ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé Àìsáyà

      • Èéhù Jésè máa fi òdodo ṣàkóso (1-10)

        • Ìkookò máa bá ọmọ àgùntàn gbé (6)

        • Ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé (9)

      • Àṣẹ́kù pa dà (11-16)

Àìsáyà 11:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 132:11; Ais 53:2; Ifi 5:5; 22:16
  • +Rut 4:17; 1Sa 17:58; Mt 1:1, 6; Lk 3:23, 32; Iṣe 13:22, 23; Ro 15:12
  • +Jer 23:5; 33:15; Sek 3:8; 6:12

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2011, ojú ìwé 5

    12/1/2006, ojú ìwé 9

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 83-84

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 159

Àìsáyà 11:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 42:1; Jo 1:32; Iṣe 10:38
  • +Lk 2:52
  • +Ais 9:6

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2010, ojú ìwé 16-19

    10/1/1992, ojú ìwé 18-19

    7/1/1992, ojú ìwé 14

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 159-160

Àìsáyà 11:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 5:7
  • +Jo 7:24; 8:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 159-161

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    10/1/1995, ojú ìwé 13

    3/15/1995, ojú ìwé 11

    7/1/1992, ojú ìwé 14

Àìsáyà 11:4

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “Ó máa fi òdodo dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀.”

  • *

    Tàbí “ẹ̀mí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 2:9; 110:2; Ifi 19:11, 15
  • +2Tẹ 2:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 33

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1992, ojú ìwé 14

Àìsáyà 11:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 3:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 3/2017, ojú ìwé 3

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161

Àìsáyà 11:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ọmọ kìnnìún tó tó ọdẹ ṣe (onígọ̀gọ̀).”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “Ọmọ màlúù àti kìnnìún á jọ máa jẹun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 65:25
  • +Isk 34:25

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    1/2018, ojú ìwé 31

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 7

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 232, 233-234, 236

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 7-9

    2/15/1996, ojú ìwé 25

    9/15/1991, ojú ìwé 31

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161-165

    Ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run, ojú ìwé 26

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 173-175

Àìsáyà 11:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 2:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 7

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 232, 233-234, 236

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161-165

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 173-175

Àìsáyà 11:8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 7

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161-165

    Ìtọ́sọ́nà Ọlọ́run, ojú ìwé 26

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 173-175

Àìsáyà 11:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 2:4; 35:9; 60:18; Mik 4:4
  • +Ais 51:3; 56:7; 65:25
  • +Sm 22:27; Hab 2:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 31

    Ìwé Ìpàdé Ìgbésí Ayé àti Iṣẹ́ Òjíṣẹ́,

    12/2016, ojú ìwé 7

    Ìjọba Ọlọ́run Ti Ń Ṣàkóso!, ojú ìwé 233-234, 236

    Ilé Ìṣọ́,

    9/1/2010, ojú ìwé 7-9

    5/15/2007, ojú ìwé 6

    4/15/2000, ojú ìwé 18

    10/1/1992, ojú ìwé 19

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 161-165

    Ìmọ̀, ojú ìwé 184-185

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 173-176

Àìsáyà 11:10

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òpó tí a fi ṣe àmì.”

  • *

    Tàbí “Àwọn orílẹ̀-èdè máa wá a.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 15:12; Ifi 22:16
  • +Jẹ 49:10; Ais 49:22; 62:10
  • +Iṣe 11:18; 28:28

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2008, ojú ìwé 4-5

    12/1/2006, ojú ìwé 9

    8/15/1994, ojú ìwé 31

    10/1/1992, ojú ìwé 19

    Ìparí Ìṣípayá, ojú ìwé 83-84

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 165-166

Àìsáyà 11:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ìyẹn, Babilóníà.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 11:16
  • +Ais 27:13; Jer 44:28; Mik 7:12
  • +Jer 44:15
  • +Sef 3:10
  • +Da 8:2
  • +Ais 66:19

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 166-167

Àìsáyà 11:12

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “òpó tí a fi ṣe àmì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹsr 1:2, 3; Ais 49:22; 62:10
  • +Sm 147:2; Ais 66:20

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 166-167

Àìsáyà 11:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kr 30:1, 10; Jer 31:6
  • +Jer 3:18; Isk 37:16, 19; Ho 1:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 167-168

Àìsáyà 11:14

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Héb., “èjìká.”

  • *

    Tàbí “Wọ́n máa mú kí agbára wọn dé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Emọ 9:11, 12; Ọbd 18
  • +Ais 25:10
  • +Jer 49:2

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 167-168

Àìsáyà 11:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “gbẹ.”

  • *

    Ní Héb., “pín ahọ́n òkun Íjíbítì.”

  • *

    Ìyẹn, odò Yúfírétì.

  • *

    Tàbí “ẹ̀mí.”

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “pín in sí ọ̀gbàrá méje.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 14:22
  • +Jẹ 15:18

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 168

Àìsáyà 11:16

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 19:23; 27:13; 35:8; 40:3; 57:14; Jer 31:21
  • +Ẹsr 1:2, 3

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àsọtẹ́lẹ̀ Aísáyà, Apá Kìíní, ojú ìwé 168-169

Àwọn míì

Àìsá. 11:1Sm 132:11; Ais 53:2; Ifi 5:5; 22:16
Àìsá. 11:1Rut 4:17; 1Sa 17:58; Mt 1:1, 6; Lk 3:23, 32; Iṣe 13:22, 23; Ro 15:12
Àìsá. 11:1Jer 23:5; 33:15; Sek 3:8; 6:12
Àìsá. 11:2Ais 42:1; Jo 1:32; Iṣe 10:38
Àìsá. 11:2Lk 2:52
Àìsá. 11:2Ais 9:6
Àìsá. 11:3Heb 5:7
Àìsá. 11:3Jo 7:24; 8:16
Àìsá. 11:4Sm 2:9; 110:2; Ifi 19:11, 15
Àìsá. 11:42Tẹ 2:8
Àìsá. 11:5Ifi 3:14
Àìsá. 11:6Ais 65:25
Àìsá. 11:6Isk 34:25
Àìsá. 11:7Ho 2:18
Àìsá. 11:9Ais 2:4; 35:9; 60:18; Mik 4:4
Àìsá. 11:9Ais 51:3; 56:7; 65:25
Àìsá. 11:9Sm 22:27; Hab 2:14
Àìsá. 11:10Ro 15:12; Ifi 22:16
Àìsá. 11:10Jẹ 49:10; Ais 49:22; 62:10
Àìsá. 11:10Iṣe 11:18; 28:28
Àìsá. 11:11Ais 11:16
Àìsá. 11:11Ais 27:13; Jer 44:28; Mik 7:12
Àìsá. 11:11Jer 44:15
Àìsá. 11:11Sef 3:10
Àìsá. 11:11Da 8:2
Àìsá. 11:11Ais 66:19
Àìsá. 11:12Ẹsr 1:2, 3; Ais 49:22; 62:10
Àìsá. 11:12Sm 147:2; Ais 66:20
Àìsá. 11:132Kr 30:1, 10; Jer 31:6
Àìsá. 11:13Jer 3:18; Isk 37:16, 19; Ho 1:11
Àìsá. 11:14Emọ 9:11, 12; Ọbd 18
Àìsá. 11:14Ais 25:10
Àìsá. 11:14Jer 49:2
Àìsá. 11:15Ẹk 14:22
Àìsá. 11:15Jẹ 15:18
Àìsá. 11:16Ais 19:23; 27:13; 35:8; 40:3; 57:14; Jer 31:21
Àìsá. 11:16Ẹsr 1:2, 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
Àìsáyà 11:1-16

Àìsáyà

11 Ẹ̀ka igi+ kan máa yọ látinú kùkùté Jésè,+

Èéhù+ kan látinú gbòǹgbò rẹ̀ sì máa so èso.

 2 Ẹ̀mí Jèhófà máa bà lé e,+

Ẹ̀mí ọgbọ́n+ àti ti òye,

Ẹ̀mí ìmọ̀ràn àti ti agbára,+

Ẹ̀mí ìmọ̀ àti ti ìbẹ̀rù Jèhófà.

 3 Ìbẹ̀rù Jèhófà máa jẹ́ ìdùnnú rẹ̀.+

Kò ní gbé ìdájọ́ rẹ̀ ka ohun tó fojú rí,

Kò sì ní gbé ìbáwí rẹ̀ ka ohun tó fetí gbọ́ lásán.+

 4 Ó máa dá ẹjọ́ àwọn ẹni rírẹlẹ̀ bó ṣe tọ́,*

Ó sì máa fi òtítọ́ báni wí torí àwọn oníwà pẹ̀lẹ́ tó wà ní ayé.

Ó máa fi ọ̀pá ẹnu rẹ̀ lu ayé,+

Ó sì máa fi èémí* ètè rẹ̀ pa ẹni burúkú.+

 5 Òdodo ló máa jẹ́ àmùrè ìgbáròkó rẹ̀,

Òtítọ́ ló sì máa jẹ́ àmùrè ìbàdí rẹ̀.+

 6 Ìkookò máa bá ọ̀dọ́ àgùntàn gbé fúngbà díẹ̀,+

Àmọ̀tẹ́kùn máa dùbúlẹ̀ ti ọmọ ewúrẹ́,

Ọmọ màlúù, kìnnìún* àti ẹran tó sanra á jọ wà pa pọ̀;*+

Ọmọ kékeré á sì máa dà wọ́n.

 7 Màlúù àti bíárì á jọ máa jẹun,

Àwọn ọmọ wọn á sì jọ dùbúlẹ̀.

Kìnnìún máa jẹ pòròpórò bí akọ màlúù.+

 8 Ọmọ ẹnu ọmú máa ṣeré lórí ihò ṣèbé,

Ọmọ tí wọ́n ti gba ọmú lẹ́nu rẹ̀ sì máa fọwọ́ sí ihò ejò olóró.

 9 Wọn ò ní fa ìpalára kankan,+

Tàbí ìparun kankan ní gbogbo òkè mímọ́ mi,+

Torí ó dájú pé ìmọ̀ Jèhófà máa bo ayé,

Bí omi ṣe ń bo òkun.+

10 Ní ọjọ́ yẹn, gbòǹgbò Jésè+ máa dúró bí àmì* fún àwọn èèyàn.+

Ọ̀dọ̀ rẹ̀ ni àwọn orílẹ̀-èdè máa yíjú sí fún ìtọ́sọ́nà,*+

Ibi ìsinmi rẹ̀ sì máa di ológo.

11 Ní ọjọ́ yẹn, Jèhófà tún máa na ọwọ́ rẹ̀ lẹ́ẹ̀kejì, láti gba àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ pa dà, àwọn tó ṣẹ́ kù láti Ásíríà,+ Íjíbítì,+ Pátírọ́sì,+ Kúṣì,+ Élámù,+ Ṣínárì,* Hámátì àti àwọn erékùṣù òkun.+ 12 Ó máa gbé àmì* kan sókè fún àwọn orílẹ̀-èdè, ó sì máa kó àwọn tó fọ́n ká lára Ísírẹ́lì jọ,+ ó máa kó àwọn tó tú ká lára Júdà jọ láti ìkángun mẹ́rẹ̀ẹ̀rin ayé.+

13 Owú Éfúrémù máa pòórá,+

Àwọn tó sì ń fi ẹ̀tanú hàn sí Júdà máa pa run.

Éfúrémù ò ní jowú Júdà,

Júdà ò sì ní fi ẹ̀tanú hàn sí Éfúrémù.+

14 Wọ́n máa já ṣòòrò wálẹ̀ sí gẹ̀rẹ́gẹ̀rẹ́* àwọn Filísínì lápá ìwọ̀ oòrùn;

Wọ́n jọ máa kó ẹrù àwọn ará Ìlà Oòrùn.

Wọ́n máa na ọwọ́ wọn sí* Édómù+ àti Móábù,+

Àwọn ọmọ Ámónì sì máa di ọmọ abẹ́ wọn.+

15 Jèhófà máa pín* ibi tí òkun Íjíbítì ti ya wọ ilẹ̀,*+

Ó sì máa fi ọwọ́ rẹ̀ lórí Odò.*+

Ó máa fi èémí* rẹ̀ tó ń jó nǹkan gbẹ kọ lu ọ̀gbàrá rẹ̀ méjèèje,*

Ó sì máa mú kí àwọn èèyàn fi bàtà wọn rìn kọjá.

16 Ọ̀nà kan sì máa jáde+ láti Ásíríà fún àṣẹ́kù àwọn èèyàn rẹ̀ yòókù,+

Bó ṣe rí fún Ísírẹ́lì ní ọjọ́ tó kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́