ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kọ́ríńtì 6
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Kọ́ríńtì

      • Kí a má ṣi inú rere Ọlọ́run lò (1, 2)

      • Bí iṣẹ́ òjíṣẹ́ Pọ́ọ̀lù ṣe rí (3-13)

      • Ẹ má fi àìdọ́gba so pọ̀ (14-18)

2 Kọ́ríńtì 6:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 5:20
  • +Ro 2:4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2016, ojú ìwé 27-32

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2010, ojú ìwé 14

    12/15/1998, ojú ìwé 18-19

    7/15/1991, ojú ìwé 16-17

    2/15/1991, ojú ìwé 19-20

2 Kọ́ríńtì 6:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 49:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2010, ojú ìwé 12-14

    12/15/1998, ojú ìwé 18-20

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 126-127

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kejì, ojú ìwé 143-146

2 Kọ́ríńtì 6:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 40

2 Kọ́ríńtì 6:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:1, 2
  • +2Kọ 11:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 40

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    9/2016, ojú ìwé 18-19

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2000, ojú ìwé 20

    4/15/2000, ojú ìwé 19-21

    12/15/1998, ojú ìwé 19

2 Kọ́ríńtì 6:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 2:10
  • +2Kọ 11:25, 27

2 Kọ́ríńtì 6:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 3:13; 1Tẹ 5:14
  • +Ef 4:32
  • +Ro 12:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 19-20

2 Kọ́ríńtì 6:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ fún ìjà.

  • *

    Ó ṣeé ṣe kó jẹ́ fún ààbò.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 2:4, 5
  • +2Kọ 10:4; Ef 6:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 19-20

2 Kọ́ríńtì 6:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 20

2 Kọ́ríńtì 6:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹni tí wọ́n gbà pé ikú tọ́ sí.”

  • *

    Tàbí “bá wí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:10, 11
  • +Iṣe 14:19; 2Kọ 4:8, 9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 20

2 Kọ́ríńtì 6:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Flp 4:13; Ifi 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/1998, ojú ìwé 20

2 Kọ́ríńtì 6:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “A ti bá yín sọ òótọ́ ọ̀rọ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 56

2 Kọ́ríńtì 6:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Àyè kò há mọ́ wa láti fìfẹ́ hàn sí yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 12:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 56

    Ilé Ìṣọ́,

    1/1/2007, ojú ìwé 9-10

2 Kọ́ríńtì 6:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ẹ jẹ́ kí ìfẹ́ yín pọ̀ sí i.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 2:17; 1Jo 4:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 56

    Jí!,

    No. 3 2020 ojú ìwé 10

    Ilé Ìṣọ́,

    11/15/2009, ojú ìwé 20-21

    1/1/2007, ojú ìwé 9-11

    10/1/2004, ojú ìwé 16-17

    12/1/1995, ojú ìwé 16

    Iṣẹ́ Òjíṣẹ́ Ìjọba,

    5/2004, ojú ìwé 8

    Jọ́sìn Ọlọ́run, ojú ìwé 149-150

2 Kọ́ríńtì 6:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “so mọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 23:32, 33; Di 7:3, 4; 1Ọb 11:4; 1Kọ 7:39
  • +Jem 4:4
  • +Ef 5:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 42

    ‘Ìfẹ́ Ọlọ́run’, ojú ìwé 113-115

    Ilé Ìṣọ́,

    6/1/2010, ojú ìwé 27

    5/1/2007, ojú ìwé 15-16

    7/1/2004, ojú ìwé 30-31

    10/15/2003, ojú ìwé 32

    11/15/1995, ojú ìwé 31

    10/1/1993, ojú ìwé 29-30

    Àwọn Ọ̀dọ́ Ń Béèrè, Apá Kejì, ojú ìwé 34

    Jí!,

    1/22/1998, ojú ìwé 20

2 Kọ́ríńtì 6:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Látinú ọ̀rọ̀ Hébérù tó túmọ̀ sí “Tí Kò Dára fún Ohunkóhun.” Ó ń tọ́ka sí Sátánì.

  • *

    Tàbí “olóòótọ́.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 4:10; Ifi 12:7, 8
  • +1Kọ 10:21

2 Kọ́ríńtì 6:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 10:14
  • +1Kọ 3:16
  • +Ẹk 29:45
  • +Le 26:11, 12; Isk 37:27

2 Kọ́ríńtì 6:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 52:11; Jer 51:45; Ifi 18:4
  • +Isk 20:41; 2Kọ 7:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2006, ojú ìwé 27-31

    12/1/1991, ojú ìwé 12-13

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 266

2 Kọ́ríńtì 6:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Sa 7:14
  • +Ais 43:6; Ho 1:10; Jo 1:12

Àwọn míì

2 Kọ́r. 6:12Kọ 5:20
2 Kọ́r. 6:1Ro 2:4
2 Kọ́r. 6:2Ais 49:8
2 Kọ́r. 6:31Kọ 9:22
2 Kọ́r. 6:42Kọ 4:1, 2
2 Kọ́r. 6:42Kọ 11:23
2 Kọ́r. 6:5Ifi 2:10
2 Kọ́r. 6:52Kọ 11:25, 27
2 Kọ́r. 6:6Kol 3:13; 1Tẹ 5:14
2 Kọ́r. 6:6Ef 4:32
2 Kọ́r. 6:6Ro 12:9
2 Kọ́r. 6:71Kọ 2:4, 5
2 Kọ́r. 6:72Kọ 10:4; Ef 6:11
2 Kọ́r. 6:92Kọ 4:10, 11
2 Kọ́r. 6:9Iṣe 14:19; 2Kọ 4:8, 9
2 Kọ́r. 6:10Flp 4:13; Ifi 2:9
2 Kọ́r. 6:122Kọ 12:15
2 Kọ́r. 6:131Pe 2:17; 1Jo 4:20
2 Kọ́r. 6:14Ẹk 23:32, 33; Di 7:3, 4; 1Ọb 11:4; 1Kọ 7:39
2 Kọ́r. 6:14Jem 4:4
2 Kọ́r. 6:14Ef 5:7, 8
2 Kọ́r. 6:15Mt 4:10; Ifi 12:7, 8
2 Kọ́r. 6:151Kọ 10:21
2 Kọ́r. 6:161Kọ 10:14
2 Kọ́r. 6:161Kọ 3:16
2 Kọ́r. 6:16Ẹk 29:45
2 Kọ́r. 6:16Le 26:11, 12; Isk 37:27
2 Kọ́r. 6:17Ais 52:11; Jer 51:45; Ifi 18:4
2 Kọ́r. 6:17Isk 20:41; 2Kọ 7:1
2 Kọ́r. 6:182Sa 7:14
2 Kọ́r. 6:18Ais 43:6; Ho 1:10; Jo 1:12
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Kọ́ríńtì 6:1-18

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

6 Bí a ṣe ń bá a ṣiṣẹ́,+ à ń rọ̀ yín pé kí ẹ má ṣe gba inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí Ọlọ́run, kí ẹ sì pàdánù ohun tó wà fún.+ 2 Nítorí ó sọ pé: “Ní àkókò ìtẹ́wọ́gbà, mo gbọ́ ọ̀rọ̀ rẹ, ní ọjọ́ ìgbàlà, mo ràn ọ́ lọ́wọ́.”+ Wò ó! Ìsinsìnyí gan-an ni àkókò ìtẹ́wọ́gbà. Wò ó! Ìsinsìnyí ni ọjọ́ ìgbàlà.

3 A ò ṣe ohun tó lè fa ìkọ̀sẹ̀ lọ́nàkọnà, kí iṣẹ́ òjíṣẹ́ wa má bàa ní àbùkù;+ 4 àmọ́ ní gbogbo ọ̀nà, à ń dámọ̀ràn ara wa bí òjíṣẹ́ Ọlọ́run,+ nínú ọ̀pọ̀ ìfaradà, nínú ìpọ́njú, nínú àìní, nínú ìṣòro,+ 5 nínú lílù, nínú ẹ̀wọ̀n,+ nínú rúkèrúdò, nínú iṣẹ́ àṣekára, nínú àìsùn, nínú àìrí oúnjẹ jẹ;+ 6 nínú jíjẹ́ mímọ́, nínú ìmọ̀, nínú sùúrù,+ nínú inú rere,+ nínú ẹ̀mí mímọ́, nínú ìfẹ́ tí kò ní ẹ̀tàn,+ 7 nínú ọ̀rọ̀ òtítọ́, nínú agbára Ọlọ́run;+ nípasẹ̀ àwọn ohun ìjà òdodo+ lọ́wọ́ ọ̀tún* àti lọ́wọ́ òsì,* 8 nínú ògo àti àbùkù, nínú ìròyìn burúkú àti ìròyìn rere. Wọ́n kà wá sí ẹlẹ́tàn, síbẹ̀ a jẹ́ olóòótọ́, 9 bí ẹni tí a kò mọ̀, síbẹ̀ a dá wa mọ̀, bí ẹni tó ń kú lọ,* síbẹ̀, wò ó! a wà láàyè,+ bí ẹni tí wọ́n fìyà jẹ,* síbẹ̀ a kò fà wá lé ikú lọ́wọ́,+ 10 bí ẹni tó ń kárí sọ àmọ́ à ń yọ̀ nígbà gbogbo, bí aláìní àmọ́ à ń sọ ọ̀pọ̀ di ọlọ́rọ̀, bí ẹni tí kò ní nǹkan kan, síbẹ̀ a ní ohun gbogbo.+

11 A ti la ẹnu wa láti bá yín sọ̀rọ̀,* ẹ̀yin ará Kọ́ríńtì, a sì ti ṣí ọkàn wa sílẹ̀ pátápátá. 12 Ìfẹ́ tí a ní sí yín kò ní ààlà,*+ àmọ́ ẹ ti pààlà sí ìfẹ́ oníjẹ̀lẹ́ńkẹ́ tí ẹ ní sí wa. 13 Torí náà, mò ń bá yín sọ̀rọ̀ bí ẹni ń bá àwọn ọmọ mi sọ̀rọ̀, ẹ̀yin náà, ẹ ṣí ọkàn yín sílẹ̀ pátápátá.*+

14 Ẹ má fi àìdọ́gba so pọ̀ pẹ̀lú* àwọn aláìgbàgbọ́.+ Nítorí àjọṣe wo ni òdodo àti ìwà tí kò bófin mu ní?+ Tàbí kí ló pa ìmọ́lẹ̀ àti òkùnkùn pọ̀?+ 15 Bákan náà, ìṣọ̀kan wo ló wà láàárín Kristi àti Bélíálì?*+ Àbí kí ló pa onígbàgbọ́* àti aláìgbàgbọ́ pọ̀?+ 16 Kí ló pa òrìṣà pọ̀ mọ́ tẹ́ńpìlì Ọlọ́run?+ Nítorí àwa jẹ́ tẹ́ńpìlì Ọlọ́run alààyè;+ bí Ọlọ́run ṣe sọ pé: “Èmi yóò máa gbé láàárín wọn,+ èmi yóò sì máa rìn láàárín wọn, èmi yóò jẹ́ Ọlọ́run wọn, wọn yóò sì di èèyàn mi.”+ 17 “‘Nítorí náà, ẹ jáde kúrò láàárín wọn, kí ẹ sì ya ara yín sọ́tọ̀,’ ni Jèhófà* wí, ‘ẹ má fọwọ́ kan ohun àìmọ́ mọ́’”;+ “‘màá sì gbà yín wọlé.’”+ 18 “‘Màá di bàbá yín,+ ẹ ó sì di ọmọkùnrin àti ọmọbìnrin mi,’+ ni Jèhófà,* Olódùmarè wí.”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́