdè+ yóò di aṣọ* Júù* kan mú, àní wọn yóò dì í mú ṣinṣin, wọ́n á sì sọ pé: “A fẹ́ bá yín lọ,+ torí a ti gbọ́ pé Ọlọ́run wà pẹ̀lú yín.”’”+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́