ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Kọ́ríńtì 3
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun

Kò sí fídíò kankan ní apá yìí.

Má bínú, fídíò yìí kò jáde.

Ohun Tó Wà Nínú Ìwé 2 Kọ́ríńtì

      • Lẹ́tà ìdámọ̀ràn (1-3)

      • Àwọn òjíṣẹ́ májẹ̀mú tuntun (4-6)

      • Ògo májẹ̀mú tuntun ta yọ (7-18)

2 Kọ́ríńtì 3:2

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 9:2

2 Kọ́ríńtì 3:3

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Kọ 3:5
  • +Ẹk 31:18; 34:1
  • +Owe 3:3; 7:3

2 Kọ́ríńtì 3:5

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 4:12, 15; Flp 2:13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2008, ojú ìwé 28

    2/15/2002, ojú ìwé 24-25

    11/15/2000, ojú ìwé 17-19

2 Kọ́ríńtì 3:6

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Heb 8:6
  • +Ro 13:9
  • +Ga 3:10
  • +Jo 6:63

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    2/15/2002, ojú ìwé 24-25

    11/15/2000, ojú ìwé 17-19

    Àìléwu Kárí-Ayé, ojú ìwé 108-112

2 Kọ́ríńtì 3:7

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 31:18; 32:16
  • +Ẹk 34:29, 30

2 Kọ́ríńtì 3:8

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 2:1, 4
  • +1Pe 4:14

2 Kọ́ríńtì 3:9

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Di 27:26
  • +Ẹk 34:35
  • +Ro 3:21, 22

2 Kọ́ríńtì 3:10

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Kol 2:16, 17

2 Kọ́ríńtì 3:11

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 19:16; 24:17
  • +Heb 12:22-24

2 Kọ́ríńtì 3:12

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +1Pe 1:3, 4

2 Kọ́ríńtì 3:13

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:33-35

2 Kọ́ríńtì 3:14

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ro 11:7
  • +Jo 12:40
  • +Ro 7:6; Ef 2:15

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    4/1/2009, ojú ìwé 21

    8/15/2005, ojú ìwé 20

    3/15/2004, ojú ìwé 16

    2/1/1998, ojú ìwé 10

    3/1/1995, ojú ìwé 19

2 Kọ́ríńtì 3:15

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Iṣe 15:21
  • +Ro 11:8

2 Kọ́ríńtì 3:16

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Ẹk 34:34

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    4/2018, ojú ìwé 9

    Ilé Ìṣọ́,

    8/15/2005, ojú ìwé 23

2 Kọ́ríńtì 3:17

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +Jo 4:24
  • +Ais 61:1; Ro 6:14; 8:15; Ga 5:1, 13

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́ (Ẹ̀dà Tó Wà fún Ìkẹ́kọ̀ọ́),

    11/2018, ojú ìwé 19-20

    4/2018, ojú ìwé 8-9

    Ilé Ìṣọ́,

    7/15/2012, ojú ìwé 10

    1/15/1991, ojú ìwé 6

2 Kọ́ríńtì 3:18

Àlàyé ìsàlẹ́ ìwé

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Wo Àfikún A5.

  • *

    Tàbí kó jẹ́, “gẹ́gẹ́ bí ẹ̀mí Jèhófà.”

Atọ́ka Àárín Ìwé

  • +2Kọ 4:6; Ef 4:23, 24; 5:1

Atọ́ka

  • Ìwé Ìwádìí

    Ilé Ìṣọ́,

    5/15/2012, ojú ìwé 23-24

    8/15/2005, ojú ìwé 14-15, 23-24

    3/15/2004, ojú ìwé 16-17

Àwọn míì

2 Kọ́r. 3:21Kọ 9:2
2 Kọ́r. 3:31Kọ 3:5
2 Kọ́r. 3:3Ẹk 31:18; 34:1
2 Kọ́r. 3:3Owe 3:3; 7:3
2 Kọ́r. 3:5Ẹk 4:12, 15; Flp 2:13
2 Kọ́r. 3:6Heb 8:6
2 Kọ́r. 3:6Ro 13:9
2 Kọ́r. 3:6Ga 3:10
2 Kọ́r. 3:6Jo 6:63
2 Kọ́r. 3:7Ẹk 31:18; 32:16
2 Kọ́r. 3:7Ẹk 34:29, 30
2 Kọ́r. 3:8Iṣe 2:1, 4
2 Kọ́r. 3:81Pe 4:14
2 Kọ́r. 3:9Di 27:26
2 Kọ́r. 3:9Ẹk 34:35
2 Kọ́r. 3:9Ro 3:21, 22
2 Kọ́r. 3:10Kol 2:16, 17
2 Kọ́r. 3:11Ẹk 19:16; 24:17
2 Kọ́r. 3:11Heb 12:22-24
2 Kọ́r. 3:121Pe 1:3, 4
2 Kọ́r. 3:13Ẹk 34:33-35
2 Kọ́r. 3:14Ro 11:7
2 Kọ́r. 3:14Jo 12:40
2 Kọ́r. 3:14Ro 7:6; Ef 2:15
2 Kọ́r. 3:15Iṣe 15:21
2 Kọ́r. 3:15Ro 11:8
2 Kọ́r. 3:16Ẹk 34:34
2 Kọ́r. 3:17Jo 4:24
2 Kọ́r. 3:17Ais 61:1; Ro 6:14; 8:15; Ga 5:1, 13
2 Kọ́r. 3:182Kọ 4:6; Ef 4:23, 24; 5:1
  • Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
  • 1
  • 2
  • 3
  • 4
  • 5
  • 6
  • 7
  • 8
  • 9
  • 10
  • 11
  • 12
  • 13
  • 14
  • 15
  • 16
  • 17
  • 18
Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
2 Kọ́ríńtì 3:1-18

Ìwé Kejì sí Àwọn Ará Kọ́ríńtì

3 Ṣé ká tún bẹ̀rẹ̀ sí í dámọ̀ràn ara wa ni? Àbí, ṣé a tún nílò lẹ́tà ìdámọ̀ràn sí yín tàbí látọ̀dọ̀ yín bíi ti àwọn kan ni? 2 Ẹ̀yin fúnra yín ni lẹ́tà wa,+ tí a kọ sára ọkàn wa, tí gbogbo aráyé mọ̀, tí wọ́n sì ń kà. 3 Nítorí ó ṣe kedere pé ẹ jẹ́ lẹ́tà Kristi tí àwa gẹ́gẹ́ bí òjíṣẹ́ kọ,+ kì í ṣe yíǹkì la fi kọ ọ́, ẹ̀mí Ọlọ́run alààyè ni, kì í sì í ṣe ara wàláà òkúta la kọ ọ́ sí,+ ara wàláà ti ẹran ara ni, ìyẹn sára ọkàn.+

4 A ní irú ìgbọ́kànlé yìí nínú Ọlọ́run nípasẹ̀ Kristi. 5 Kì í ṣe pé àwa fúnra wa kúnjú ìwọ̀n láti ṣe ohunkóhun, Ọlọ́run ló ń mú ká kúnjú ìwọ̀n,+ 6 ẹni tó mú ká kúnjú ìwọ̀n lóòótọ́ láti jẹ́ òjíṣẹ́ májẹ̀mú tuntun kan,+ kì í ṣe ti àkọsílẹ̀ òfin,+ àmọ́ ó jẹ́ ti ẹ̀mí; torí àkọsílẹ̀ òfin ń dáni lẹ́bi ikú,+ àmọ́ ẹ̀mí ń sọni di ààyè.+

7 Ní báyìí, tí àkójọ òfin tó ń mú ikú wá, tí a fi àwọn lẹ́tà fín sára àwọn òkúta+ bá wá pẹ̀lú ògo tó pọ̀ débi pé àwọn ọmọ Ísírẹ́lì ò lè wo ojú Mósè nítorí ògo ojú rẹ̀,+ ògo tó jẹ́ pé ó máa dópin, 8 ṣé iṣẹ́ tí ẹ̀mí ń ṣe+ kò ní ní ògo tó pọ̀ ju bẹ́ẹ̀ lọ ni?+ 9 Nítorí tí àkójọ òfin tó ń mú ìdálẹ́bi+ wá bá ní ògo,+ ǹjẹ́ iṣẹ́ tó ń mú ká pe àwọn èèyàn ní olódodo kò ní ní ògo tó jù bẹ́ẹ̀ lọ?+ 10 Kódà, èyí tí a ti ṣe lógo tẹ́lẹ̀ ti pàdánù ògo rẹ̀ nítorí ògo tó ju tirẹ̀ lọ.+ 11 Nítorí tí a bá mú èyí tó máa dópin wá pẹ̀lú ògo,+ ǹjẹ́ ògo èyí tí á máa wà nìṣó kò ní pọ̀ ju bẹ́ẹ̀ lọ?+

12 Torí pé a ní irú ìrètí yìí,+ a lẹ́nu ọ̀rọ̀, 13 a kò sì ṣe bíi ti Mósè nígbà tó ń fi nǹkan bo ojú rẹ̀,+ kí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì má bàa tẹjú mọ́ òpin ohun tó máa pa rẹ́. 14 Àmọ́ èrò inú wọn ò ṣiṣẹ́ dáadáa mọ́.+ Nítorí títí di òní yìí, a kò ká ìbòjú yẹn kúrò tí a bá ń ka májẹ̀mú láéláé,+ torí ipasẹ̀ Kristi nìkan la fi ń mú un kúrò.+ 15 Kódà, títí di òní, nígbàkigbà tí wọ́n bá ń ka ìwé Mósè,+ ìbòjú máa ń bo ọkàn wọn.+ 16 Àmọ́ nígbà tẹ́nì kan bá yíjú sí Jèhófà,* ìbòjú náà á ká kúrò.+ 17 Jèhófà* ni Ẹ̀mí náà,+ ibi tí ẹ̀mí Jèhófà* bá sì wà, òmìnira á wà níbẹ̀.+ 18 Bí a ṣe ń fi ojú tí a kò fi nǹkan bò gbé ògo Jèhófà* yọ bíi dígí, gbogbo wa ni à ń pa lára dà sí àwòrán kan náà láti ògo dé ògo, bí Jèhófà* tó jẹ́ Ẹ̀mí náà* ti ṣe gẹ́lẹ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́