ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 1 Pétérù 2
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 1 Pétérù

      • Kí ọ̀rọ̀ náà máa wù yín (1-3)

      • Òkúta ààyè tí a fi kọ́ ilé tẹ̀mí (4-10)

      • Ẹ máa gbé bí àjèjì nínú ayé (11, 12)

      • Àwọn tó yẹ ká tẹrí ba fún (13-25)

        • Kristi fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún wa (21)

1 Pétérù 2:1

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 5:16; Jem 1:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    9/15/2006, ojú ìwé 21

    Yiyan, ojú ìwé 42-43

1 Pétérù 2:2

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ògidì wàrà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mk 10:15
  • +2Ti 3:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 11

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2011, ojú ìwé 4

    10/1/2000, ojú ìwé 11

    7/1/2000, ojú ìwé 12

    5/1/2000, ojú ìwé 15

    11/1/1999, ojú ìwé 9

    6/1/1998, ojú ìwé 10

    4/15/1997, ojú ìwé 31

    9/1/1993, ojú ìwé 16-17

    Ilé Ẹ̀kọ́ Ìjọba Ọlọ́run, ojú ìwé 11

    Jí!,

    1/22/1996, ojú ìwé 23

    Ìmọ̀, ojú ìwé 22

    Yiyan, ojú ìwé 43, 44-46

1 Pétérù 2:3

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ti mọ̀.”

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    6/1/1994, ojú ìwé 30

    Yiyan, ojú ìwé 43-44

1 Pétérù 2:4

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:3; Jo 19:15
  • +Sm 118:22; Ais 42:1; Mt 21:42; Iṣe 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 50-55

1 Pétérù 2:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 2:21
  • +Heb 13:15
  • +Ro 12:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 50, 55-59

1 Pétérù 2:6

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “dójú tì.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 28:16

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 50, 55

1 Pétérù 2:7

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “olórí igun.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Sm 69:8
  • +Sm 118:22; Mt 21:42; Lk 20:17; Iṣe 4:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    12/2017, ojú ìwé 9-10

    Yiyan, ojú ìwé 55

1 Pétérù 2:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 8:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    10/1/2008, ojú ìwé 5

    Yiyan, ojú ìwé 55

1 Pétérù 2:9

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ìwà mímọ́,” ìyẹn àwọn ìwà àti ìṣe rẹ̀ tó ń wúni lórí.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ifi 5:10; 20:6
  • +Ẹk 19:5, 6; Di 7:6; 10:15; Mal 3:17
  • +Ais 43:20, 21
  • +Ef 5:8; Kol 1:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    1/15/2012, ojú ìwé 26-30

    3/15/2010, ojú ìwé 24

    2/15/2006, ojú ìwé 22

    8/1/2002, ojú ìwé 12-13

    3/15/1998, ojú ìwé 13

    2/1/1998, ojú ìwé 17

    11/1/1995, ojú ìwé 30-31

    9/1/1995, ojú ìwé 13-18

    7/1/1995, ojú ìwé 18-19

    6/1/1992, ojú ìwé 15-16

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 107, 118-119

    Yiyan, ojú ìwé 59-60

1 Pétérù 2:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ho 1:10; Iṣe 15:14; Ro 9:25
  • +Ho 2:23

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    3/15/2010, ojú ìwé 24

    Yiyan, ojú ìwé 59

1 Pétérù 2:11

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “àtìpó.”

  • *

    Tàbí “ọkàn yín.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:17
  • +Ro 8:5; Ga 5:24
  • +Ga 5:17; Jem 4:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 19, 21

    11/1/2002, ojú ìwé 12

    Yiyan, ojú ìwé 97-98, 100-102

1 Pétérù 2:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 12:17; 1Ti 3:7
  • +Mt 5:16; Jem 3:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 21

    11/1/2002, ojú ìwé 12-13

    1/1/1998, ojú ìwé 15

    9/1/1997, ojú ìwé 7

    Jí!,

    11/8/2003, ojú ìwé 29

    Yiyan, ojú ìwé 102-107

1 Pétérù 2:13

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “gbé kalẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:1; Ef 6:5; Tit 3:1
  • +1Pe 2:17

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 45

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 22

    11/1/2002, ojú ìwé 13

    Yiyan, ojú ìwé 62-63

1 Pétérù 2:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:3, 4

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 45

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2002, ojú ìwé 13

    6/1/1992, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 62-63

1 Pétérù 2:15

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “mú kí àwọn aláìnírònú tó ń fi àìmọ̀kan sọ̀rọ̀ kó ẹnu wọn níjàánu.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Tit 2:7, 8

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2002, ojú ìwé 13

    11/1/1997, ojú ìwé 18

    6/1/1992, ojú ìwé 16-17

    Yiyan, ojú ìwé 63-65

1 Pétérù 2:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ṣe àwáwí.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ga 5:1
  • +Ga 5:13
  • +1Kọ 7:22

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 10-12

    Ilé Ìṣọ́,

    11/1/2002, ojú ìwé 13-14

    5/1/1996, ojú ìwé 8

    6/1/1992, ojú ìwé 14

    Ọlọrun Bikita, ojú ìwé 11-12

    Yiyan, ojú ìwé 65

1 Pétérù 2:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Ní Grk., “ẹgbẹ́ àwọn ará.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 19:32; Ro 12:10; 13:7
  • +1Jo 2:10; 4:21
  • +Sm 111:10; Owe 8:13; 2Kọ 7:1
  • +Owe 24:21

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 19

    Ilé Ìṣọ́,

    12/15/2012, ojú ìwé 23

    11/1/2002, ojú ìwé 14

    5/1/1996, ojú ìwé 6, 8

    8/1/1995, ojú ìwé 31

    6/1/1992, ojú ìwé 16-18

    2/1/1991, ojú ìwé 20

    Yiyan, ojú ìwé 65-68

1 Pétérù 2:18

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ef 6:5; Kol 3:22; 1Ti 6:1; Tit 2:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    2/1/1991, ojú ìwé 21

    Yiyan, ojú ìwé 70-72

1 Pétérù 2:19

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ìbànújẹ́; ìrora.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 13:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 70-72

1 Pétérù 2:20

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 4:15
  • +Mt 5:10; Iṣe 5:41; 1Pe 4:14

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 59

    Yiyan, ojú ìwé 70-72

1 Pétérù 2:21

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 3:18
  • +Mt 16:24; Jo 13:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2021, ojú ìwé 2-7

    Gbádùn Ayé Rẹ Títí Láé!, ẹ̀kọ́ 16

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2015, ojú ìwé 5-6

    12/1/2008, ojú ìwé 4-7

    11/15/2008, ojú ìwé 21

    12/1/2007, ojú ìwé 28-30

    8/15/2002, ojú ìwé 15

    2/15/2000, ojú ìwé 11

    9/15/1999, ojú ìwé 22

    2/15/1996, ojú ìwé 28

    “Máa Tọ̀ Mí Lẹ́yìn,” ojú ìwé 74-75

    Yiyan, ojú ìwé 72-73, 83-86

1 Pétérù 2:22

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 8:46; Heb 4:15
  • +Ais 53:9

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 72-73

1 Pétérù 2:23

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “kẹ́gàn rẹ̀.”

  • *

    Tàbí “kẹ́gàn wọn.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Mt 27:39
  • +Ais 53:7; Ro 12:21
  • +Heb 5:8
  • +Jer 11:20; Jo 8:50

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    5/2020, ojú ìwé 18-19

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    8/2017, ojú ìwé 28

    Ilé Ìṣọ́,

    5/1/2006, ojú ìwé 21

    Yiyan, ojú ìwé 72-73

1 Pétérù 2:24

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “igi.”

  • *

    Tàbí “bọ́ lọ́wọ́ ẹ̀ṣẹ̀.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Le 16:21
  • +Flp 2:8
  • +Ais 53:5

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Yiyan, ojú ìwé 73-74

1 Pétérù 2:25

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Tàbí “ayé.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ais 53:6
  • +Sm 23:1; Ais 40:11

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Àwọn Ìtẹ̀jáde Tá A Tọ́ka sí Nínú Ìwé Ìpàdé, 10/2019, ojú ìwé 3

    Ilé-Ìṣọ́nà,

    7/1/1992, ojú ìwé 16

    Yiyan, ojú ìwé 73-74

Àwọn míì

1 Pét. 2:1Ga 5:16; Jem 1:21
1 Pét. 2:2Mk 10:15
1 Pét. 2:22Ti 3:15
1 Pét. 2:4Ais 53:3; Jo 19:15
1 Pét. 2:4Sm 118:22; Ais 42:1; Mt 21:42; Iṣe 4:11
1 Pét. 2:5Ef 2:21
1 Pét. 2:5Heb 13:15
1 Pét. 2:5Ro 12:1
1 Pét. 2:6Ais 28:16
1 Pét. 2:7Sm 69:8
1 Pét. 2:7Sm 118:22; Mt 21:42; Lk 20:17; Iṣe 4:11
1 Pét. 2:8Ais 8:14
1 Pét. 2:9Ifi 5:10; 20:6
1 Pét. 2:9Ẹk 19:5, 6; Di 7:6; 10:15; Mal 3:17
1 Pét. 2:9Ais 43:20, 21
1 Pét. 2:9Ef 5:8; Kol 1:13
1 Pét. 2:10Ho 1:10; Iṣe 15:14; Ro 9:25
1 Pét. 2:10Ho 2:23
1 Pét. 2:111Pe 1:17
1 Pét. 2:11Ro 8:5; Ga 5:24
1 Pét. 2:11Ga 5:17; Jem 4:1
1 Pét. 2:12Ro 12:17; 1Ti 3:7
1 Pét. 2:12Mt 5:16; Jem 3:13
1 Pét. 2:13Ro 13:1; Ef 6:5; Tit 3:1
1 Pét. 2:131Pe 2:17
1 Pét. 2:14Ro 13:3, 4
1 Pét. 2:15Tit 2:7, 8
1 Pét. 2:16Ga 5:1
1 Pét. 2:16Ga 5:13
1 Pét. 2:161Kọ 7:22
1 Pét. 2:17Le 19:32; Ro 12:10; 13:7
1 Pét. 2:171Jo 2:10; 4:21
1 Pét. 2:17Sm 111:10; Owe 8:13; 2Kọ 7:1
1 Pét. 2:17Owe 24:21
1 Pét. 2:18Ef 6:5; Kol 3:22; 1Ti 6:1; Tit 2:9
1 Pét. 2:19Ro 13:5
1 Pét. 2:201Pe 4:15
1 Pét. 2:20Mt 5:10; Iṣe 5:41; 1Pe 4:14
1 Pét. 2:211Pe 3:18
1 Pét. 2:21Mt 16:24; Jo 13:15
1 Pét. 2:22Jo 8:46; Heb 4:15
1 Pét. 2:22Ais 53:9
1 Pét. 2:23Mt 27:39
1 Pét. 2:23Ais 53:7; Ro 12:21
1 Pét. 2:23Heb 5:8
1 Pét. 2:23Jer 11:20; Jo 8:50
1 Pét. 2:24Le 16:21
1 Pét. 2:24Flp 2:8
1 Pét. 2:24Ais 53:5
1 Pét. 2:25Ais 53:6
1 Pét. 2:25Sm 23:1; Ais 40:11
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
  • 19
  • 20
  • 21
  • 22
  • 23
  • 24
  • 25
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
1 Pétérù 2:1-25

Ìwé Kìíní Pétérù

2 Nítorí náà, ẹ jáwọ́ nínú gbogbo ìwà burúkú,+ ẹ̀tàn, àgàbàgebè àti owú, ẹ má sì sọ̀rọ̀ ẹnikẹ́ni láìdáa. 2 Bíi ti ìkókó,+ ẹ jẹ́ kí wàrà tí kò lábùlà* tó jẹ́ ti ọ̀rọ̀ náà máa wù yín gan-an, kí ẹ lè dàgbà dé ìgbàlà nípasẹ̀ rẹ̀,+ 3 tí ẹ bá ti tọ́ ọ wò* pé onínúure ni Olúwa.

4 Bí ẹ ṣe wá sọ́dọ̀ rẹ̀, ẹni tó jẹ́ òkúta ààyè tí àwọn èèyàn kọ̀ sílẹ̀,+ àmọ́ tó jẹ́ àyànfẹ́, tó sì ṣeyebíye lójú Ọlọ́run,+ 5 bí àwọn òkúta ààyè, à ń fi ẹ̀yin pẹ̀lú kọ́ ilé tẹ̀mí+ kí ẹ lè di ẹgbẹ́ àlùfáà mímọ́, kí ẹ lè máa rú àwọn ẹbọ ẹ̀mí+ tí Ọlọ́run tẹ́wọ́ gbà nípasẹ̀ Jésù Kristi.+ 6 Torí Ìwé Mímọ́ sọ pé: “Wò ó! Màá fi òkúta àyànfẹ́ kan lélẹ̀ ní Síónì, òkúta ìpìlẹ̀ igun ilé tó ṣeyebíye, kò sì sí ẹni tó ní ìgbàgbọ́ nínú rẹ̀ tí a máa já kulẹ̀.”*+

7 Nítorí náà, ẹ̀yin ló ṣe iyebíye fún, torí ẹ jẹ́ onígbàgbọ́; àmọ́ fún àwọn tí kò gbà gbọ́, “òkúta tí àwọn kọ́lékọ́lé kọ̀ sílẹ̀,+ òun ló wá di olórí òkúta igun ilé”*+ 8 àti “òkúta ìkọ̀sẹ̀ kan àti àpáta agbéniṣubú.”+ Wọ́n ń kọsẹ̀ torí wọn ò ṣègbọràn sí ọ̀rọ̀ náà. Ìdí tí a fi yàn wọ́n nìyí. 9 Àmọ́ ẹ̀yin ni “àwọn èèyàn tí Ọlọ́run yàn, ẹgbẹ́ àlùfáà aládé, orílẹ̀-èdè mímọ́,+ àwùjọ àwọn èèyàn tó jẹ́ ohun ìní pàtàkì,+ kí ẹ lè kéde káàkiri àwọn ọlá ńlá”*+ Ẹni tó pè yín jáde kúrò nínú òkùnkùn wá sínú ìmọ́lẹ̀ àgbàyanu rẹ̀.+ 10 Torí ẹ kì í ṣe àwùjọ èèyàn nígbà kan, àmọ́ ní báyìí ẹ ti di àwùjọ èèyàn Ọlọ́run;+ a kò ṣàánú yín nígbà kan, àmọ́ ní báyìí, a ti ṣàánú yín.+

11 Ẹ̀yin ará mi ọ̀wọ́n, mò ń gbà yín níyànjú, ẹ̀yin tí ẹ jẹ́ àjèjì àti olùgbé fún ìgbà díẹ̀*+ pé kí ẹ máa sá fún ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ ara+ tó ń bá yín* jà.+ 12 Ẹ jẹ́ oníwà rere láàárín àwọn orílẹ̀-èdè,+ kó lè jẹ́ pé tí wọ́n bá fẹ̀sùn ìwà ibi kàn yín, wọ́n á lè fojú ara wọn rí àwọn iṣẹ́ àtàtà yín,+ kí wọ́n sì torí ẹ̀ yin Ọlọ́run lógo lọ́jọ́ àbẹ̀wò rẹ̀.

13 Nítorí Olúwa, ẹ fi ara yín sábẹ́ gbogbo ohun tí èèyàn dá sílẹ̀,*+ ì báà jẹ́ ọba+ torí pé ó jẹ́ aláṣẹ 14 tàbí àwọn gómìnà tó rán níṣẹ́ pé kí wọ́n fìyà jẹ àwọn aṣebi, kí wọ́n sì yin àwọn tó ń ṣe rere.+ 15 Torí ìfẹ́ Ọlọ́run ni pé kí ẹ fi ìwà rere yín pa àwọn aláìnírònú tó ń fi àìmọ̀kan sọ̀rọ̀ lẹ́nu mọ́.*+ 16 Ẹ wà lómìnira,+ kí ẹ má sì fi òmìnira yín bojú* láti máa hùwà burúkú,+ àmọ́ kí ẹ lò ó bí ẹrú Ọlọ́run.+ 17 Ẹ máa bọlá fún onírúurú èèyàn,+ ẹ máa nífẹ̀ẹ́ gbogbo àwọn ará,*+ ẹ máa bẹ̀rù Ọlọ́run,+ ẹ bọlá fún ọba.+

18 Kí àwọn ìránṣẹ́ máa tẹrí ba fún àwọn ọ̀gá wọn pẹ̀lú ìbẹ̀rù tó yẹ,+ kì í ṣe fún àwọn tó jẹ́ ẹni rere, tó sì ń gba tẹni rò nìkan, àmọ́ fún àwọn tó ṣòroó tẹ́ lọ́rùn pẹ̀lú. 19 Torí ó dáa tí ẹnì kan bá fara da ìnira,* tó sì jìyà tí kò tọ́ sí i nítorí kó lè ní ẹ̀rí ọkàn rere lójú Ọlọ́run.+ 20 Àbí àǹfààní wo ló wà níbẹ̀ tí wọ́n bá lù yín torí pé ẹ dẹ́ṣẹ̀ tí ẹ sì fara dà á?+ Àmọ́ tí ẹ bá fara da ìyà torí pé ẹ̀ ń ṣe rere, èyí dáa lójú Ọlọ́run.+

21 Kódà, ọ̀nà yìí la pè yín sí, torí Kristi pàápàá jìyà torí yín,+ ó fi àpẹẹrẹ lélẹ̀ fún yín kí ẹ lè máa tọ ipasẹ̀ rẹ̀ pẹ́kípẹ́kí.+ 22 Kò dá ẹ̀ṣẹ̀ kankan,+ kò sì sí ẹ̀tàn ní ẹnu rẹ̀.+ 23 Nígbà tí wọ́n sọ̀rọ̀ àbùkù sí i,*+ kò sọ̀rọ̀ àbùkù sí wọn* pa dà.+ Nígbà tó ń jìyà,+ kò bẹ̀rẹ̀ sí í halẹ̀, àmọ́ ó fi ara rẹ̀ sí ìkáwọ́ Ẹni tó ń dájọ́+ òdodo. 24 Ó fi ara rẹ̀ ru àwọn ẹ̀ṣẹ̀ wa+ lórí òpó igi,*+ ká lè di òkú sí ẹ̀ṣẹ̀,* ká sì wà láàyè sí òdodo. Ẹ “sì rí ìwòsàn nítorí àwọn ọgbẹ́ rẹ̀.”+ 25 Torí ẹ dà bí àwọn àgùntàn tó sọnù,+ àmọ́ ẹ ti wá pa dà sọ́dọ̀ olùṣọ́ àgùntàn+ àti alábòójútó ọkàn* yín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́